Yoruba CLASS: Olodun Kerin.

SCOND TERM EXAMINATION. 2016/ 2017

SUBJECT: Yoruba CLASS: Olodun Kerin.

DATE: ________________________________. TIME: 1 HOUR.

NAME: ___________________________________________

  1. Ojo ____ lo wa ninu ose kan . a. meji b. meta d. merin e. meje
  2. Osu ____ lo wa ninu odun kan a. mefa b. merinla d. meje e. mejila
  3. Konsonanti inu oro yii “baba “ ni ___ a.ba b.baba d.b,b e. a,a
  4. Konsonanti inu oro yin “ogede “ ni ____ a.ogede b.o d.oee e.gd
  5. Faweeli inu oro yii “iyawo” ni _____a.i,a,o, iyawo d.iywo e. awo
  6. Ojo aiku ni ede geesi ni _____ a.Monday b.Sunday d.Tuesday e.Friday
  7. Ojo aje ni ede geesi ni ______ a.Sunday b.Saturday d.Monday e.Wednesday
  8. Ojo isegun ni ede geesi ni ____ a.Tuesday b.Wednesday d.Thursday e.Friday
  9. Ojoru ni ede geesi ni _______ a.Wednesday b.Thursday d.Saturday e.Sunday
  10. Ojobo ni ede geesi ni ________ a.Monday b.Friday d.Thursday e.Tuesday[mediator_tech][mediator_tech]

IPIN B

Ko awon osu wonyi sile ni ede Yoruba

EDE GEESI EDE YORUBA
January
February
March
April
May
June
July
August
September
October

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share