

SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… 1.) Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije 2.) Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won IWE KIKA DAROSA 1.) Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko (b) egbe ti o nko (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni 2.) Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo (a) o nya won lowo (b) o nran won nile eko (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe 3.) Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo? (a) o nraso ile-eko fun won (b) o nfun won ni eko-ofe (d) o nra aso odun funwon (e) o nfun won ni ebun owo 4.) Nibo ni darosa ti nri owo tire? (a) nibi ole jija (b) nibi jibiti lilu (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re 5.) Darosa nfe ki omode ______ (a) feran obi (b) maa sa ni ile-eko (d) fi oju si eko re (e) di fole fole OWE ILE YORUBA 1.) Pari owe yii: Agba kii nwa loja __________________________________________________ 2.) Bami na omo mi, _____________________________________________________________ 3.) Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________ 4.) Esin iwaju, __________________________________________________________________ 5.) Obe ti baale ile kii nje, _________________________________________________________
Am a dedicated educator with a passion for learning and a keen interest in technology. I believe that technology can revolutionize education and am committed to creating an online hub of knowledge, inspiration, and growth for both educators and students. Welcome to Edu Delight Tutors, where learning knows no boundaries.
Most Read Posts This Week
Spread the Word, Share This!
Like this:
Like Loading...
Explore Further
About The Author
Edu Delight Tutors
Am a dedicated educator with a passion for learning and a keen interest in technology. I believe that technology can revolutionize education and am committed to creating an online hub of knowledge, inspiration, and growth for both educators and students. Welcome to Edu Delight Tutors, where learning knows no boundaries.