YORUBA LANGUAGE THIRD TERM EXAMINATION

Table of Contents

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 1                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

Imototo

  • Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu
  • Ge _________ re ni asiko ti o ye (a) imu (b) irun
  • Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b) imu
  • Gba _________ re pelu (a) ita (b) ayika
  • Fo __________ re ki o mo toni toni (a) aso (b) inu

 

Alo Apamo:

  • Alo o, alo o, ki lo bo somi, ti ko ro to, kini o (a) okinni    (b) irin
  • Alo o, alo o, kilo ba oba jeun, ti ko palemo (a) Abe       (b) Esinsin
  • Alo o, alo o, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) Agbara ojo (b) Esinesin
  • Aloo, aloo, okun nho yaya, osa nho yaya, omoburuku tori bo (a) irin   (b) omorogun
  • Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro, kini o (a) Ata               (b) Ewa

 

ITAN KOKO IYA ARUGBO

  • __________ kan wa ni aye atijo (a) Baba (b) Egbon
  • O bi omokunrin ________ (a) mewa (b) meje
  • Okan ninu won losi ____________ iya arugbo ile won je (a) koko (b) ewa
  • _____________ beere eni ti o ji koko ounje (a) Baba arugbo (b) Iya arugbo
  • Awon omo naa si __________ lokoolan lori afara (a) Bura (b) Korin

 

ITAN IJAPA ATI YAN NIBO

  • O pe ti _______________ ko ti ri omo bi (a) yannibo (b) ijapa
  • O wa bere si i ______________ (a) ke (b) banuje
  • Ijapa ba to ___________ lo (a) babalawo (b) esu
  • Babalawo se ___________________ oogun fun-un (a) iresi (b) obe
  • Ijapa oko yannibo ____________ (a) loyun (b) bimo

 

 

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 2                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

Imo Toto

  • ____________ nge koriko ti o wa ni ayika ile won (a) Tunde      (b) Kola
  • ____________ naa ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi     (b) Bola
  • O nsa won si ori ____________ isasosi (a) Okun     (b) Irin
  • _______________ Tunde ko gbeyin rara (a) Egbon    (b) Aburo
  • Bi e ba sise tan, e maa gbagbe lati ______________ (a) we     (b) sun

 

Ipin Keta: Ikini

  • __________ ni omo kunrin nki baba tabi iyare (a) ido bale (b) ikunle
  • __________ ni omo binrin nki baba ati iyare bi o ba ku (a) ikunle (b) idobale
  • E ku otutu nla ki ni nigba _____________ (a) oye (b) ojo
  • E ku ogbele yii, e ku ooro ni a nki ni nigba ___________ (a) eerun (b) ojo
  • Ni dede agogo mejila si agogo meta abo, a maa nki ni ni ile Yoruba pe _____

(a) kaaroo (b) e kasano

 

Ise Agbe

  • __________ ni Oba (a) Agbe (b) Ode
  • Agbe lo ngbin _________ (a) okuta (b) isu
  • Isu ti a fi ngun ________ (a) amala (b) iyan
  • Agbe lo nbgin __________ (a) ogede (b) Igbin
  • Agbe lo ngbin paki, paki ti a fi nse _________ (a) elubo (b) gaari

 

Alagbede

  • Talo nro oko ati ada (a) Alagbede       (b) Agbe
  • Nibo ni won ti nro (a) oko              (b) agbede
  • Kilo fi nro won (a) paanu pelebe       (b) irin pelebe
  • Kiini awon ohun elo ise alagbede (a) ewiri  (b) Agba
  • __________ ni o nlo oko ati ada ti Alagbede nse (a) ode   (b) Agba

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 3                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ASA IKINI

  • Iya _____________ sese bimo ni (a) Sola (b) Yemi
  • Iya ______________ fe lo ki i (a) Adunni (b) Alake
  • O ba ti o gbe __________________ naa lowo (a) Ikoko (b) Oyun
  • Bawo ni a se nki eni ti o nsile (a) ile a tura o (b) ile rewa o
  • Bawo ni a se nki eni ti o bimo (a) Eku ise omo (b) E ku ewu omo

 

Owe Ile Yoruba

  • Pari owe yii: Bami na omo mi ___________________________________________________
  • Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
  • Pari owe yii: Ile la nwo, ________________________________________________________
  • Pari owe yii:: Esin iwaju, _______________________________________________________
  • Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________

