Pry one Ose kefa Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogun 1-Ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa 11-Okanla 12-Ejila 13-Etala 14-Erinla 15-Aarundinlogun 16-Eerindinlogun 17-Eetadinlogun 18-Ejidinlogun 19-Okandinlogun 20-ogun-un Ise kilaasi Kinni oruko awon nomba yii ni ede yoruba 1.11(a)etala (b)okanla 2.13(a)okanla (b)etala 3.15 (a)arundinlogun (b)arundinlogbon
Class: Pry one Akole:Ere idaraya ni ile yoruba (ere okoto) Eniyan meji tabi meta le ta okoto lekan naa. Ori ile didan ni a ti maa nta okota. Paanu ti a ka,ti idi re ri soso ni a fi nse okoto. Okoto maa nj roinroin ti a ba nta. Ti aba ta okoto ti
Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole:lilo leta ede yoruba loro A—Aaja B—Bata D—Doje E—Ejo E—-Eye F—-Fila G—-Gele Gb—-Gbaguda H—-Hausa I—-Igi J—-Jagunjagun K—Kiniun L—–Labalaba M—–Maalu N—–Nahudu O—-Ogongo O—-Ogede P—-Pepeye R—-Rakunmi S—-salubata S—-sango T—-Tafatafa U—-Uku UK u W—-Waala Y—-Yanmuyanmu Ise kilaasi A duro fun ___ (a) aja. (b)ologbo B duro fun kinni ____ (a) apo (b)
Àwọn Faweeli àti konsananti tí ó wà nínú Èdè Yorùbá Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole: FAWELI ATI KONSONANTI EDE YORUBA Faweli yoruba pin si ona meji awon naa nii 1 Airanmupe 2 Aranmupe 1 FAWELI AIRANMUPE: A E E I O O U 2 FAWELI ARANMUPE: AN EN IN ON
Class: Primary 1 Subject: Home Economics Topic: Alufabeti Ede Yoruba (The Letters of the Alphabets in Yoruba) Duration: 45 minutes Term: First Term Week: Week 8 Set Induction: Begin by displaying the Yoruba alphabet on the board and ask students if they know the names of some Yoruba letters. Previous Knowledge: Students should have a
Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry one Subject: Yoruba Studies Akole: Onka ni ede yoruba lati ori ookan de ori ewaa. 1-ookan 2-Eeji 3-Eeta 4-Eerin 5-Aarun 6-Eefa 7-Eeje 8-Eejo 9-Eesan 10-Ewaa Review work: Kini oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba 1: 2- (a) Eerin (b) Eeji 2: 4-
SECOND TERM EXAMINATION 2020 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… 1.) DI AWON ALAFO WONYII PELU AWON LETA TI OYE A ________ D ________ Ę ________ G _________ I ________ H ________ J ________ L ________ N _________ Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y ERE IDARA YA: 1.) Eniyan melo ni
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE IDARAYA: – ERE OKOTO Eniyan _____ ni o nta okoto le e kan naa (a) meji (b) mefa Ori ______ ni a ti maa nta okoto (a) eni (b) ile _________ ti a ka, ti idire ri soso ni a fin se okoto (a) paanu (b) ike
SECOND TERM EXAMINATION CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE AYO ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) awo ayo Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE OKOTO: Eniyan _____ ni o nta okoto nleekan naa (a) meji (b) mefa Ori _______________ didan ni a ti nta okoto (a) eni (b) ile ______________ ni a fi nse okoto (a) paanu (b) igi Ti a bat a okoto sile,