MID TERM TEST FIRST TERM YORUBA SS 2
FIRST TERM MID TERM TEST
Subject: YORUBA Class: S.S 2 Time:
Apa kinni
Dahun gbogbo ibeere
Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee
Ise agbe se Pataki. Gbogbo eiyan lo mo ise ribiribi ti awon agbe n se lawujo. Idi ti a fi gbodo mu ise agbe ni okunkun dun iyii. Gege bi a se mo,awon agbe lo n gbin oiruuru ounje ti a n je. Lai si akitiyan awon agbe, nje enikeni le wa? Ti elomiran ko ba ri ounje je ni oko kan, a dabi eni pe eni naa ko jeun lati bi ojo meta seyin ni.
Bi a se ni agbe olunje naa ni a ni agbe eleran osin. Iru awon agbe yii amaa sin awon eranko bi maluu, ewure, adiye ati bee bee lo. Awon eranko wonyi ni a n pa, ti a si fi se obe eyi ti o n tu eje ati ara wa se.
Oniruuru aso ti a n wo n naa je ise owo agbe. Awon lo n gbin owu ti a fi n hun aso . isori awon agbe olohun osin naa maa n lo awo eran lati se baagi ati beta ti a le fi se amuyangan ni awujo wa titi lo fi de oke-okun
IBEERE
- Ewo ninu awon wonyi ni ale fi se bata ____eran(a)Awo (b)Eti (c)Ese (d)Iwo
- Kin ni idi ti ise agbe se se Pataki lawujo gege bi alayoka se menu ba a?(a)Gbogbo eniyan lo nilo ise agbe (b) O n je ki agbe le lowo-lowo (c)O n je ki a rowo fe iyawo (d)O n pese ohun abalaye
- Awon agbe a maa sin ohunosin wonyi ayafi(a)Ologbo (b)Maluu (c)Adiye (d)Agutan
- Orisii agbe meloo ni alayoka menuba? (a)Okan (b)Meta (c)Meji (d)Merin
- Ewo ni a ko le fi owu hun ninu awon wonyi (a)Ankara (b)Apere (c) Leesi (d)Ofi
- “Omo yin looto” le je yo ninu aroko (a)Alalaye (b)Oni leta (c)Alariyanjiyan(d)Asotan
- Ninu leta aigbefe ni kan ni a maa n ko (a)Adiresi (b)Oruko (c)Akori (d)Afiwe
- “Ile-iwe mi” je ori oro fun aroko (a)Oniroyin (b)Oni leta (c)Alapejuwe(d)Alariyanjiyan
- Faweli aranmupe meloo ni o wa ninu ede Yoruba (a)Meje (b)Mefa (c)Marun (d)Merin
- Esin ti o wopo julo lawujo Yoruba lode-oni ni (a)Isegun gbigbe(b)Kirisiteeni (c)Buda (d)Oro
- Okan Pataki lara opo tie sin musulumi duro le lori ni (a)Ogun jija (b)Itore aanu sise (c)Iku ati ajinde Allah(d)Fifi iya je elesin miran
- Awon____ ni o ko esin Musulumi wo awujo Yoruba(a)Heberu (b)Hausa (c)Giriki (d)Larubawa
- Ere idaraya ojumomo ni (a)Okoto tita (b)Alo pipa (c)Ijakadi(d)Ekun meeran
- Akoko wo ni Yoruba maa n saaba se ere idaraya (a)Owuro kutu hai (b)Iyaleta (c)Osan gangan(d)Leyin ise
- Awon _____ ni o ni ege dida (a)Ijebu (b)Oyo (c)Osogbo (d)Egba
- Awon ilu wo lo ni oro ayingun? Awon (a)Oyo (b)Ife (c)Ospgbo (d)Egba
- Okan ninu awon wonyi ni a maa n lo oro fun (a)Wiwa Owo (b)Lile ajakale arun ni ilu (c)Lati je ki eto oro aje gbooro si (d)Fun eni ti o n wa omo
- Akoko wo ni ale da ega? (a)Osan (b)Owuro (c)Asale(d)Igbakuugba
- Okan lara ewi alojunaje-mesin n (a)Ekun iyawo (b)Bolojo (c)Alamo(d)Iyere
- Orisa_____ ni o ni arungbe (a)Sago(b)Oro (b)Egungun(d)Oya
- Orisa ti o ni iwi kikani(a) Sango (b)oro (c)Egugun(d)Obatala
- Gbolohun ti a fi n gbe oro okan kale lori koko kan ni gbolohun (a)Abode (b)Alakanpo (c)Alaye (d)Onisorogbesi
- Irufe gbolohun wo niyi “Gbigba ni won gba owo ayo ni owo mi ”Gbolohun ”(a)abode (b)Ase (c)ibeere
- “Pa ilekun de” je apeere gbolohun (a)Abode (b)Ase (c)Alayaye(d)Ibeere
- “Nje oga ti de ”gbolohun(a)Abode (b)Ase (c)Alayaye(d)Ibeere
- “Ki I se olu ni o mu owo ”je apeere gbolohun(a)Abode (b)Ayisodi (d)alauye(c)ibeere(d)Ase
- Olori awon oyomesi ni (a)Agbaakin(b)Basorun(c)Asipa (d)samu
- Oloye Melo ni iwarefa? (a)Marun (b)Mefa (c)Meje (d)Mejo
- Oyo ajewo ni oye (a)iyaloja (b)Iyalode (c)Bobagunwa(d)Ajiroba
APA KEJI
Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki
- Ko aroko ti ko din ni 300 eyo oro lori Okan ninu koko wonyi
- Ile iwe ijoba dara ju ile iwe aladani
- Omo kunrin wulo fun obi ju omobririn lo
- Ojo kan ti n ko le gbagbe
- Ko leta si olootu iwe iroyin kan ni agbagbe re salaye fun nipa awon ona ti o ti di koto orun ni adugbo re
- Toka si ojuseosugbo marun
2b. Menuba ohun marun ti a le ri oro se
- Meuba opo marun ti o wa iu esin Musulumi
3b. Daruko esin marun ti o wa ni awujo Yoruba lode oni
- Menuba ise olori ilu marun salaye awon wonyi
- Oba alakoro
- Oba alade
- Pelu apeere meji-meji, ki ni
- Gbolohun ase
- Gbolohun ibeere
- Gbolohun abode
- Gbolohun akanpo
- Gbolohun ayisodi