SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 2 YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION 2020

CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ERE IDARAYA: ERE AYO

1.) Eniyan ___________ lo nta ayo olopon (a) meji (a) merin

2.) Omo ayo ________ lo wa ni oju opon Ayo lapapo (a) merindinlogun (b) mejidinladota

3.) Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi

4.) Omo ayo ______ ni o nwa ninu iho Kankan (a) mefa (b) merin

5.) Awon ti o nworan nibi ere ayo ni anpe ni ____________ (a) osefe Ayo (b) onilaja Ayo

 

ITOJU ATI OORE SISE

1.) _______________ nse baba Aina (a) Aisan (b) Arun

2.) ______________ wa kii (a) ojo (b) Aina

3.) ____________ baba Aina nya diedie (a) Ara (b) Ese

4.) ___________ fee ro (a) omi (b) ojo

5.) Iya ___________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Yemi

 

ALO APAMO

1.) Alo o, alo o, kilo bo somi ti ko ro to, kini o (a) Okuta (b) Okinni

 

2.) Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo (b) Igi

3.) Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o

(a) Agba (b) Ilu

4.) Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o

(a) omorogun (b) irin

5.) Alo o, alo o, yara ko topo kiki egun, kini o (a) Eyin (b) Enu

 

ALO APAGBE: IJAPA ATI OKERE

1.) _________ ati _________ je ore (a) asin ati okere (b) ijapa ati okere

2.) _______ kii se ore won (a) Ekute (b) asin

3.) Ijapa la ija ___________ (a) Eru (b) Ayo

4.) Inu bi Asin, O si ge ijapa ni ___________ je (a) Ese (b) Imu

5.) O mu _____________ sile fun okere lati na (a) ijapa (b) asin

 

 

[mediator_tech]

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share