Yoruba Literature BECE Past Questions : Test Your Knowledge with These JSS 3 Questions!
LAGOS STATE MINISTRY OF EDUCATION EXAMINATIONS BOARD
2024 BASIC EDUCATION CERTIFICATE EXAMINATION
YORUBA LANGUAGE
LASEB/BECE/YORUBA/2024/012
INSTRUCTIONS TO CANDIDATES
This paper consists of One Section Only.
Time: 2hrs
- Write your Examination number in the space provided.
NAME:
(Complete your name as it should be written; Surname first followed by other names.)
NAME OF SCHOOL:
- Do not open this Question Booklet until you are told to do so. While you are waiting, read the following instructions carefully:(i) Attempt all questions. In Section A, each question is followed by four options lettered A-D.
(ii) Find out the correct option for each question and shade your answer.
(iii) Do not spend too much time on any question. If you find a question difficult, leave it and try it again later.
(iv) YOU ARE ADVISED TO WORK COMPLETELY ON YOUR OWN.
- Àṣìlò ọ̀gùn olóró di:A. Aláágánná
B. Ológbón
C. Olópolo pipe
D. Alálísé - Akẹ́kọ̀ọ́ tó bá n lo ọ̀gùn olóró kò lè:A. Kó lẹ́kọ́ọ́ yéye
B. Kò lè lo sí ilú ọ̀yinbó
C. Kò lè jà
D. Kò lè bí ọmọ - Àkọlé tó bá ẹ̀wì yìí mu ni:
A. Ìmòràn òbí àti olùkọ́
B. Ọ̀gùn olóró
C. Akẹ́kọ̀ọ́
D. Abíàmọ
- Fonólójì ni ẹ̀kọ́ nípa:
A. Sílébù
B. Kònsónántì
C. Àwọn ìró èdè
D. Ìsàlè òrò
- Létà tí a kọ sí Gíwá ilé ẹ̀kọ́ wa láti fi chónú hàn ni:
A. Létà chónú
B. Létà ifẹ́
C. Létà gbéfé
D. Létà àìgbéfé
- Létà tí a máa ń bèrè pẹ̀lú “Bàbá mì tòótọ́” jẹ́:
A. Létà àìgbéfé
B. Létà àìgbéfé àti gbéfé
C. Létà tí a kọ sí ògá ẹni
D. Létà gbéfé
- “Lílò èrò igbálódé kó àwọn akékòó sàn ju lílò ojú pátákó àti ẹ̀fun ìkòwé lọ” jẹ́:
A. Àròkọ aláláyé
B. Àròkọ onísòròngbèsì
C. Àròkọ aláríyànjiyàn
D. Àròkọ àṣòtàn
- Àròkọ Èdè àti Àṣà Yorùbá tí a ṣe ní ilé ẹ̀kọ́ mi jẹ́ àpẹẹrẹ:
A. Àròkọ Àṣapẹ̀júwe
B. Àròkọ Àṣòtàn
C. Àròkọ Aláríyànjiyàn
D. Àròkọ Aláláyé
- Àpẹẹrẹ orí àròkọ alátayé ni:
A. Ìkìlọ̀
B. Bí mo ṣe lo ìsinmi mi tó kọjá
C. Ìgbà tí ó dára
D. Eré ìdíje onílẹ̀jidé tí a ṣe ní ilé ẹ̀kọ́ mi
- Ẹ̀wà ní inú àwọn kókó wọ̀nyí ni kò wúlà nínú àròkọ kọ́ ní èdè Yorùbá?
A. Awòrán yíyà
B. Àjàrá
C. Ìgúnlè
D. Ìtápà èrò
- Ẹ̀wo ni fáwélì àrànmúpé nínú àwọn wọ̀nyí?
A. In
B. Àtàárá
C. Ló
D. On
- Kònsónántì àrànmúpé asesilébù nínú àwọn wọ̀nyí ni:
A. Wàtib
B. Nátìn
C. Nàtì un
D. Mátì in
- Ẹ̀wo ni èyà ara ifọ́ / ìpèró nínú àwọn wọ̀nyí?
A. Owó
B. Ojú
C. Ẹ̀sè
D. Ètè
- Àwọn èyà ara ifọ́ / ìpèró tó dúró gbàárí sí ojú kan tí a bán sọ̀rọ̀ ni:
A. Àfípe àsúnsi
B. Àfásé
C. Ẹ̀dòfóró
D. Àfípe àkànmòle
- Ìtápà tí a fi ṣe àpẹẹrẹ “Ogẹ́dẹ̀ ni”:
A. KFFKF
B. FFKKF
C. FKFKF
D. KFFKF
- Òrò tí a ṣe pẹ̀lú KFKFKF ni:
A. Ògẹ́dẹ̀
B. Fáwélì
C. Bàbànlá
D. Alàyé
- Òrò orúkọ tí a ṣe pẹ̀lú àpèjúwe Apóláìṣe ni:
A. Péjápéjà
B. Òmòòmò
C. Òsòbò
D. Òdòdún
- Ayélabólá jẹ́ òrò onísílébú mélòó?
A. Márùn-ún
B. Méta
C. Méra
D. Mérin
- Pín òrò yìí sí sílébù “Alantakun”:
A. A-lá-nta-kün
B. A-lá-n-ta-kün
C. A-lán-ta-kün
D. A-la-n-ta-ku-n
- Èwo ni kí í ṣe lórí òrò inú èdè Yorùbá nínú àwọn wọ̀nyí?
A. Òrò-ìṣe
B. Òrò-òrúkọ
C. Ìṣe-dá-prò
D. Òrò-àtòkun
- Fi àmì ohùn sí orí òrò yìí “Akoko” (Time):
A. Akoko
B. Akokó
C. Akóko
D. Akóko
- Àpẹẹrẹ òrò arópò àfàràjò-rúkọ èyí ni:
A. Àwa
B. Àwọn
C. Ẹ̀yìn
D. Òun
- Àpòlà orúkọ nínú gbólóhùn òkè yìí ni:
A. Pa ẹyẹ
B. Odẹ pa ẹyẹ
C. Bàbá odẹ
D. Odè pa ẹyẹ
- Mo jẹ́ ẹ̀kọ́ (méjì) ní àná. Òrò tó wà nínú àkámọ́ jẹ́:
A. Ẹ̀yàn àfihàn
B. Ẹ̀yàn àṣònkà
C. Ẹ̀yàn àṣàpèjúwe
D. Ẹ̀yàn aláláyé
- Ìsòrí òrò tó máa ń fún gbólóhùn ní ìtumọ̀ ni:
A. Òrò-ìṣe
B. Òrò-òrúkọ
C. Òrò-arópò-òrúkọ
D. Òrò-àtòkun
- Gbólóhùn tó ní ẹ̀yà òrò-ìṣe kan ṣoṣo ni a n pè ní:
A. Gbólóhùn abódé
B. Gbólóhùn ìbéèrè
C. Gbólóhùn alákanpò
D. Gbólóhùn gígbàpọ̀ òrò-ìṣe
- Nígbà wo ni ógà de 7 jé?
A. Gbólóhùn aláláyé
B. Gbólóhùn ìbéèrè
C. Gbólóhùn gígbàpọ̀ òrò-ìṣe
D. Gbólóhùn eléyà òrò-ìṣe
- Péjú ṣe ògèdè dúdú, “Dúdú” jẹ́ àpẹẹrẹ ìsòrí?
A. Òrò-àtòkun
B. Òrò-òrúkọ
C. Òrò-àpèjúwe
D. Òrò-àpónlé
- Inú gbólóhùn tí a tí là rìí awé – gbólóhùn ni:
A. Gbólóhùn eléyà òrò-ìṣe
B. Gbólóhùn àyísódi
C. Gbólóhùn aláláyé
D. Gbólóhùn oníbò
- Bí mo ti délé, mo jẹun. “Mo jẹun” jẹ́:
A. Awé gbólóhùn afáráhẹ̀ àpónlé
B. Awé gbólóhùn afáráhẹ̀ àṣòdorúkọ
C. Awé gbólóhùn afáráhẹ̀ àṣàpèjúwe
D. Olórí awé gbólóhùn
- Délé jókòó sí orí àga. Òrò àtòkun inú gbólóhùn yìí ni:
A. Délé
B. Orí
C. Sí
D. Jóko
- Èwo ni àkọtó rè kò tònà nínú òrò wọ̀nyí?
A. Pétélè
B. Pépèlye
C. Pélépèlé
D. Pápaàpá
- Àpẹẹrẹ èyà ara ifò tí a kò lè fojú rí ni:
A. Kòmoòdùn
B. Ẹnu
C. Etè
D. Àjà ènìyàn
- Parí òwe yìí: “Eni tó yá ẹ̀gbàáfà tí kò san”:
A. Ọ̀ bégi dínà ẹ̀gbèjè
B. Kò ní náwó tán
C. Yóò lówó tó pọ
D. Ọ̀ di dandan kó ní ẹ̀gbàáwàá
- Kín ni ònkà Yorùbá fún 230?
A. Òpẹ̀tẹ́rùgbà
B. Òlérúgba dín mẹ́wàá
C. Òjílérúgba lé méwàá
D. Òjílérúgba dín mẹ́tà
- Òkóólérúgba dín méwàá jẹ́:
A. 220
B. 222
C. 210
D. 230
- Ònkà èdè Yorùbá fún 480 ni:
A. Òtálé nírínwó
B. Òkóólé nírínwó
C. Òjílè nírínwó
D. Òrìnlé nírínwó
- Túmọ̀ gbólóhùn èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí sí èdè Yorùbá: “Pride goes before destruction”
A. Igbéraga ní èrè
B. Igbéraga jẹ́ àfojúdí
C. Igbéraga máa n borí
D. Igbéraga ni í sáájú ìparun
- Ejilé lóóódúnrún jẹ́:
A. 402
B. 202
C. 302
D. 102
- Òjílè lóóòdúnrún jẹ́:
A. 335
B. 340
C. 345
D. 350
- “Charity begins at home” túmọ̀ sí:
A. Ilé ni a ti n kọ́ ẹ̀sùn ròde
B. Ifẹ̀ fúnni bẹ̀rẹ̀ láti ilé
C. Ilé ni ẹ̀kọ́ wà
D. Ó dára láti láwò
- “Our future will be great” túmọ̀ sí:
A. Ọjọ́ òla wa yóò dára
B. A ó gbádùn ní òla
C. Òní là mọ̀, a kò mọ̀ òla
D. Ìgbádùn ni ti wa lójọ́ òla
- “A good student should try to break new ground” túmọ̀ sí:
A. Akékòó gidi gbódò kàwé
B. Akékòó gidi gbódò gbìyànjú láti ṣe ohun tuntun
C. Akékòó gidi gbódò lè lu ilé
- “Our teacher tells us that cutting corners is not profitable” túmọ̀ sí:
A. Olúkó wa sọ pé gbígba kòrò dára
B. Olúkó wa sọ pé gígé igun kò dára
C. Olúkó wa sọ pé ogbón àrékérekè kò lérè
D. Olúkó sọ fún wa pé ogbón wa kò lérè
- Òmò Okànbí tó jẹ́ obìnrin ni:
A. Aláàfin
B. Òṣèmáwé
C. Aláké
D. Olówó
- Tún òrò yìí kọ́ ní akótó òde – “Tafía lo offa”:
A. Taffa lo offà
B. Tafá lo tafa
C. Táfá lo offà
D. Tafá lọ offà
- Òkúnfà ogun jijà láyé àtijọ́ ni:
A. Ibáṣepò láàárín ìlú méjì
B. Pípẹ̀tù sááwọ̀ láàárín ìlú méjì
C. Ijà à à lá ilé
D. Títùbà
- Parí gbólóhùn yìí: “aboyún bí, ara:
A. sófo
B. wúwo
C. tutù
D. ú
- Igbésẹ̀ akókó nínú àṣà ìgbéyàwó abínibí Yorùbá ni:
A. Ìfojúsóde
B. Alárina
C. Ìbálé
D. Itòrò
- Adíá fún jéyò nínú ewi alárèmésìn ni:
A. Ẹ̀sè Ifá
B. Ẹ̀sà egúngún
C. Òfò
D. Òríkì orílẹ̀
- Ọ̀kan lára onà tí Yorùbá n gbà ṣe itójú aboyún láyé àtijọ́ ni:
A. Lílò oògùn òyinbó
B. Jíjẹ̀ àsèjẹ̀ àti mímu àgbo onírúurú
C. Rírí dókítà onísègùn òyinbó
D. Gbígba abéré àjẹ̀sára
- Ọ̀kan lára ògè ṣe nílé Yorùbá láyé àtijọ́ ni:
A. Etè kikun
B. Irun jijó
C. Laán iné
D. Sòkòto wiwò fún obìnrin
- Báwo ni a ṣe n kí akópẹ́?
A. Igbà á dá o
B. Ojú gbooro o
C. Kwó á yá o
D. Igbà á ró o
- Àṣà ìranra ènìyàn lówó tó jẹ́ iṣẹ́ ìlú ni:
A. Arokodóko
B. Ẹ̀bèsè
C. Òwe
D. Owó elé
- Babaláwo là n kí pé:
A. Aboyè bó ṣe jẹ
B. Kífá ó gbà o
C. Ifá á ṣe o
D. Aborúboyè o
- Ọ̀kan lára iṣẹ́ abínibí ilè Yorùbá ni:
A. Iṣẹ́ Qlópàá
B. Iṣẹ́ Agbẹdẹ
C. Iṣẹ́ Tíṣà
D. Iṣẹ́ Woléwolé
- Itún ló ni kí ę tún mi ṣe, tfà ló ni kí ę fà mí mọ́ra. Abèèrè ló ní kí ę firè gbogbo bèèrè mi. Irúfé ewi alòhùn wo nìyí?
A. Òfò
B. Òríkì orílẹ̀
C. Ẹ̀sà egúngún
D. Ìyère Ifá
- Èni tó tí kú ni Yorùbá n pè ní:
A. Olóògbé
B. Ológbe
C. Ológbè
D. Ológbèé
- Èwo ni orúkọ àbíkú nínú àwọn orúkọ wọ̀nyí?
A. Alná
B. Dálísí
C. Dáódù
D. Alágbé
- Lára ojúṣe ọmọ́lúàbí ni:
A. Kì í kékòó
B. Kì í jísé fún àgbàlagbà
C. Kí ó ní ìteríba fún àgbà
D. Kì í wá sí ilé ẹ̀kọ́ déédé
- Fijábí tó jẹ́ olórí egbé áwọn akékoó ro gbogbo akékoó pé:
A. Kí àwọn darapò mọ́ egbé ökünkün
B. Kí àwọn máa dáwó fún egbé ökünkün
C. Kí àwọn máa sayésí egbé ökünkün
D. Kí àwọn gbógún ti àwọn ẹgbé ökünkün
- Igbà mélòó ni Ayobámi fidí rẹmi nínú idánwò Waęęki tó ṣe?
A. Igbà méjì
B. Igbà mẹ́ta
C. Igbà mẹ́rin
D. Lékan ṣoṣo
- Nínú ìwé Lítírésò Apiléko “Ayédèrú”, ta ni ó fún Tìnú lóyún tí kò gba oyún náà?
A. Jíbówú
B. Ayobámi
C. Tóyè
D. Dáre
- Ta ni ènìyàn tí ó sọ gbólóhùn yìí “ní báyìí lì tì gbé e mì” nínú ìwé Ì?
A. Móníjà Donald
B. Bísi
C. Wolé
D. Déglá
- Nínú ìwé Ì, ènìyàn tí àwọn òyìnbó mú lọ sí ọ́ lù oyìnbó láti máa gbá bóòlù nínú àwọn ọmọ sadé ni:
A. Målik
B. Fareed
C. Fareedah
D. Táyé àti Kéhindé
- Ìwà……….. kò sí nínú ìwà omolúàbí nínú ìran Yorùbá?
A. Ìranra ènìyàn lówó
B. Ifipábánilòpò
C. Ìbọ́wọ́fúnni
D. Ìsapónlé
- Ekó pàtàkì kan tí ìwé Témiòtán ký wa ni pé:
A. Ìṣẹ́ ibi ló dára ká máa ṣe
B. Ìwà ànikànjopón ló yẹ ká máa hù
C. Ìṣẹ́ ibi àti ìwà lká kò dára láwùjo
D. Ìwà omolúàbí kò dára láwùjo
- Ta ni olósèlú tí ó fé du ipò Góminà llú rẹ nínú ìwé “Témiòtán”?
A. Oyerindé
B. Oritóóké
C. Feyisayo
D. Ogbónmipo
- Kini ó mú kí oko Eniopétósí kó ó sílẹ̀?
A. Nítorí pé ó jẹ́ oníwàálá obìnrin
B. Nítorí pé kò ní ìwà
C. Nítorí pé ó máa n sọ́rẹ
D. Nítorí pé kò bí ọmọ
- Odún wo ni “Awólówo Hannah Idowú Dideolú”, tó jẹ́ ìyàwó Awólówo, jáde láyé?
