YORUBA SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 2
IDANWO TAAMU KEJI
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyii.
- Tani a n pe ni alapamasise (a) olopa (b) ole
- Kin ni ole pati ninu arofo iwa ole ko dara?
(a) ile-eko (b) soosi
- Kin ni atunbotan oro yi? W + a = (a) wa (b) ga
- Kin ni A + de = (a) Ede (b) Ade
- Kin ni a n pe apapo faweeli ati konsonanti? (a) alifabeeti (b) silebu
- Apapo _____ ni a fi n seda oro (a) gbolohun ati gbolohun (b) konsonanti ati faweeli
- Ona kan Pataki ti a fin mo afinju ni (a) aso idoti (b) aso mimo
- Aisan onigbameji ni a mo si (a) kolera (b) eyin riro
- Ona ti a le fi se itoju ara wa ni (a) wiwe ni osoose (b) wiwe ni ojoojumo
- Kin ni a n pe aisan iba (a) malaria (b) cough
- Ta ni Iya Toriola (a) Adepate (b) Bukola
- Kin ni oruko baba toriola (a) Jemisi
(b) abinuwawaje
- Kilaasi wo ni Toriola wa? (a) kilaasi keji
(b) kilaasi keta
- Ise wo ni baba Toriola n se (a) Awako (b) agbe
- Ijanba wo ni o sele si Toriola? (a) oju re fo
(b) eti re di
IPIN KEJI[mediator_tech]
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.
a. Ko atunbotan awon oro onisebu wonyi
- e + ye = __________________
- o + mi = __________________
- e + wa = ___________________
- i + gi = _______________________
- o + wo = ____________________
B. Kale mo marun -un ninu ohun ti a fi n tun wa se.
Igbale, odo, aga, ada, reeki, omi, tabili, telifisani, ikole
D. Ko leta faweeli marun –un jade
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _________________________________
iv. ________________________________
v. ___________________________________