 

Ipolowo Oja

  • Oja wo ni a npolowo bayii: langbe jinna o, oroku ori ebe (a) alagbado       (b) orisu
  • Oja wo ni a npolowo bayii: gbetuuru o, omi akerese, kii ndun lodo, to ba dele, adoyin

(a) eleran                         (b) eleja tutu

  • Oja wo ni a npolowo bayii: ___eleelo, o gbona feli feli,     (a) asaro       (b) iyan
  • ___________ re, obe re, ewojo ob eke mu _________ (a) isu (b) iyan
  • Oja wo ni a npolowo bayii: gbanjo, gbanjo, ko lo nle, ko dowo o, oyinbo wo gbese

(a) aso      (b) ounje

 

ETO AGBOOLA: EBI IKEKERE

  • Ipo wo ni baba ko ninu ebi re ____________ (a) olori (b) alagbara
  • Opo kanni _______________ je ninu ebi re (a) egbon (b) iya
  • Awon _________________ ni opo keta ninu eto ebi (a) omo (b) ebi
  • Ise Iya ni lati rii pe ____________ ati ______________ gbogbo ebi nbo si asiko

(a) lilo ati dide    (b) jije ati mimu

  • Ise baba kii se “keremi”, kini itumo “keremi” (a) kekere (b) nla

 

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 4                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

IWE KIKA: BALOGUN IBIKUNLE

  • Balogun Ibikunle je omo (a) Ibadan (b) Ogbomoso (d) Ijaye
  • Ninu awon ogun ti Balogun Ibikunle ja ni ajabegun ni ogun: ______

(a) ijaye ati kutuje (b) Ibadan ati Ijaye (d) ogbomoso ati Ibadan

  • A fi Ibikunle joye Balogun nitori pe o _______

(a) je omo ogbomoso, o si lowo (b) Jagun ajasegun pupo fun Ibadan (d) bimo, o si kole

  • Balogun Ibikunle lokan tumo si pe o ________

(a) le farada isoro           (b) ijegun pupo         (d) ni okan ninu ara re

  • Se alaiye meji ninu ebun ti ibikunle ni ti fi tayo awon elegbe re:

________________________________,     _________________________________

 

IWE KIKA: EFUNROYE TINUBU

  • Oloye Tinubu je ibatan ___________ (a) Akintoye (b) Kosoko (d) Geso
  • Ohun ti o so Iyaafin Tinubu di olowo ni _________ (a) awon egba (b) owo sise (d) Dosunmu
  • Awon Egba fi Iyaafin Tinubu je oye iyalode nitori _______

(a) awon eru re po    (b) o lowo, olooto, o lola     (d) o ran Egba lowo

  • Iyato to wa laarin Tinubu ati Efunsetan ni pe, Tinubu __________

(a) ni opolopo eru    (b) feran gbogbo eniyan     (d) je akoni obinrin

  • Owo re pelu awon oyinbo mo ki o _______ gidigidi (a) binu (b) lagbara (d) lajo

 

AKANLO EDE

  • Kini itumo akanlo ede yii: Tu teru nipa:

(a) Ki eniyan ku                         (b) Ki eniyan salo                (d) Ki eniyan bimo

  • Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori

(a) Ki a fi aake si aarin ori (b) Ki eniyan ko jale lati se nnkan (d) Ki eniyan salo

  • Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle: _____ (a) Edun ti o nrin nile

(b) Edun ti o gbooro gan-an                 (d) Eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago

  • Kini itumo akanlo ede yii: E pa ko boro mo:

(a) e pa ko si ninu oro               (b) ko si atunse mo              (d) ko si epa mo

  • Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe niko: (a) ki a soro pato si ibi ti oro wa

(b) ki a kan abe ni iko               (d) Ki a maa kana be daadaa

 

 

AWON OWE ILE YORUBA

  • Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________
  • Pari owe yii: Kekere lati npeka iroko _____________________________________________
  • Pari owe yii: Aja ti yoo sonu, ___________________________________________________
  • Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
  • Pari owe yii:: Eni jin si koto, ____________________________________________________

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 5                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

OSU NINU ODUN 

  • Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, January _______________ (a) Seere   (b) Erena
  • Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, February _______________ (a) Igbe   (b) Erele
  • Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, March _________________ (a) Erena   (b) Igbe
  • Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, April ___________________(a) Ebibi   (b) Igbe
  • Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, May ____________________(a) Belu   (b) Ebibi

ORO ISE NINU GBOLOHUN

Fa ila si eyi ti o nse oro ise ninu awon gbolohun wonyii:

  • Wale je eba ni ale
  • Isola pa eran ti o tobi
  • Yemi ra iru ati iyo ni oja
  • Tunde mu emu ni oko baba Sule
  • Yetunde sun si ori ibusun re

 

IWE KIKA: AGBEPO LAJA  

  • Bawo ni Tayo se jesi Abiola (a) egbon (b) ore (d) aburo
  • Tani o ru apere (a) Abiola (b) Egbon (d) Tayo
  • Kini baba Olosan pinnu lati se fun Tayo ati Abiola? (a) o pinnu lati na won

(b) o pinnu lati so fun baba won             (d) O pinnu lati fun won ni osan

  • Kini o je ki oro naa dun Abiola pupo

(a) o je iya ona meji   (b) owo ko te Tayo   (d) Baba gba osan re kale

  • Ona wo ni Abiola fi je onigbowo fun Tayo

(a) Oduro nidi igi osan   (b) O ru agbon osan   (d) O gba osan kale

 

 

 

IWE KIKA: ISEGUN OYINBO

  • Omo melo ni Iya Alabi bi ye? (a) omo meta (b) omo kan (d) omo meji
  • Kini mu ki Asabi ke tooto (a) Ebi npa omo re  (b) Oko re kosi nile (d) Giri mu omo re
  • Iru egboogi wo ni won gbe wa fun omo Iya Alabi

(a) Egboogi Ibile        (b) Egboogi oyinbo        (d) Egboogi to pe nile

  • Nigba wo ni Alabi ti pinnu lati ko nipa isegun oyinbo

(a) leyin ti o jade ile iwe   (b) leyin iku aburo re    (d) leyin ti o pari eko re ni yunifasiti

  • Nibo ni Alabi tin se ise isegun oyinbo (a) ni abule (b) ni ilu oyinbo (d) ni yunifasiti

 

 

 

 

 

 

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021

CLASS: PRIMARY 6                                                         SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ORUKO OYE OBA ALAYE

  • Kiini oruko oye Oba Oyo (a) Alaafin (b) Oloyo (d) Lamidi
  • Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Onife (b) Ooni (d) Enitan
  • Kiini oruko oye Oba Ilu Egba (a) Olowo (b) Elegba (d) Alake
  • Kiini oruko oye Oba Ilu Ijebu Ode (a) Awujale (b) Onijebu (d) Sikiru
  • Kiini oruko oye Oba Ilu Osogbo (a) Soun (b) Ata Oja (d) Okere

 

Akanlo Ede

  • Kiini itumo akanlo ede yii: Fa omo yo

(a) Ki eniyan mu omo jade    (b) Ki a se ase yori (d) Ki a ni omo pupo

  • Kiini itumo akanlo ede yii: Eja nba kan

(a) Iroyin buburu tabi, iroyin rere (b) Eja ati akan ni nejeeji (d) Eja kan, Akan kan

  • Kiini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo

(a) Epa ko si ninu oro (b) Ko si atunse mo (d) Epa ko le ba oro

  • Kiini itumo akanlo ede yii: Edun arinle        (a) Edun ti o nrin ni ile

(b) Edun ti o po ganan               (d) Eni ti o ti lowo ri sugbon ti o pada raago

  • Kiini itumo akanlo ede yii: je oju ni gbese

(a) Dara lati wo               (b) san gbese fun oju           (d) Oju gbese to dara

 

IWE KIKA: AJALA TA N NA O

  • Kiini awon ara abule sefun Ajala (a) won buu (b) won kii (d) won na an
  • Ajala maa nse ___________ kiri abule (a) agidi (b) ijangbon (d) omoluabi
  • Omo ________________ ni Ajala (a) lile (b) oponu (d) ole
  • Tan ni suur tumo si __________________

(a) mu suuru patapata    (b) iluwa to le mu ni binu gan-an  (d) gba suuru tan

  • Itumo fa ijangbon ni __________ (a) da wahala sile (b) mu ijangbon dani (d) ni ijangbon lawo

 

IGBAGBO ATI ERO YORUBA NIPA OLODUMARE  

  • Tan Olodumare?
  • So meji nipa Igbagbo awa Yoruba nipa Olodumare