Second Term Examination Yoruba Upper Primary 4, 5 and 6
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE OKOTO:
- Eniyan _____ ni o nta okoto nleekan naa (a) meji (b) mefa
- Ori _______________ didan ni a ti nta okoto (a) eni (b) ile
- ______________ ni a fi nse okoto (a) paanu (b) igi
- Ti a bat a okoto sile, o maa ___________ rainrain (a) jo (b) sun
- A maa ______________ okoto ni (a) sun (b) de
ERE AYO
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin
- ______ ni omo Ayo (a) Eso igi (b) oronbo
- Apa ___________ ni a maa nta ayo si (a) osi (b) otun
- Omo ayo ________ ni o ngbe oju opon ayo lapapo (a) mejidin ladota (b) mejile logun
- Eniyan ______ ni o nta ayo olopon (a) merin (b) meji
ORIN IREMOLEKUN
- Talo bami _______ wi o? (a) lomo (b) legbon
- ______ e lo ba a wi o? (a) egbon (b) iya
- Bi o ku o, maa ra ___________ fun o (a) igi (b) aso
- _________ orun ni iyemo lorun (a) egba (b) okun
- ________ mo ra la pono ka o (a) oko (b) eru
APA KERIN
- _________ je eran ile (a) ewure (b) erin
- A maa je ______ pupo (a) eni (b) iya
- Nitori _____________ re (a) aigboran (b) ika
- Bi won ba na ewure tan, a gbon _________ re mejeeji pepe (a) imu (b) eti
- Eyin ____________, e gbo, e maa se bi ewure (a) omode
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE AYO
- ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) awo ayo
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin
- Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi
- Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin (b) meji
- Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun
ALO APAMO
- Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o
(a) irin (b) omorogun
- Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo (b) agbara
- Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o (a) ata (b) ewa
- Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o
(a) ilu (b) igba
- Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin, kini o (a) agbara (b) odo
ALO APAGBE: IJAPA ATI OKERE
- _________ ati okere je ore (a) asin (b) ijapa
- _______ kii se ore won (a) ijapa (b) asin
- Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru
- Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere
- Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese
IMOTOTO ILE
- _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde (b) Kola
- _________ ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola
- Mama ________ sese fo aso tan ni (a) Bola (b) Kemi
- Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina (a) Kola (b) Tunde
- O n sa wonsi ori ________.
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
OTITO BORI
- Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto (b) Ayedande
- Kii ni ise Mosun (a) agbejoro (b) onisowo
- Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan (b) Omodekunrin kan
- Bawo ni won se ko ba Mosun? (a) won ba Mosun ja (b) won fi oja fayawo ranse si iso re
- Bawo ni Mosun se bo ninu isoro re? (a) awon olopaa fi sile (b) omode kunrin kan lo tu asiri
ALO APAMO
- Alo o, alo o, opo baba alo kan laelae, opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa ni iku de ba a o, kini o (a) abela omorogun
- Alo o, alo o, ikoko rugudu feyin tigbo, kini o (a) ijapa (b) igbin
- Alo o, alo o, kini koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) agbara (b) sigidi
- Alo o, alo o, awe obi kana je doyo, kini o (a) enu (b) ahon
- Alo o, alo o, yara kotopo, kiki egun, ki ni o (a) enu (b) ibepe
ALO APAGBE: IJAPA ATI ERIN
- Kini awon oba fi maa nbo ori won laye atijo (a) eranko nla (b) eranko wewe
- Bawo ni ijapa se je si erin (a) ota (b) ore
- Ona wo ni ijapa gba mu erin wo ilu (a) o fun ni akara (b) o fun ni robo aladun
- Ileri wo ni kabiyesi se fun ijapa (a) o da ohun ini resi meji (b) o je ijapa ni iya
- Eko wo ni itan yii ko wa?
