SECOND TERM EXAMINATION 2020 CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
SECOND TERM EXAMINATION 2020
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON
1.) Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan
2.) Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu
3.) Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Alangba
4.) Kini o mu ki won re roba Dauda?
(a) ofi npa eye (b) o fi fo agbe emu (d) o fin pa adan
5.) Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye (b) ile-eku (d) adan
IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE
1.) Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba (b) talaka (d) olowo
2.) Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo oja (b) ojo odun (d) ojo ere
3.) Kini Lamurin lo se ni oko ni ojo naa
(a) o lo wa igi (b) o lo wa isu (d) o lo sa obi
4.) Kini o mu inu bi Lamurin
(a) o ri ewu re lorun elomiran (b) omi odo ko kaa lara (d) ko gbadun iwe naa
5.) Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada (b) kumo (d) opa
IKINI LENU ISE ATI IDAHUN
Bawo ni a se nki awon onise owo wonyii, ati bi won se nda wa loun
S/N ONISE IKINI IDAHUN
1.) Alaro
2.) Awako
3.) Akope
4.) Alagbede
5.) Onidiri
ONKA NI EDE YORUBA:
1.) Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 75 (a) arundinlogorin (b) arundinladota (d) arundinlogoji
2.) Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) adojo (b) adofa (d) ogorin
3.) Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) adorun (b) adota (d) ogota
4.) Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 45 (a) arundinlogun (b) arundinladota (d) arundinlogbon
5.) Kini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 130 (a) ogojo (b) ogorun (d) adoje
[mediator_tech]