ERE IDARAYA NI ILE YORUBA

Pry two

Akole:ERE IDARAYA NI ILE YORUBA

 

ERE BOJUBOJU:Ere bojuboju je okan ninu ere idaraya ti awon omode feran lati maa se akoko ti osupa ba tan imole ni won maa gbadun ere naa, idi niyi ti a fi npa ni ere osupa.Awon omode yoo lo pe are won lati ojule si ojule lati adugbo si adugbo,lejin ti won ba jeunale tan ni won,maanse ere bojuboju, nitori awon omo miran kiiranti jeunale nigba ti ere ba ti won won lara.

 

BI WON SE NSE ERE BOJUBOJU.

Awon omode le tobi marundin lo gun tabi jubelo, won yoo yan enikan ti won yoo booju re,ki o maa ba mo ibi tu won fi are pamosi.

Leyin naa won yoo maa le orin awon ti won lo fi ara pamo yoo si maa gbe eni ti o bo loju ni yoo le orin bayii.

Bojuboju o———-oooo

Oloronbo ———–ooooo

Se kinsi————-maa ti si

Eni ti oloro ba mu———– ohun ni yoo diju dipore.

Se ki nsi————o ya si.

Ki awon to si oju re gbogbo won yoo ti fi ara pamo woo maa waeni ti yoo mu, ti o bari eniyah mu, eni naa ni yoo to bo oju, sugbon ti ko ba ri eniyah mu le mata, won yoo ko orin fun,won yoo fi idi re gunyah lemeta.

 

Ise kilaasi

1.Igba so no wonder maa nse ere bojuboju (a)Ale (b)owuro

 

2.ibo ni won ti nse ere bojuboju?(a)ita agangba(b)inu ile

 

3.awon omode melo ni o le se ere bojuboju?(a)meta(b)marundinlogun.

4. Mini oruko eni ti won bo loju(a)oloro(b)olosa

5.kini eni ti won ba mu yoo se(a)yoosun(b)yoobojudipore

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share