Yorùbá JSS 1 Ọsẹ Kínní Akọ́lé Kẹ̀kọ́: Yorùbá Kíláàsì: JSS 1 Ọ̀sẹ̀: Kínní Ọmọ ọdún: 12 ọdun Akọ́lé: Alifabeti Yorùbá, Itan Isedale Yorùbá, àti Litireso Ẹ̀ka: Alifabeti Yorùbá, Itan Isedale Yorùbá, àti Iru Litireso Ìpinnu Akoko: 1 wakati 30 ìsẹ́jú Àfojúsùn Ẹ̀kọ́: Kọ́ àwọn ọmọ kéékèèké láti mọ̀ àti sọ alifabeti Yorùbá. Ṣàpèjúwe itan àti
ILANA ISE FUN SAA KETA OLODUN KIN-IN-NI (JSSONE) OSE KIN-IN-NI: ATUNYEWO ISE SAA KEJI OSE KEJI: EDE: LETA KIKO ASA: AWON ISE ISEMBAYE ILE YORUBA OSE KETA: LITIRESO: ASAYAN IWE TI IJOBA YAN ASA: ISE AGBE OSE KERIN: EDE: ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN ASA: ISE ILU LILU OSE KARUN-UN: EDE: IHUN GBOLOHUN ABODE
Weekly Lesson Notes Yoruba JSS 1 First Term AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan. Ami Ohun lori oro onisilebu meji SILEBU NINU EDE YORUBA Akoto ede yoruba ode-oni ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). OONKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU
OSE KEFA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI Akotoni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia Alaafia Oloto