YORUBA SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 4

IDANWO TAAMU KEJI

SUBJECT: YORUBA CLASS: KERIN

Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.

  1. Itumo _______ ni akanlo ede maa n ni (a) geere (b) akanda (d) kikun
  2. Itumo juba ehoro ni ____(a) fori bale fun ehoro (b) dobale fun ehoro (d) sare lo
  3.  Kin ni Yoruba n fi owe se (a) ibawi (b) jeun (d) salo
  4.  _____ ni atewonro (a) Awolowo (b) Orannyan(d) Oduduwa
  5.  Ta ni o fi omo re rubo fun odo Esinminrin? (a) Moremi (b) Ogunmola (d) olabisi
  6. Akoni obinrin ni _____(a) oduduwa (b) Awolowo (d) moremi
  7.  Tani o se to eko o fe fun awon omo ile-eko alakoobere ni ipinle iwo orun? (a) Efunroye(b) Awolowo (d) Oduduwa
  8.  ____ je asiri ara oto ninu ede Yoruba.(a) ofo (b) alo (d) owe
  9.  Ohun ti a roki a to so o ni ____(a) aroso(b) aroko (d) ajako
  10.  ___lo gba awon egba sile lowo imunisin oloyoo. (a) Lisabi (b) Awolowo (d) Moremi
  11.  Omo ilu wo ni Basorun ogunmola (a) Eko(b) Ibadan (d) Ekiti
  12.  Kiko ni a maa n ko (a) aroko (b) aroso (d) ajaso
  13.  Oluko ni ki awon akekoo ______bo lati ile(a) ko apeko (b) ko aroko (d) so aroso
  14.  Tani babanla Yoruba? (a) moremi(b) Obafemi (d) Oduduwa
  15.  Kini oruko omokunrin kan ti oduduwa bi?(a) Akindele (b) Okanbi (d) Ejibi
  16.  Iru eniyan wo ni Bamidele je? (a) Odale(b) Ore gidi (d) ole
  17.  Ki lo gbe muyiwa kuro lodo ebi re?(a) Iwe kika (b) ise sise (d) Igbadun
  18.  Itumo ilu Oba ni ____(a) ilu oyinbo(b) ilu ti oba wa (d) ilu oyo
  19.  Oruko iyawo Bamidele ni (a) Ajike(b) Arike (d) Atoke
  20.  Kin ni o sele si Bamidele ni igbeyin?(a) o ku (b) o salo (d) o sare
  21. Ta ni o lo si ilu oba ninu awon ore yi Bamidele/ Muyiwa
  22. Aso ise ti kii ya boro ni (a) Buba (b) kijipa(d) oyala
  23. Aso ti obinrin maa n wo bi awotele ni ____(a) agbeko (b) iro (d) gele
  24.  Aso olowopooku ni aso ____(a) imurode(b) leesi (d) aso isere
  25.  Kin ni a n pe aso ti awon obinrin maa n we sori? (a) ipele (b) fila (d) gele
  26.  Oruko egbe oloselu ti obafemi Awolowo da sile ni ____(a) Alajeseku (b) Afenifere (d) ogboni
  27.  Omo ilu wo ni Obafemi Awolowo (a) Ibadan(b) Eko (d) Ijebu Ikenne
  28. Awon ilu wo ni o maa n yo ara ile-ife lenu (a) Egba (b) Igbo (d) Ido
  29.  Kini oruko omo Moremi (a) oluorogbo (b) kolade (d) olufemi
  30.  Ilu wo ni Efunroye Tinubu wa tele ri ki o to pada si Abeokuta (a) Ijesa (b) Ijebu (d) Ilu-Ekiti

IPIN KEJI

Dahun gbogbo awon ibeere wonyi

A. so itumo awon akanlo ede wonyi.

  •  juba ehoro -_______________________
  •  Na papa bora ___________________________
  • Fera ku – ________________________________
  • Foju lounje – ____________________________
  • Oba waja – ______________________________

B. Daruko orisii marun-un ninu awon aso ti okunrin n wo ni ile Yoruba

i. _____________________________________

ii. ____________________________________

iii.____________________________________

iv.______________________________________

v. ______________________________________

D. Daruko marun-un ninu awon akoni Yoruba

i. _____________________________________

ii. ____________________________________

iii.____________________________________

iv.______________________________________

v. ______________________________________

E. Daruko marun-un ninu aso ti awon obinrin n wo ni ile Yoruba

i. _____________________________________

ii. ____________________________________

iii.____________________________________

iv.______________________________________

v. _____________________________________

Oonka Ede Yoruba ookanla (11) titi dé ogún (20) Yoruba Primary 1 First Term Lesson Notes Week 5 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share