Akole:asa imototo Pry two Akole:oro ati idakeji Fala si eyi ti onse idakeji awon oro wonyii. ORO. IDAKEJI 1.Baba. (a)iya (b) Egbon 2.Egbon. (a)ore (b) aburo 3.Onile. (a)alejo (b)ara ilu 4.Omode. (a)Egbon (b)agba 5.Dide (a)joko (b)fosoke
Pry two Akole:Asa ikini ni ile yoruba Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo.awon ona naa ni awon wonyi:: 1 ikini ni asiko 2 ikini ni igba 3 ikini si ipo ti aba wa tabi ohun tio ba sele sii eniyan 4 ikini ni
Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry two Subject: Yoruba Studies Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-Ogun Review work: Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba: 1: 8-