YORUBA LANGUAGE THIRD TERM PRIMARY 1 , 2 , 3, 4, 5 AND 6
EDU DELIGHT TUTORS
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:………………………………………………………………………………………
Imototo
- Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu
- Ge _________ re ni asiko ti o ye (a) imu (b) irun
- Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b) imu
- Gba _________ re pelu (a) ita (b) ayika
- Fo __________ re ki o mo toni toni (a) aso (b) inu
Alo Apamo:
- Alo o, alo o, ki lo bo somi, ti ko ro to, kini o (a) okinni (b) irin
- Alo o, alo o, kilo ba oba jeun, ti ko palemo (a) Abe (b) Esinsin
- Alo o, alo o, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) Agbara ojo (b) Esinesin
- Aloo, aloo, okun nho yaya, osa nho yaya, omoburuku tori bo (a) irin (b) omorogun
- Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro, kini o (a) Ata (b) Ewa
ITAN KOKO IYA ARUGBO
- __________ kan wa ni aye atijo (a) Baba (b) Egbon
- O bi omokunrin ________ (a) mewa (b) meje
- Okan ninu won losi ____________ iya arugbo ile won je (a) koko (b) ewa
- _____________ beere eni ti o ji koko ounje (a) Baba arugbo (b) Iya arugbo
- Awon omo naa si __________ lokoolan lori afara (a) Bura (b) Korin
ITAN IJAPA ATI YAN NIBO
- O pe ti _______________ ko ti ri omo bi (a) yannibo (b) ijapa
- O wa bere si i ______________ (a) ke (b) banuje
- Ijapa ba to ___________ lo (a) babalawo (b) esu
- Babalawo se ___________________ oogun fun-un (a) iresi (b) obe
- Ijapa oko yannibo ____________ (a) loyun (b) bimo
EDU DELIGHT TUTORS
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:………………………………………………………………………………
Imo Toto
- ____________ nge koriko ti o wa ni ayika ile won (a) Tunde (b) Kola
- ____________ naa ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola
- O nsa won si ori ____________ isasosi (a) Okun (b) Irin
- _______________ Tunde ko gbeyin rara (a) Egbon (b) Aburo
- Bi e ba sise tan, e maa gbagbe lati ______________ (a) we (b) sun
Ipin Keta: Ikini
- __________ ni omo kunrin nki baba tabi iyare (a) ido bale (b) ikunle
- __________ ni omo binrin nki baba ati iyare bi o ba ku (a) ikunle (b) idobale
- E ku otutu nla ki ni nigba _____________ (a) oye (b) ojo
- E ku ogbele yii, e ku ooro ni a nki ni nigba ___________ (a) eerun (b) ojo
- Ni dede agogo mejila si agogo meta abo, a maa nki ni ni ile Yoruba pe _____
(a) kaaroo (b) e kasano
Ise Agbe
- __________ ni Oba (a) Agbe (b) Ode
- Agbe lo ngbin _________ (a) okuta (b) isu
- Isu ti a fi ngun ________ (a) amala (b) iyan
- Agbe lo nbgin __________ (a) ogede (b) Igbin
- Agbe lo ngbin paki, paki ti a fi nse _________ (a) elubo (b) gaari
Alagbede
- Talo nro oko ati ada (a) Alagbede (b) Agbe
- Nibo ni won ti nro (a) oko (b) agbede
- Kilo fi nro won (a) paanu pelebe (b) irin pelebe
- Kiini awon ohun elo ise alagbede (a) ewiri (b) Agba
- __________ ni o nlo oko ati ada ti Alagbede nse (a) ode (b) Agba
EDU DELIGHT TUTORS
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………………
ASA IKINI
- Iya _____________ sese bimo ni (a) Sola (b) Yemi
- Iya ______________ fe lo ki i (a) Adunni (b) Alake
- O ba ti o gbe __________________ naa lowo (a) Ikoko (b) Oyun
- Bawo ni a se nki eni ti o nsile (a) ile a tura o (b) ile rewa o
- Bawo ni a se nki eni ti o bimo (a) Eku ise omo (b) E ku ewu omo
Owe Ile Yoruba
- Pari owe yii: Bami na omo mi ___________________________________________________
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
- Pari owe yii: Ile la nwo, ________________________________________________________
