JSS 2

Isori oro +ninu gbolohun

OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si.   Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION ) EKA

Aroko atonisona Alapejuwe

OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE. Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu

ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE.

OSE KESA-AN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE. Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A

ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100).

OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57

ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50).

OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo 9 Eesan-an 10 Eewaa 11 Ookanla 10+1=11 12

EKA ISE: EDE

OSE KEFA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKOTO AWON ORO TI A SUNKI Akoto ni sipeli titun ti awon onimo ede Yoruba fi enu ko le lori ni odun 1974 lati maa lo. Sipeli atijo Sipelu titun Olopa Olopaa Na Naa Orun Oorun Ogun Oogun Anu Aanu Papa Paapaa Suru Suusu Alafia Alaafia Oloto Oloooto

Akoto ode oni

OSE KARUN-UN EKA ISEl LITIRESO AKOLE ISE: Akoto ode-oni Akoto ni ona ti a n gba ko ede Yoruba ni ona ti o bojumu ju ti ateyinwa lo. Alaye lori akoto ode-oni Ede Yoruba di kiko sile ni odun 1842 Pelu iranlowo awon ajihinrere ijo siemesi bisobu Samueli Ajayi crowther ati Henry Townsend. Ile ijosin

SILEBU

OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: SILEBU Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo. Iye ami ohun ti o jeyo ninu oro kan ni iye silebu iru oro bee. Ihun oro orusilebu kan le je, I faweli nikan –(F) ii Apapo konsonati ati

Ami Ohun lori oro onisilebu meji

OSE KETA Eka Ise Ede Akole Ise Ede Ami Ohun lori oro onisilebu meji i ba – ta(shoe) (dd) – kf – kf ii E – we(leaf) (rd) – f – kf iii A– ja(dog) (rm) – f – kf iv Ba – ba (father)(dm) – kf – kf v Ti – ti(a name of