Ikoto Ede Yoruba
Ipin Kiini: Ere Idaraya
1.) _____ ni a fin se okoto. (a) paanu (b) igi
2.) Eniyan ________ o ma anta okoto (a) merin (b) meji
3.) _______ ni omo ayo (a) eso igi (b) daisi
4.) Eniyan _____ ni o ma anta ayo (a) meta (b) meji
5.) Apa _____ ni a ma anta ayo si (a) otun (b) eyin
Ipin Keji: Imototo
1.) We ____________ re ki o mo tonitoni (a) Ara (b) Aso
2.) Ge ______________ owo re pelu (a) irun (b) eekanna
3.) Fo ___________ re ki o mo tonitoni (a) Aso (b) Igi
4.) Gba ________ ile re bi o ba ji ni owuro (a) ayika (b) oke
5.) ____________ lo le segun arun gbogbo (a) obun (b) imototo
Ipin Keta: Alo Apamo
1.) Aloo, aloo, ki lo bo somi, ti ko ro to (a) okinni (b) okuta
2.) Aloo, aloo, Awe obi kan, a je do yo, kini o (a) oju (b) ahon
3.) Aloo, aloo, ki lo ba oba muti kini o (a) Esinsin (b) Agbara
4.) Aloo, aloo, opa tinrin kanle, o kanrun , kini o (a) irin (b) ojo
5.) Aloo, aloo, mo nlo soyo, mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o
(a) ilu (b) igba
Ipin Kerin: Itan Koko Iya Arugbo
1.) Baba kan wa laye atijo o bi omo ________ (a) meje (b) mewa
2.) Won maa nba baba won lo si ______ (a) odo (b) oko
3.) Okan ninu won lo ji _____ iya arugbo ile won je (a) amala (b) koko
4.) Awon omo yii bere sii bura lokankan lori _______ (a) afara (b) ile
5.) Itan yii ko w ape ______ ko dara (a) agbere (b) ole