OWE ILE YORUBA (Pry 6)
Pry six Akole: OWE ILE YORUBA Eni ti yoo je oyin inu apata,koni wo enu aake Oju ti yoo baa ni kale, kin ti owuro sepin ile ti afi to omo,iri ni yoo wo kekere la ti npeka iroko,toba dagba tan apa kii nka Bi omode mo owo we,aba agba