BI A SE N KI IKINI ASA IKINI NI ILE YORUBA
Subject : Yoruba
Class : Jss 2
Term : Second Term
Week : Week 8
Topic :
EDE: Akaye ( ilana kika akaye Onisorogbesi).
ASA: Ikini
LIT: Kika iwe apikeko ti ijoba yan
OSE KEJO
AKAYE ONISOROGBESI Deeti………………..
( Olu ati Aina pade arawon ni ile itura piremia ni Ilu Ibadan. Won ti ri arawon tipe die. Bayi ni won bere oro won.)
Aina Olu, iwo niyen, e ma ku ojo meta.
0lu Emi niyen o, lowo oko aaro.
Aina Se ko si nnkan Olu? O da bi igba wi pe ara re fa die.
Olu Ara mi da ko si nnkan to n se omo olorun. Bi ode ti ri naa ku ni.
Aina Iyen o maa to o ro. Arun gbogbo aye niyen ( Leyin igba ti won joko ).
Olu Aina, Iyawo ati awon omo nko?
Aina Gbogbo won wa daadaa. Igba ti mo tile n bo ni oko mi n mura lati mu awon omo jade
Olu Abi ohun naa wa ninu awon igbimo idagbasoke?
Aina O wa nibe, sugbon emi ko ri si idagbasoke ilu Ibadan.
Olu Nnkan to da ni eto idagbasoke ilu. Looto wahala wa nibe sugbon ojuse gbogbo wa ni.
Aina Bee ni o o paro.
IGBELEWON
- Awon wo ni won n soro ninu akaye yii?
- Ilu ibo ni won ti n soro?
- Ki ni koko oro won?
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
Oyebamiji Mustapha (2009) Eko ede Yoruba titun iwe keji (J.S.S.3) oju iwe 102- 225 231 university Press Plc.
IKINI (GREETINGS)
AKOKO IKINI IDAHUN
Aaro/owuro Ekaaro o o o, a dupe
E e jiire bi o
Osan E kaasan o o o.
Irole E kuurole o o o
Ale E kale o o o
BI A SE N KI IKINI IDAHUN
Aboyun Asokale anfaani o e se o
Nibi isomoloruko E ku ijade oni adun a kari o
Nibi oku E ku aseyinde o eyin naa a gbeyin arugbo yin o
Onidiri Eku ewa/oju gbooro o o
Agbe Aroko bodun de o ase o
Osise ijoba oko oba o ni sayin lese o ami o
Ijoye kara o le wa a gbo.
Oba Kabiyesi o oba n ki o
Eni to n jeun lowo E bamiire o omo rere a ba o je
Nibi oku agba E ku aseyinde o e se o, eyin naa a gbeyin arugbo yin o
ÌGBÉLÉWÒN
1 Bawo ni won se n ki awon wonyi?
- Onidiri
- Agbe
- Nibi oku agba
- Bawo ni won se n ki eniyan ni
- Aaro
- Osan
LITIRESO
Kikai we apileko ti ijoba yan.
IGBELEWON
- Awon wo ni won n soro ninu akaye yii?
- Ilu ibo ni won ti n soro?
- Ki ni koko oro won?
- Bawo ni won se n ki awon wonyi?
- Onidiri
- Agbe
- Nibi oku agba
- Bawo ni won se n ki eniyan ni
- Aaro
- Osan
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
S Y Adewoyin (2003) New simplified Yoruba L1 iwe kin-in-ni [J s s1] oju we 5-7.
ISE ASETILEWA
1. Aroko ti o maa ni asogba ni aroko …. A. asotan B. oniroyin D. onisorogbesi.
2. Aroko onisorogbesi maa n ni eniyan … A. meji si meta B. eni kan soso D.
3 asa iranra-eni-lowo ti o dabi adiye irana ni A. aaro B. ebese D. ajo.
4 … won maa n da owo ninu re sugbon iye ti o ba wu eni kookan ni won maa n da. A. esusu B. ebese D. ajo.
5 Aroko wa gbodo …… A. pani lerin B. kun eeyan loorun D. ba ori oro mu.
APA KEJI
-
- Bawo ni won se n ki n ni: aaro, osan, ale, igba otutu?
- Salaye: ikini.
- Salaye eda itan merin ninu iwe apileko ti o ka.