SILEBU NINU EDE YORUBA

Pry five

Akole:SILEBU

 

KINI A NPE NI SILEBU

Silebu ni fonran oro ri emile gbejade lekan soso tabi silebu ni ige oro si wewe tabi silebu ni ihun ti a fi nse afaoe iro ni a mo si silebu.

Ami oh un no a fi in oro si silebi,iyeami ti o ba wa lori oro kankan ni a fi mss mo iye silebu ti o ja.

Orisi ami ohun meta ni o wa ninu ede yoruba ami ohun oke ,ami ohun aarin ,ami ohun oke ti a mo si “do” ,ami ohun aarin ti a mo si “re” ,ami ohun isale ti a mo si “mi”.

 

Bi apeere

 

I|BA|DAN —–Silebu meta

O|SO|GBO——Silebu

meta.

O|GBO|MO|SO—-Silebu

merin.

A|JE|GUN|LE—–Silebu

merin.

A|GUN|LE|JI|KA—-Silebu

marun.

A|JI|GBO|TI|NU—Silebu

marun.

 

 

Ise kilaasi

 

Silebu melo lowa ninun awon oro wonyii.

1.igbagbo

2.Ajegunle

3.Agbabiaka

4.Ogbomoso

5.Eniyan

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share