Fawẹ̀li Àti Konsonanti Èdè Yorùbá. Jss 3. First Term

1. Kini a npe ni iro faweli

2. Oríṣi ọna ti àbùdá ìró Fawẹ̀li pinsi
3. Yíya ate faweli airanmupe àti aranmupe
1. Ìró faweli ni èyí tí èémí mú jáde ní pipe rẹ láìsí idiwo kankan nínú eka ẹnu, àpẹẹrẹ ìró faweli èdè Yorùbá ni a, ẹ, ẹ, í, ó, ọ, ú,.
Àwọn wọ̀nyí ni a mọ sì faweli airanmupe
2. Gíga odidi ahọn
Ipò oke
Ipò ebake
Ipò odo
Ipò ebado
Gíga iwájú ahọn
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Tags: