YORUBA SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 4
IDANWO TAAMU KEJI
SUBJECT: YORUBA CLASS: KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.
- Itumo _______ ni akanlo ede maa n ni (a) geere (b) akanda (d) kikun
- Itumo juba ehoro ni ____(a) fori bale fun ehoro (b) dobale fun ehoro (d) sare lo
- Kin ni Yoruba n fi owe se (a) ibawi (b) jeun (d) salo
- _____ ni atewonro (a) Awolowo (b) Orannyan(d) Oduduwa
- Ta ni o fi omo re rubo fun odo Esinminrin? (a) Moremi (b) Ogunmola (d) olabisi
- Akoni obinrin ni _____(a) oduduwa (b) Awolowo (d) moremi
- Tani o se to eko o fe fun awon omo ile-eko alakoobere ni ipinle iwo orun? (a) Efunroye(b) Awolowo (d) Oduduwa
- ____ je asiri ara oto ninu ede Yoruba.(a) ofo (b) alo (d) owe
- Ohun ti a roki a to so o ni ____(a) aroso(b) aroko (d) ajako
- ___lo gba awon egba sile lowo imunisin oloyoo. (a) Lisabi (b) Awolowo (d) Moremi
- Omo ilu wo ni Basorun ogunmola (a) Eko(b) Ibadan (d) Ekiti
- Kiko ni a maa n ko (a) aroko (b) aroso (d) ajaso
- Oluko ni ki awon akekoo ______bo lati ile(a) ko apeko (b) ko aroko (d) so aroso
- Tani babanla Yoruba? (a) moremi(b) Obafemi (d) Oduduwa
- Kini oruko omokunrin kan ti oduduwa bi?(a) Akindele (b) Okanbi (d) Ejibi
- Iru eniyan wo ni Bamidele je? (a) Odale(b) Ore gidi (d) ole
- Ki lo gbe muyiwa kuro lodo ebi re?(a) Iwe kika (b) ise sise (d) Igbadun
- Itumo ilu Oba ni ____(a) ilu oyinbo(b) ilu ti oba wa (d) ilu oyo
- Oruko iyawo Bamidele ni (a) Ajike(b) Arike (d) Atoke
- Kin ni o sele si Bamidele ni igbeyin?(a) o ku (b) o salo (d) o sare
- Ta ni o lo si ilu oba ninu awon ore yi Bamidele/ Muyiwa
- Aso ise ti kii ya boro ni (a) Buba (b) kijipa(d) oyala
- Aso ti obinrin maa n wo bi awotele ni ____(a) agbeko (b) iro (d) gele
- Aso olowopooku ni aso ____(a) imurode(b) leesi (d) aso isere
- Kin ni a n pe aso ti awon obinrin maa n we sori? (a) ipele (b) fila (d) gele
- Oruko egbe oloselu ti obafemi Awolowo da sile ni ____(a) Alajeseku (b) Afenifere (d) ogboni
- Omo ilu wo ni Obafemi Awolowo (a) Ibadan(b) Eko (d) Ijebu Ikenne
- Awon ilu wo ni o maa n yo ara ile-ife lenu (a) Egba (b) Igbo (d) Ido
- Kini oruko omo Moremi (a) oluorogbo (b) kolade (d) olufemi
- Ilu wo ni Efunroye Tinubu wa tele ri ki o to pada si Abeokuta (a) Ijesa (b) Ijebu (d) Ilu-Ekiti
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. so itumo awon akanlo ede wonyi.
- juba ehoro -_______________________
- Na papa bora ___________________________
- Fera ku – ________________________________
- Foju lounje – ____________________________
- Oba waja – ______________________________
B. Daruko orisii marun-un ninu awon aso ti okunrin n wo ni ile Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
D. Daruko marun-un ninu awon akoni Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
E. Daruko marun-un ninu aso ti awon obinrin n wo ni ile Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. _____________________________________
Oonka Ede Yoruba ookanla (11) titi dé ogún (20) Yoruba Primary 1 First Term Lesson Notes Week 5