- Pari owe yii:: Esin iwaju, _______________________________________________________
- Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________
Ipolowo Oja
- Oja wo ni a npolowo bayii: langbe jinna o, oroku ori ebe (a) alagbado (b) orisu
- Oja wo ni a npolowo bayii: gbetuuru o, omi akerese, kii ndun lodo, to ba dele, adoyin
(a) eleran (b) eleja tutu
- Oja wo ni a npolowo bayii: ___eleelo, o gbona feli feli, (a) asaro (b) iyan
- ___________ re, obe re, ewojo ob eke mu _________ (a) isu (b) iyan
- Oja wo ni a npolowo bayii: gbanjo, gbanjo, ko lo nle, ko dowo o, oyinbo wo gbese
(a) aso (b) ounje
ETO AGBOOLA: EBI IKEKERE
- Ipo wo ni baba ko ninu ebi re ____________ (a) olori (b) alagbara
- Opo kanni _______________ je ninu ebi re (a) egbon (b) iya
- Awon _________________ ni opo keta ninu eto ebi (a) omo (b) ebi
- Ise Iya ni lati rii pe ____________ ati ______________ gbogbo ebi nbo si asiko
(a) lilo ati dide (b) jije ati mimu
- Ise baba kii se “keremi”, kini itumo “keremi” (a) kekere (b) nla
Yoruba BASIC 2 1st TERM EXAMINATION Primary 2
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
EDU DELIGHT TUTORS
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:…………………………………………………………………………………………………………………………………………………
IWE KIKA: BALOGUN IBIKUNLE
- Balogun Ibikunle je omo (a) Ibadan (b) Ogbomoso (d) Ijaye
- Ninu awon ogun ti Balogun Ibikunle ja ni ajabegun ni ogun: ______
(a) ijaye ati kutuje (b) Ibadan ati Ijaye (d) ogbomoso ati Ibadan
- A fi Ibikunle joye Balogun nitori pe o _______
(a) je omo ogbomoso, o si lowo (b) Jagun ajasegun pupo fun Ibadan (d) bimo, o si kole
- Balogun Ibikunle lokan tumo si pe o ________
(a) le farada isoro (b) ijegun pupo (d) ni okan ninu ara re
- Se alaiye meji ninu ebun ti ibikunle ni ti fi tayo awon elegbe re:
________________________________, _________________________________
IWE KIKA: EFUNROYE TINUBU
- Oloye Tinubu je ibatan ___________ (a) Akintoye (b) Kosoko (d) Geso
- Ohun ti o so Iyaafin Tinubu di olowo ni _________ (a) awon egba (b) owo sise (d) Dosunmu
- Awon Egba fi Iyaafin Tinubu je oye iyalode nitori _______
(a) awon eru re po (b) o lowo, olooto, o lola (d) o ran Egba lowo
- Iyato to wa laarin Tinubu ati Efunsetan ni pe, Tinubu __________
(a) ni opolopo eru (b) feran gbogbo eniyan (d) je akoni obinrin
- Owo re pelu awon oyinbo mo ki o _______ gidigidi (a) binu (b) lagbara (d) lajo
AKANLO EDE
- Kini itumo akanlo ede yii: Tu teru nipa:
(a) Ki eniyan ku (b) Ki eniyan salo (d) Ki eniyan bimo
- Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori
(a) Ki a fi aake si aarin ori (b) Ki eniyan ko jale lati se nnkan (d) Ki eniyan salo
- Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle: _____ (a) Edun ti o nrin nile
(b) Edun ti o gbooro gan-an (d) Eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago
- Kini itumo akanlo ede yii: E pa ko boro mo:
(a) e pa ko si ninu oro (b) ko si atunse mo (d) ko si epa mo
- Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe niko: (a) ki a soro pato si ibi ti oro wa
(b) ki a kan abe ni iko (d) Ki a maa kana be daadaa
AWON OWE ILE YORUBA
- Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, ___________________________________________________
- Pari owe yii: Kekere lati npeka iroko _____________________________________________
- Pari owe yii: Aja ti yoo sonu, ___________________________________________________
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja, _________________________________________________
- Pari owe yii:: Eni jin si koto, ____________________________________________________
