MID TERM TEST FIRST TERM YORUBA SS 1

 

FIRST TERM MID TERM TEST 

                  Subject: YORUBA      Class: S.S 1 Time:

Apa kinni

Dahun gbogbo ibeere 

Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee

Ni   aye atijo,eko ilese Pataki ju lo laarin  awon omo Yoruba sugbon laye ode –oni, eko ile-iwe ni awon eniyan gbojule nitori ona atije atimu  nikan. Won ko mo  wi pe eko kookan lo ni  aye tire. Bi omo ba ni eko-iwe ti ko ni eko ile, alailekoo I won maa npe iru omo bee, nitori omo ti o ba ni eko-ile ni Yoruba maa n  pe omoluab. 

Lara eko  ile ni iwa ikini,imototo,ibowo fagba,itiju,itoju ouje,abbl. Opolopo omo ode-oni ni o ni eko  ile-iwe. Sugbon   ti ko ni eko ile nitori pe awon obi won paapaa ko ka eko ile kun Pataki. Omo  won ko mo ina da, ko ni ibowo fagba, sibe inu awon obi won si dun sii. Won  ti gbagbe pe eko ile-iwe lai si eko ile  dabii tii ti ko ni suga, omo birin ti ko ni eko ile ni yoo so iru eni ti awon obi re je  ni ile-oko

Dahun ibeere

  1. Kin ni o n mu ki inu awon obi dun  si eko  ile-iwe (a)gbayi pupo (b)o le mu  eniyan bimo pupo (c) le e pese atije atim atimu (d)maa n fa aisan si eniyan lara
  2. Eyi maa n fa iwa olaju ailekoo laarin awon  Yoruba tumo si omo fi ko (a)Feran oluko re (b)Jara mose (c)Mo nipa ise owo (d) ni eko  ile
  3. Ewo ni  ko si lara eko ile lara awon woyi(a)Ibowo fagba (b)Ikini (c)Imototo(d)iwe kika
  4. Eko wo lo se Pataki laarin awon Yoruba ni ode-oni gege bi o ti wa ninu ayoka yii? (a)Ile (b)Imototo (c)Iwe (d)Isoro
  5. Ewo ni o tona gege bi o ti wa ninu akaye yii? Eko (a)Ile ko gbayi (b)Ile nikan ni o dara (c)iwe ati tile ko dara (d)iwe ati tile ni  o dara
  6. Ewo ni ole je ori-oro fun  aroko  asapejuwe ninu awon wonyi  (a)asa ibile dara ju asa oyinbo lo(b)  Ti mo ba je oga ile eko(c)Faari aseju (d)Ile awon Bukunmi
  7. Ewo ni igbese  ti o gaaju ninu leta kiko? (a)Ori-oro  (b)Deeti (c)Adiresi(d)Ikini
  8. /W/je konsonanti (a)Afeji-ete-pe (b)Aferigipe(c)Afafasefetepe (d)Afajape
  9. Kin ni batani silebu ti o pari ipekun? (a)N (b)KF (c)KFN (d)F
  10. /Q/ ninu ogbon je Mofiimu (a)Afomo (b)Adaduro (c)Ipile (d)Afarahe
  11. Silebu meloo ni o wa ninu “BELETASE” (a)Mesan (b)Mejo (c)Mefa (d)Marun
  12. /e/ je faweeli (a)Ayanupe (b)Ayanudiepe(c)Ahaupe(d)Ahanudiepe
  13. Konsonanti akunyun ni (a)/P/(b)/j/(c)/s/(d)/f/
  14. Eyin  oke ati ete isale ni a fi pe iro (a)/d/(b)/f/(c)/g/(d)/h/
  15. “F-KF-KF-KF-KF” je batani silebu fun (a)Alaafia (b)Agabagebe (c)Agandangodo (d)Arugbo
  16. /r/je konsonanti (a)Arehon (b)Afegbeenupe (c)Aseesetan (d)Asenupe
  17. Ki ni itupale si mofiimu “OMOKOMO”(a)OMO+KO+MO (b)OMO+KOMO (c)OMOKO+MO (d)OMO+KI+OMO
  18. Apetunpe waye ninu (a)Wase (b)Lilo (c)Eewo (d)Darandaran
  19. Okan lara ise isenbaye iran Yoruba ni (a)Tisa (b)Loya (c)Igba finfin (d)Dokita
  20. Iran Yoruba wo lo ni epo fifo? Iran (a)Aresa (b)Irese (c)Onikoyi (d)Olugbon
  21. Okan ninu ise wonyi nilo oogun (a)Agbe (b)Onidiri (c)Aro dida (d)Ode
  22. Awon wo ni won n pa oko ni ile Yoruba? Awon (a)ode  (b)agbede (c)Agbe (d)Onigbajamo
  23. Igbese akoko ninu asa igbeyawo ni  (a)Iwadii (b)Ifojusode (c)Itoro (d)ijohen
  24. Gbigba  ti omobinrin gba lati fe omokunrin ni a n pe ni (a)Iwadii (b)Ifojusode (c)Ijohen (d)Ibale
  25. Igbeyawo ti omokunrin ati obirin da ara won yan lore ni a n pe ni (a)Asante (b)Ibale (c)Momi-n-mo-e (d)Abasile

 

ITAN  AROSO 

DEBO AWO,MOREMI AJANSORO

  1. Olu eda itan iwe yii ni  _______  (a)fogido (b)Diwura (c)Moremi (d)Orunto
  2. ______ ni won ba ninu agbara eje ara re? (a)Moremi  (b)Olurobi (c)Olu orogbo (d)Fogido
  3. Kini Elujoba fe fi ewe ti o f era se? o fe (a)Fi pon eko (b)Fib o ile re (c)Fi pon olele (d)ta a
  4. Iya – baba Moremi ni (a)Diwura (b)Fogido (c)Samosegi (d)Iyun
  5. _____ ni o toju Moremi dagba (a) Samosegi (b) Diwura(c)Orunto (d)Arole Atewon ro

APA KEJI

Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki 

  1. Ko aroko ti ko din ni 300 eyo oro olori okan lara koko wonyi 
  1. Oremi ti mo feran julo 
  2. Ere   alarinrin  kan ti mo wo
  3. Iya wulo fun omo ju baba lo 
  4. Ko   leta si   ore re ni ilu miran salaye akitiyan ijoba lori awon ona ti o wo ilu re
  1. Salaye  lori awon wonyi 
  1. Ipo ete 
  2. Giga   apakan  ahon
  1.    Toka si   ona merin  ti ale gba seda oro oruko titun ki  o si fi apere meji  -meji gbe idahun re lese
  2. Ki ni itumo awon oro wonyi? 
  1. Abasile 
  2. Asante
  3. Apon
  4. Alarina
  5. Ifojusode
  1.   Daruko ise abinibi marun, ko si ko ohun elo meta-meta fun okookan won

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share
Use the search box to search for any topics or subjects that you want
Use the search box to search for any topics or subjects that you want