(a) okowa ki a maa sora ni ile aye (b) o kowa ki a maa sora fun awon odale ore
SISE KANGO
- Iya __________ fe din kango (a) Ayoka (b) Adunni
- ________ ya agbado wa lati oko (a) Egbon (b) Baba
- Iya Adunni re agbado naa sinu ______ nla kan (a) ikoko (b) agba
- O bu epo pupa sinu _______ (a) ina (b) agbada
- Nigba ti __________ gbona daadaa (a) epo (b) o
SECOND TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ORIKI ILU
- Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun
(a) Ibadan (b) Akura (d) Oyo
- Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba (b) Eko (d) Akure
- Ilu wo ni a nki bayi pe: oloyemekun, omo a muda sile mogun enu pani
(a) Akure (b) Ilorin (d) Ondo
- Ilu wo ni a nki bayi pe; omo ajifi kalamu damo leko arise kandun kandun, ilu to jinna to sunmo alujona (a) Egba (b) Oyo (d) Ilorin
- Ilu wo ni a nki bayii pe, omo lisabi, oniruuru – po nile Alake (a) Ogbomoso (b) Egba (d) Ijesa
ONKA NI EDE YORUBA
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 75
(a) arundinlogbon (b) arundinlogoji (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 45
(a) arundinladota (b) arundinlogun (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) ogorun (b) adorun (d) ogota
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) ogorin (b) ogorun (d) adofa
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 65
(a) arundinladorin (b) arundinlogoji (d) arundinnigba
ASO ILE YORUBA
- Ewo ni aso ile wa ninu awon oruko wonyii (a) alari (b) akara (d) seti
- Ara ti obinrin fi aso ran ni _____ ati _____
(a) gele ati ipele (b) iro ati buba (d) oyala ati dansiki
- Ara to okunrin nfi aso ran ni ______ ati _____
(a) buba ati sokoto (b) iro ati gele (d) tobi ati oyala
- Aso ati a nran ti o ngun de orun ese ni ______ o dabi jalamia ti won ba ran tan
(a) agbada (b) dandogo (d) gbariye
- Aso ti o jo agbada, sugbon ko tobi to agbada ti a ba ran tan ni a npe ni _____
(a) dansiki (b) gbariye (d) oya
AGBON TA GBONJU
- Kini o ta gbonju? (a) ikamudu (b) oyin (d) agbon (e) kan-in-kan-in
- Ninu eko yii, baba gbonju ko fe ki awon omo oun ya______
(a) ole (b) ole (d) olojukokoro (e) alaigboran
- Itumo se imele ni ______ (a) roju (b) gun ope (d) ja ole (e) ya ole
- __________ ni baba gbonju (a) olowo (b) akikanju (d) ole (e) okuroro
- Kini koje ki baba gbonju lo si oko (a) idiwo kekere (b) ise nla (d.
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
- Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije
- Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won
IWE KIKA DAROSA
- Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko (b) egbe ti o nko (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni
- Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo
(a) o nya won lowo (b) o nran won nile eko (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe
- Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo? (a) o nraso ile-eko fun won
(b) o nfun won ni eko-ofe (d) o nra aso odun funwon (e) o nfun won ni ebun owo
- Nibo ni darosa ti nri owo tire?