EDU DELIGHT TUTORS
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………………
- Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, January _______________ (a) Seere (b) Erena
- Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, February _______________ (a) Igbe (b) Erele
- Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, March _________________ (a) Erena (b) Igbe
- Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, April ___________________(a) Ebibi (b) Igbe
- Kini oruko osu yii ni ede Yoruba, May ____________________(a) Belu (b) Ebibi
ORO ISE NINU GBOLOHUN
Fa ila si eyi ti o nse oro ise ninu awon gbolohun wonyii:
- Wale je eba ni ale
- Isola pa eran ti o tobi
- Yemi ra iru ati iyo ni oja
- Tunde mu emu ni oko baba Sule
- Yetunde sun si ori ibusun re
IWE KIKA: AGBEPO LAJA
- Bawo ni Tayo se jesi Abiola (a) egbon (b) ore (d) aburo
- Tani o ru apere (a) Abiola (b) Egbon (d) Tayo
- Kini baba Olosan pinnu lati se fun Tayo ati Abiola? (a) o pinnu lati na won
(b) o pinnu lati so fun baba won (d) O pinnu lati fun won ni osan
- Kini o je ki oro naa dun Abiola pupo
(a) o je iya ona meji (b) owo ko te Tayo (d) Baba gba osan re kale
- Ona wo ni Abiola fi je onigbowo fun Tayo
(a) Oduro nidi igi osan (b) O ru agbon osan (d) O gba osan kale
IWE KIKA: ISEGUN OYINBO
- Omo melo ni Iya Alabi bi ye? (a) omo meta (b) omo kan (d) omo meji
- Kini mu ki Asabi ke tooto (a) Ebi npa omo re (b) Oko re kosi nile (d) Giri mu omo re
- Iru egboogi wo ni won gbe wa fun omo Iya Alabi
(a) Egboogi Ibile (b) Egboogi oyinbo (d) Egboogi to pe nile
- Nigba wo ni Alabi ti pinnu lati ko nipa isegun oyinbo
(a) leyin ti o jade ile iwe (b) leyin iku aburo re (d) leyin ti o pari eko re ni yunifasiti
- Nibo ni Alabi tin se ise isegun oyinbo (a) ni abule (b) ni ilu oyinbo (d) ni yunifasiti
[mediator_tech]
(NURSERY & PRIMARY)
15, TAPA STREET, OFF FREEMAN, LAGOS.
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 2021
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ORUKO OYE OBA ALAYE
- Kiini oruko oye Oba Oyo (a) Alaafin (b) Oloyo (d) Lamidi
- Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Onife (b) Ooni (d) Enitan
- Kiini oruko oye Oba Ilu Egba (a) Olowo (b) Elegba (d) Alake
- Kiini oruko oye Oba Ilu Ijebu Ode (a) Awujale (b) Onijebu (d) Sikiru
- Kiini oruko oye Oba Ilu Osogbo (a) Soun (b) Ata Oja (d) Okere
Akanlo Ede
- Kiini itumo akanlo ede yii: Fa omo yo
(a) Ki eniyan mu omo jade (b) Ki a se ase yori (d) Ki a ni omo pupo
- Kiini itumo akanlo ede yii: Eja nba kan
(a) Iroyin buburu tabi, iroyin rere (b) Eja ati akan ni nejeeji (d) Eja kan, Akan kan
- Kiini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo
(a) Epa ko si ninu oro (b) Ko si atunse mo (d) Epa ko le ba oro
- Kiini itumo akanlo ede yii: Edun arinle (a) Edun ti o nrin ni ile
(b) Edun ti o po ganan (d) Eni ti o ti lowo ri sugbon ti o pada raago
- Kiini itumo akanlo ede yii: je oju ni gbese
(a) Dara lati wo (b) san gbese fun oju (d) Oju gbese to dara
IWE KIKA: AJALA TA N NA O
- Kiini awon ara abule sefun Ajala (a) won buu (b) won kii (d) won na an
- Ajala maa nse ___________ kiri abule (a) agidi (b) ijangbon (d) omoluabi
- Omo ________________ ni Ajala (a) lile (b) oponu (d) ole
- Tan ni suur tumo si __________________
(a) mu suuru patapata (b) iluwa to le mu ni binu gan-an (d) gba suuru tan
- Itumo fa ijangbon ni __________ (a) da wahala sile (b) mu ijangbon dani (d) ni ijangbon lawo
IGBAGBO ATI ERO YORUBA NIPA OLODUMARE
- Tan Olodumare?
- So meji nipa Igbagbo awa Yoruba nipa Olodumare