PRIMARY 1 YORUBA LANGUAGE

            SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

ERE IDARAYA: – ERE OKOTO

Eniyan _____ ni o nta okoto le e kan naa (a) meji     (b) mefa

Ori ______ ni a ti maa nta okoto          (a) eni      (b) ile

_________ ti a ka, ti idire ri soso ni a fin se okoto (a) paanu  (b) ike

Okoto maa ____________ rainrain ti a b anta (a) sun (b) njo

A maa __________ okoto nigba ti a ba nta (a) nde (b) sun

 

ERE IDARAYA:- ERE AYO

Eniyan ______ ni o nta ayo olopon (a) meji      (b)  merin

Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) merin merin (b) mefa mefa

Owo ________________ ni a maa nta ayo (a) Ale (b) Irole

Apa ___________ ni a maa nta ayo si (a) otun (b) osi

Omo ________ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidin logun (b) mejidin ladota

ORIN IREMOLEKUN 

Talo ba mi ni _______ wi o? (a) lomo     (b) loko

______ e lo ba a wi o? (a) egbon (b) iya

___________ mi o akuru bentekuse (a) omo (b) oko

Bi o ku o, maa ___________ fun o (a) igi  (b) raso

Bi o ku, maa ra ______ orun (a) egba   (b) okun

 

AFINJU EYE:- EYELE

Inu _________ ni eyele ngbe (a) ile (b) igbo

________ kii gbe inu igbe (a) adaba (b) eyele

O ____________ tonitoni (a) mo (b) run

O __________ tonitoni bora (a) Aso (b) Iye

______________ leyele (a) afinjo    (b) obun

 

PRIMARY
1   
  SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:………………………………………………………………………………………………………
Dahun gbogbo ibeere
wonyii
(Answer the following questions) 
1.)Tumo
awon oro wonyii (Write out these words in English) 
(a)Ile
=
(b) Omi
=
(c)Osan
=
(d) Iwe
=
(e)Abo
=
(f)Ewa
=
(g)Omo
=
(h) Abo
=
(i)Tabili
=
(j)Aga
=
2.)Ko
apeere marun fun silebu kan
3.)Pari
awon alifabeti wonyii
A
___   ___   ___   E
F   ___   ___   ___   ___
J    ___   ___   M    ___
___   ___  P

 

 

 

More Exams Links 

 

PRIMARY 1 YORUBA LANGUAGE