(a) nibi ole jija (b) nibi jibiti lilu (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re
- Darosa nfe ki omode ______
(a) feran obi (b) maa sa ni ile-eko (d) fi oju si eko re (e) di fole fole
OWE ILE YORUBA
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja __________________________________________________
- Bami na omo mi, _____________________________________________________________
- Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________
- Esin iwaju, __________________________________________________________________
- Obe ti baale ile kii nje, _____________________________________________________[mediator_tech]
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON
- Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin
- Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo
- Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e) Alangba
- Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye (b) o fin pa adan
(d) koje ki o koju si eko re (e) o fi fo agbe emu
- Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye (b) ile-eku (d) adan (e) agbe-emu
IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE
- Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba (b) olowo (d) talaka (e) ode
- Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo ose (b) ojo odun (d) ojo oja (e) ojo ere
- Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa
(a) o lo wa igi (b) o lo he ekuro (d) o lo sa obi (e) o lo wa isu
- Kini o mu inu bi Lamurin
(a) ko gbadun iwe naa (b) o ri ewu re lorun elomiran (d) omi odo ko kaa lara (e) orun wo o
- Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada (b) kumo (d) opa (e) owo
IWE KIKA: – WARA
- Awon wo lo nse wara (a) maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo
- Ni akoko wo ni won maa nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo
- Ara eranko wo ni won ti nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu
- Iru ewe wo ni won fin se wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu
- Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b) eko (d) oka (e) eba
IKINI LENU ISE ATI IDAHUN
S/N | Onise | Ikini | Idahun |
1.) | Alagbede | ||
2.) | Akope | ||
3.) | Babalawo | ||
4.) | Alaro | ||
5.) | Onidiri | ||
6.) | Awako | ||
7.) | Onisowo | ||
8.) | Alayo | ||
9.) | Ode | ||
10.) | Amokoko |
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE OKOTO:
- Eniyan _____ ni o nta okoto nleekan naa (a) meji (b) mefa
- Ori _______________ didan ni a ti nta okoto (a) eni (b) ile
- ______________ ni a fi nse okoto (a) paanu (b) igi
- Ti a bat a okoto sile, o maa ___________ rainrain (a) jo (b) sun
- A maa ______________ okoto ni (a) sun (b) de
ERE AYO
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin
- ______ ni omo Ayo (a) Eso igi (b) oronbo
- Apa ___________ ni a maa nta ayo si (a) osi (b) otun
- Omo ayo ________ ni o ngbe oju opon ayo lapapo (a) mejidin ladota (b) mejile logun
- Eniyan ______ ni o nta ayo olopon (a) merin (b) meji
ORIN IREMOLEKUN
- Talo bami _______ wi o? (a) lomo (b) legbon
- ______ e lo ba a wi o? (a) egbon (b) iya
- Bi o ku o, maa ra ___________ fun o (a) igi (b) aso
- _________ orun ni iyemo lorun (a) egba (b) okun
- ________ mo ra la pono ka o (a) oko (b) eru
APA KERIN
- _________ je eran ile (a) ewure (b) erin
- A maa je ______ pupo (a) eni (b) iya
- Nitori _____________ re (a) aigboran (b) ika
- Bi won ba na ewure tan, a gbon _________ re mejeeji pepe (a) imu (b) eti
- Eyin ____________,
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE AYO
- ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) awo ayo
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin
- Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi
- Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin (b) meji
- Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun
ALO APAMO
- Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o
(a) irin (b) omorogun
- Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo (b) agbara
- Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o (a) ata (b) ewa
- Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o
(a) ilu (b) igba
- Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin, kini o (a) agbara (b) odo
ALO APAGBE: IJAPA ATI OKERE
- _________ ati okere je ore (a) asin (b) ijapa
- _______ kii se ore won (a) ijapa (b) asin
- Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru
- Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere
- Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese
IMOTOTO ILE
- _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde (b) Kola
- _________ ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola
- Mama ________ sese fo aso tan ni (a) Bola (b) Kemi
- Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina (a) Kola (b) Tunde
- O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
OTITO BORI
- Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto (b) Ayedande
- Kii ni ise Mosun (a) agbejoro (b) onisowo
- Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan (b) Omodekunrin kan
- Bawo ni won se ko ba Mosun? (a) won ba Mosun ja (b) won fi oja fayawo ranse si iso re
- Bawo ni Mosun se bo ninu isoro re? (a) awon olopaa fi sile (b) omode kunrin kan lo tu asiri
ALO APAMO
- Alo o, alo o, opo baba alo kan laelae, opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa ni iku de ba a o, kini o (a) abela (b) omorogun
- Alo o, alo o, ikoko rugudu feyin tigbo, kini o (a) ijapa (b) igbin
- Alo o, alo o, kini koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) agbara (b) sigidi
- Alo o, alo o, awe obi kana je doyo, kini o (a) enu (b) ahon
- Alo o, alo o, yara kotopo, kiki egun, ki ni o (a) enu (b) ibepe
ALO APAGBE: IJAPA ATI ERIN
- Kini awon oba fi maa nbo ori won laye atijo (a) eranko nla (b) eranko wewe
- Bawo ni ijapa se je si erin (a) ota (b) ore
- Ona wo ni ijapa gba mu erin wo ilu (a) o fun ni akara (b) o fun ni robo aladun
- Ileri wo ni kabiyesi se fun ijapa (a) o da ohun ini resi meji (b) o je ijapa ni iya
- Eko wo ni itan yii ko wa?
