3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 2 YORUBA LANGUAGE

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 2

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

IKINI

  • Omokunrin ma ______ ki  babare ti obaji ni owuro (a) dobale  (b) kunle
  • Omobinrin maa ______ ki baba / iya re bi o ba ji ni owuro (a) kunle  (b) dobale
  • Bawo ni a se nki ni ni akoko ojo?  (a) eku eerun   (b) eku otutu
  • Bawo ni a se nkini ni akoko oorun?   (a) eku otutu    (b) eku oorun yiio
  • Awon musulumi to ngbawe ni a nki pe? (a) eku ongbe   (b) eku ise

Ise Agbe

  • __________loba (a) Alagbede     (b) Agbe 
  • Agbe lo ngbin isu, isu ti a fi ngun _________ (a) Iyan   (b) Amala
  • Agbe lo nbgin ogede, ogede ti a fin din ________ (a) mosa (b) dodo
  • Agbe lo ngbin paki, paki ti a fi nse _________ (a) ogi (b) gaari
  • Ise Agbe ko le _______  ni awujo(a) salo (b) kuta

Ise Alagbede 

  • Talo nro oko ati ada     (a) Alagbede (b) Agbe 
  • Nibo ni won ti nro    (a) oko     (b) agbede 
  • Kiini won fi nro    (a) irin pelebe  (b) paanu pelebe  
  • Kiini awon ohun elo ise alagbede     (a) ofa  (b) ewiri
  • Alagbede ni o nro oko ati ada fun _______     (a) Agbe   (b) Weda

 

Oruko Amutorunwa

  • Omo ti o mu ese was aye ni _______ (a) Ige  (b) Ojo
  • Omo ti a wa ninu apo ni _______ (a) Ojo  (b) Oke
  • Omo ti o gbe iwo korun ni _______ (a) Ajayi  (b) Ojo
  • Omo tio irun re ta koko ni _______ (a) Dada   (b) Ajayi
  • Omo ti o dojubole lati inu iya re wa si aye ni _______ (a) Ajayi   (b) Oke

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share