Yoruba

Bi ase nki onise owo ati bi won se nda wo lohun

Pry two Akole:Asa ikini ni ile yoruba Orisirisi ona ni awa yoruba ngba ki ara wa ninu asa ikini ati lati mo omo yoruba lawujo.awon ona naa ni awon wonyi:: 1 ikini ni asiko 2 ikini ni igba 3 ikini si ipo ti aba wa tabi ohun tio ba sele sii eniyan 4 ikini ni

Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba:

Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry two Subject: Yoruba Studies   Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-Ogun   Review work: Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba:   1: 8-

SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 2 YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION 2020 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE IDARAYA: ERE AYO 1.) Eniyan ___________ lo nta ayo olopon (a) meji (a) merin 2.) Omo ayo ________ lo wa ni oju opon Ayo lapapo (a) merindinlogun (b) mejidinladota 3.) Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi 4.) Omo