3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 5
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
AYEWO
- Iru leta wo ni a nko sile ile-ise ? (a) leta aigbefe (b) leta gbefe (d) leta onibeji
- Ewo ni o je mo ere idaraya ninu awon wonyii: (a) ijala (b) sango pipe (d) bojuboju
- Pari owe yii: Eni ti yoo je oyin inu apata: (a) kii woe nu aake (b) a fo apata ni (d) aake a ro ni
- Pari owe yii: ileti a fi ito mo: (a) Adara sini (b) ategun a gbe lo (d) iri ni yoo wo
- Kiini oruko, namba yii ni ede Yoruba 95 (a) Arundinlogoji (b) Arundinlogota (d) Arundin logorun
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba 60 (a) Ogoji (b) Ogota (d) Ogorun
- _________ je okan ninu ohun ti a fin se oge ni ile Yoruba? (a) Lofinda (b) Laali (d) Etekikun
- Awon ______ li ni aso osun kiko n ni ikawo (a) Yoruba (b) Hausa (d) Igbo
- Orisa wo ni a maa nyo ina lenu ________ (a) Ogun (b) Sango (d) Esu
- Awon wo ni Yoruba nki bayi pe: Oju gbooroo : (a) Alaro (b) Awako (d) Onidiri
ORO ISE NINU GBOLOHUN
Ewo ni apeere oro ise ninu awon gbolohun wonyii:
- Olu je eba ni ale: (a) Olu (b) eba (d) Je
- Isola pa eran ti o tobi : (a) Pa (b) Isola (d) Eran
- Yemi lo si ile-iwe: (a) Yemi (b) Si (d) Lo
- Wale mu emu ni oko: (a) Oko (b) Wale (d) Mu
- Agbe gbin Agbada: (a) Gbin (b) Agbado (d) Agbe
IWE KIKA: AGBEPO LAJA
- Bawo ni Tayo se jesi Abiola (a) egbon (b) ore (d) aburo
- Tani o ru apere (a) Abiola (b) Egbon (d) Tayo
- Kini baba Olosan pinnu lati se fun Tayo ati Abiola? (a) o pinnu lati na won
(b) o pinnu lati so fun baba won (d) O pinnu lati fun won ni osan
- Kini o je ki oro naa dun Abiola pupo
- won fi oju ole wo (b) owo ko te Tayo (d) o je iya ona meji
- Ona wo ni Abiola fi je onigbowo fun Tayo
(a) Oduro nidi igi osan (b) O gba osan kale (d) O ru agbon osan
IWE KIKA: ISEGUN OYINBO
- Omo melo ni Iya Alabi bi ye? (a) omo kan (b) omo meta (d) omo meji
- Kini mu ki Asabi ke tooto (a) Ebi npa omo re (b) Oko re kosi nile (d) Giri mu omo re
- Iru egboogi wo ni won gbe wa fun omo Iya Alabi
(a) Ebi npa omo re (b) Giri mu omo re (d) Oko re ko si nile
- Nigba wo ni Alabi ti pinnu lati ko nipa isegun oyinbo
(a) leyin iku aburo re (b) leyin ti o jade ile iwe mefa (d) leyin ti o pari mewa
- Nibo ni Alabi tin se ise isegun oyinbo (a) ni yunifasiti (b) ni abule won (d) ni ilu oyinbo