OWE ILE YORUBA. Proverbs in Yoruba Land
Class: Pry three
Subject: Yoruba Studies
Akole: OWE ILE YORUBA
- Eni ti yoo je oyin inu apata,koni wo enu aake
- Oju ti yoo baa ni kale, kin ti owuro sepin
- ile ti afi to omo,iri ni yoo wo
- kekere la ti npeka iroko,toba dagba tan apa kii nka
- Bi omode mo owo we,aba agba jeun
Ise kilaasi
Pari awon owe wonyii
- Eni ti yoo je oyin inu apata _____(a)kin wo enu aake (b) ase wahala gan
2.Oju ti yoo ba ni kale____(a) a fo ni (b)kin ti owuro sepin
- Ile ti afi to omo ____(a) iri ni yoo wo (b) a dara si nii
- Kekere latin peka Iroko_____(a)koto dagba (b)to ba dagba tan apa koni kaa mo
- Bi omode baa mowo we_____(a) aba agba jeun (b)owo e amo nii