Exams Questions Grade 5 Yoruba Third Term
SUBJECT: YORUBA
TIME: 1 HOUR
CLASS: GRADE FIVE
NAME OF PUPIL____________________________________
DATE __________
- 20 je _________ (a) ogun (b) igba (d) Eedegbeta
- 500 je _________ (a) Egbeta (b) Eedegbeta (d) Egberun
- Egberun je _________ (a)500 (b) 200 (d) 1000
- Igba je _________ (a) 100 (b)200 (d) 20
- Adie funfun ni ede oyinbo ni (a)white duck (b) black chicken (d) white chicken
Pari owe yii
- Adie funfun__________ (a) ologbon ni (b) ko mo ara re lagba (d) omode lo n se
- Ile oba to jo __________ (a) ewa lo bu si (b) ibaje poo (d) ibaje lo bu kun
- Bami na omo mi, ko de inu _________ (a) baba (b)iya (d) olomo
- Bi esin ba da ni _______ a ma n tun gun ni (a)subu (b) gule (d) gunni
- Ewa ni ede oyinbo je ______ (a) beautiful (b) beans (c) beauty
APA KEJI
- Ko owe marun ti o mo
- Ko awon wonyi ni ede Yoruba
-
- White
- Black
- Beauty
- Head
- Cloth