Itesiwaju èkó l’ori onka Yoruba láti 200 titi de 250 ( ìgbà – otalugba dín mẹ́wàá /Aadota lè lugba)
Subject : Yoruba
Class : Primary 6
Term: Second Term
Week : Week 2
Topic :
Èdè
Èdè : Itesiwaju èkó l’ori onka Yoruba láti 200 titi de 250 ( ìgbà – otalugba dín mẹ́wàá/Aadota lè lugba)
Onka Lati ookan de egbewa (1 – 1000)
1 = eni
2 = eji
3 = eta
4 = merin
5 = marun-un
6 = mefa
7 = meje
8 = mejo
9 = mesan-an
10 = mewa
11 = mokanla
12 = mejila
13 = metala
14 = merinla
15 = meedogun (20 – 5)
16 = merindinlogun (20 – 4)
17 = metadinlogun (20 – 3)
18 = mejidinlogun (20 -2)
19 = mokandinlogun (20 – 1)
20 = ogun
21 = mokanlelogun (20 + 1)
22 = mejilelogun (20 + 2)
23 = metalelogun (20 + 3)
24 = merinlelogun (20 + 4)
25 = meedogbon (30 – 5)
26 = merindinlogbon (30 – 4)
27 = metadinlogbon (30 – 3)
28 = mejidinlogbon (30 – 2)
29 = mokandinlogbon (30 – 1)
30 = ogbon
40 = ogoji (20 x 2)
50 = aadota (20 x 3 – 10)
60 = ogota (20 x 3)
70 = aadorin (20 x 4 – 10)
80 = ogorin (20 x 4)
90 = aadorun-un (20 x 5 – 10)
100 = ogorun (20 x 5)
101 = mokanlelogorun
102 = mejilelogorun
103 = metalelogorun
104 = merinlelogorun
105 = marundinlaadofa (110 – 5)
106 = merindinlaadofa (110 – 4)
107 = metadinlaadofa (110 – 3)
108 = mejidinlaadofa (110 – 2)
109 = mokandinlaadofa (110 – 1)
110 = aadofa (20 x 6 – 10)
111 = mokanlelaadofa (110 + 1)
112 = mejilelaadofa (110 + 2)
113 = metalelaadofa (110 + 3)
114 = merinlelaadofa (110 + 4)
115 = marundinlogofa (120 – 5)
116 = merindinlogofa (120 – 4)
117 = metadinlogofa (120 – 3)
118 = mejidinlogofa (120 – 2)
119 = mokandinlogofa (120 – 1)
120 = ogofa (20 x 6)
130 = aadoje (20 x 7 – 10)
140 = ogoje (20 x 7)
150 = aadojo (20 x 8 – 10)
160 = ogojo (20 x 8)
170 = aadosan-an (20 x 9 – 10)
180 = ogosan-an (20 x 9)
190 = aadowa (20 x 10 – 10)
200 = igba/ ogowa (20 x 10)
201 = mokanlenigba (200 + 1)
202 = mejilenigba (200 + 2)
203 = metalenigba (200 + 3)
204 = merinlenigba (200 + 4)
205 = igbalemarun-un (200 + 5)
206 = igbalemefa (200 + 6)
207 = igbalemeje (200 + 7)
208 = igbalemejo (200 + 8)
209 = igbalemesan-an (200 + 9)
210 = igbalemewa (200 + 10)
300 = odunrun
400 = irinwo
500 = eedegbeta (200 x 3 – 100)
600 = egbeta (200 x 3)
700 = eedegberin (200 x 4 – 100)
800 = egberin (200 x 4)
900 = eedegberun (200 x 5 – 100)
1000 = egberun (200 x 5)
Evaluation :
- What is the Yoruba word for “1”? A. eni B. eji C. eta D. merin
- What is the Yoruba word for “5”? A. eni B. eji C. eta D. marun-un
- What is the Yoruba word for “10”? A. eni B. eji C. eta D. mewa
- What is the Yoruba word for “20”? A. mokanla B. mejila C. metala D. ogun
- What is the Yoruba word for “30”? A. mokanla B. mejila C. metala D. ogbon
- What is the Yoruba word for “40”? A. mokanla B. mejila C. metala D. ogoji
- What is the Yoruba word for “50”? A. aadota B. ogota C. aadorin D. ogorin
- What is the Yoruba word for “60”? A. aadota B. ogota C. aadorin D. ogorin
- What is the Yoruba word for “70”? A. aadota B. ogota C. aadorin D. ogorin
- What is the Yoruba word for “80”? A. aadota B. ogota C. aadorin D. ogorin
Ásà
Lítírésọ́ : Ìtàn àwọn akoni ilé Yoruba : Efunsetan Aniwura