ISORI GBOLOHUN
SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: SECOND WEEK OSE KEJI ISORI GBOLOHUN Oríkì Ìsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹ Akóónú Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí