Second Term Revision and Readiness Test Yoruba Primary 2 Second Term Lesson Notes Week 1
Ise: Ede Yoruba
Kilasi: Oniwe Keji
- Awon nkan ayika ninu ile ………………………………….. ………………………………..
- A n wo ere ori itage ati oniruuru iran lori …………… (a) telifisan (b) biriji
- A maa n gbo iroyin lori ……………… (a) igi (b) redio
- A maa n sun lori ……………………………………………… (a) Beedi (b) Eweko
- A maa n dana lori …………………………………… (a) omi (b) sitofu
- A ma n joko lori ………………….. (a) aga (b) okun
Isoro n gbesi laarin Deyo ati Deyo
- Ojo ………………….. ni ojo ibi Deyo ku. (a) mefa (b) mewa
- Ni osu ………………… ni Deyo maa n se ojo ibi re (a) kefa (b) kejila
- Kinni awon mejeeji yio pin fun awon ore won? (a) ebun (b) owo
- Kinni won ge? (a) akara oyinbo (b) buredi
- Mo ti ra aso …………………… (a) ofi (b) igan
Ki ni oruko nomba yii ni ede Yoruba?
- 9 (a) eeje (b) eesan
- 12 (a) ejila (b) erijnla
- 15 (a) aarundinlogun (b) eetadinlogun
- 10 (a) eejo (b) eewa
- 7 (a) eeje (b) aarun-un
Awon nnkan ayika wa ninu ile eko
- A maa n fi ………………………….. ko nnkan si ara patako (a) efun (b) igi
- A maa n joko sori ………………………………. (a) beedi (b) aga
- A maa n fi …………………… fa ila (a) rula (b) patako
- A maa n fi ……………………… ya aworan (a) biro (b) pensulu