(a) okowa ki a maa sora ni ile aye (b) o kowa ki a maa sora fun awon odale ore
SISE KANGO
- Iya __________ fe din kango (a) Ayoka (b) Adunni
- ________ ya agbado wa lati oko (a) Egbon (b) Baba
- Iya Adunni re agbado naa sinu ______ nla kan (a) ikoko (b) agba
- O bu epo pupa sinu _______ (a) ina (b) agbada
- Nigba ti __________
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ORIKI ILU
- Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun
(a) Ibadan (b) Akura (d) Oyo
- Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba (b) Eko (d) Akure
- Ilu wo ni a nki bayi pe: oloyemekun, omo a muda sile mogun enu pani
(a) Akure (b) Ilorin (d) Ondo
- Ilu wo ni a nki bayi pe; omo ajifi kalamu damo leko arise kandun kandun, ilu to jinna to sunmo alujona (a) Egba (b) Oyo (d) Ilorin
- Ilu wo ni a nki bayii pe, omo lisabi, oniruuru – po nile Alake (a) Ogbomoso (b) Egba (d) Ijesa
ONKA NI EDE YORUBA
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 75
(a) arundinlogbon (b) arundinlogoji (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 45
(a) arundinladota (b) arundinlogun (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) ogorun (b) adorun (d) ogota
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) ogorin (b) ogorun (d) adofa
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 65
(a) arundinladorin (b) arundinlogoji (d) arundinnigba
ASO ILE YORUBA
- Ewo ni aso ile wa ninu awon oruko wonyii (a) alari (b) akara (d) seti
- Ara ti obinrin fi aso ran ni _____ ati _____
(a) gele ati ipele (b) iro ati buba (d) oyala ati dansiki
- Ara to okunrin nfi aso ran ni ______ ati _____
(a) buba ati sokoto (b) iro ati gele (d) tobi ati oyala
- Aso ati a nran ti o ngun de orun ese ni ______ o dabi jalamia ti won ba ran tan
(a) agbada (b) dandogo (d) gbariye
- Aso ti o jo agbada, sugbon ko tobi to agbada ti a ba ran tan ni a npe ni _____
(a) dansiki (b) gbariye (d) oya
AGBON TA GBONJU
- Kini o ta gbonju? (a) ikamudu (b) oyin (d) agbon (e) kan-in-kan-in
- Ninu eko yii, baba gbonju ko fe ki awon omo oun ya______
(a) ole (b) ole (d) olojukokoro (e) alaigboran
- Itumo se imele ni ______ (a) roju (b) gun ope (d) ja ole (e) ya ole
- __________ ni baba gbonju (a) olowo (b) akikanju (d) ole (e) okuroro
- Kini koje ki baba gbonju lo si oko (a) idiwo kekere (b) ise nla (d) oro aje (e)
SECOND TERM EXAMINATION 0000
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
- Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije
- Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won
IWE KIKA DAROSA
- Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko (b) egbe ti o nko (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni
- Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo
(a) o nya won lowo (b) o nran won nile eko (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe
- Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo? (a) o nraso ile-eko fun won
(b) o nfun won ni eko-ofe (d) o nra aso odun funwon (e) o nfun won ni ebun owo
- Nibo ni darosa ti nri owo tire?
(a) nibi ole jija (b) nibi jibiti lilu (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re
- Darosa nfe ki omode ______
(a) feran obi (b) maa sa ni ile-eko (d) fi oju si eko re (e) di fole fole
OWE ILE YORUBA
- Pari owe yii: Agba kii nwa loja __________________________________________________
- Bami na omo mi, _____________________________________________________________
- Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________
- Esin iwaju, __________________________________________________________________
- Obe ti baale ile kii nje, _________________________________________________________
[mediator_tech]2