A. 1983
B. 1966
C. 2015
D. 1978
- Awólówo jà fún ìsọdáàgà Naijiria àti fífi òpin sí ogún abélé ní odún:
A. 1909
B. 1920
C. 1967
D. 1987
- Ekó pàtàkì tí a kó nínú ìwé “Awólówo Akínkanjú Àṣíwájú” ni pé:
A. Kí á kávé dójú àmi nítorí ìwé ló mú kí ó gbàgbé ní gbogbo ayé
B. Kí akẹ́kọ̀ọ́ máa ṣe ìrànlọ́wọ́ kiri
C. Kí a máa ṣe yáà
D. Kí a fara balè já òlé
- Ekó tí a kó nínú ìwé “Èmi lóko ìyà wọn” ni pé:
A. Kí a máa sọ òtítọ́, olóòtítọ́ kì í kú sípò ika
B. Kí a máa ṣe madárú
C. Kí a gbọ́yè nínú ìrọ̀ pípa
D. Kí a máa fárí olórí
- Eni tí ó jẹ́ olú êndá ìtàn nínú ìwé “Èmi lóko ìyà wọn” ni:
A. Dágunró Iṣọlá
B. Làmbę Béyídùkú
C. Gbádébo
D. Titilayo
- Ta ni ó sọ pé “bun ni oko ìyà wọn” nínú ìwé “Èmi lóko ìyà wọn”?
A. Billámínú
B. Dágunró
C. Mobólájí Okin
D. Ayodélé Gbádégesin
- Nínú tán “Ìjà à dolà,” eni tí Ayomidé fé é fé ni:
A. Oyewolé
B. Olúwolé
C. Okétádé
D. Jíde
- Orúkọ bàbá tí ó máa n sọ́ tààrà fún àwọn ọmọ rẹ̀ ní abé igi odàn ni ilú Akogun ni:
A. Tijáni
B. Ayomidé
C. Adabà
D. Ayédogbón
- Nínú tán “Ajá tó bá fé sókùn,” eni tí ó jẹ́ ajá tó sókùn tí kò gbọ́ fèrè olódè ni:
A. Fáróhunbí
B. Akanbí
C. Fárèmí
D. Oyétúndé
- Nínú ewi “Ìbọ́wòfàgbà,” akéwé sọ pé ọmọ tó bá fé lu alùyà gbódò:
A. Fa wahálà
B. Té rìbá
C. Kí á kúrò ní ilé
D. Mú kó dáa
- Nínú ewì àpilèko “Ajiméfun” àti ewì míìràn, iru iṣẹ́ wo ni akéwé pè ní iṣẹ́ AJÍMÉFUN?
A. Iṣẹ́ olúkóni
B. Iṣẹ́ Noosĩ
C. Iṣẹ́ Imọ̀ èrò
D. Iṣẹ́ woléwolé
- Nínú ewì “Ẹ̀kọ́ se kókó,” akékoó tó bá kàwé ní akàyanjú lè di:
A. Gómina àti Ààrẹ orílẹ̀-èdè
B. Oníjàngbọn àti oníwàhálà
C. Ọmọ iṣẹ́ àti alárinká
D. Awakò àti agbẹ́rò
- Nínú ewì “Erù àgbà,” kí ni ohun tí ó dà bí eni pé arúgbó dé filà fúnfun sórí ní orí àgbà?
A. Fila aṣọ alá.
B. Ewú orí àgbà.
C. Òògùn tí wọ́n dé sóri.
D. Aṣọ funfun tí wọ́n wo.
- Nínú ewì “Gbèsè níkù,” akéwé ri ikú gégé bí:
A. Oré àtàárọ̀
B. Alájosepò tó dára
C. Ipẹ̀kun irinàjò èdá
D. Idáwọ̀p ìdùn
- Nínú ewì “Ẹ má bàgbà jé,” eni tó bá gba òpá lówó arúgbó:
A. Kò ní jẹun
B. Kò ní woso
C. Kò ní wòkò
D. Kò ní dàgbà
More Useful Links
- BECE Comprehensive Quiz on Basic Science, Technology, and Physical Education for JSS3
- Comprehensive Guide to BECE English Language Exam Questions and Answers
- Essential Guide to the Lagos State Basic Education Certificate Examination: English Language 2024
- Cultural and Creative Art BECE Past Questions : Test Your Understanding