OSE KẸRIN AKORI EKO: APOLA INU EDE YORUBA Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Gbolohun le je eyo oro kan tabi akojopo oro ti oni itumo. Ihun gbolohun ede Yoruba dabi igba ti a bah un eni, a ni lati to awon oro wonyii jo lona ti yoo fi le e
OSE KINNI AKORI EKO: FONOLOJI EDE YORUBA Fonoloji ni imo eto amulo iro lapapo. Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori si gbolohun ede Yoruba ni a n pen i fonoloji. Iro Faweli: Eyi ni awon iro
Ò̩SÈ̩ 3 EDE: Akoto siwaju JEC 1974; Agbeyewo ipinnu 1974 ti ijoba apapo lori akoto Yoruba (Joint Consultative Committee-JCC ASA: Itoju Alaboyun (1)Igbagbo Yoruba nipa agan, omo bibi ati abiku. Awon ti oyun nini wa fun (tokotaya). Ona ti a le gba din bibi abiku ku lawujo wa; Orisiirisii jenotaipu eje to wa ati
FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022 CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:……………………………………………………… EWI: IBAWI E dake je je je Omo ile eko, e gbohun enun mi, E je nkorin ara si yin leti Bee romo ile eko Ti-nsojika Ti-nwarun-unki To tun nkotiikun soro agba IBEERE: 1.) Arofo yii nba omo ________________ wi (a) ile-eko (b) ile-ise
Edu Delight Tutors Subuode Gbaga Gasline Ogun State 1st Term Examination YORUBA JSS 3 IPIN A Ka ewi yii ki o si dahun ibeere ti tele e Bi won ba n ba o soro Jowo ma se binu omo Eni oyinbo feran lo n ti mole Omo obi fera lo n ba wi Igba obi
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… Imototo Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu Ge _________ re ni asiko ti o ye (a) imu (b) irun Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b)
Yoruba basic four Faweli meloo lo wa ninu oro yii ? Aso (a) Eyookan (b) meji (d) meta Faweli meloo lo wa ninu oro yii ? Bata (a) meji (b) meta (d) merin Konsonanti inu oro yii ni IJAPA (a) I,J (b) J,P (d) P,A Konsonanti inu oro yii ni IGO (a) I (b) G
1. Kini a npe ni iro faweli 2. Oríṣi ọna ti àbùdá ìró Fawẹ̀li pinsi 3. Yíya ate faweli airanmupe àti aranmupe 1. Ìró faweli ni èyí tí èémí mú jáde ní pipe rẹ láìsí idiwo kankan nínú eka ẹnu, àpẹẹrẹ ìró faweli èdè Yorùbá ni a, ẹ, ẹ, í, ó, ọ, ú,. Àwọn wọ̀nyí