MID TERM TEST FIRST TERM YORUBA LANGUAGE ALL CLASSES SECONDARY JSS AND SS CLASS
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- Di awon alafo wonyii pelu awon leta ti o ye:
A _______ D _____ E _____ G _____ I ______ J _____ L ____ N _____ O _____ R _____ S
- Kiini oruko nomba wonyii ni ede Yoruba :
- 3 – (a) Eeta (b) Arun-un
- 1 – (a) Eerin (b) Ookan
- 5 – (a) Arun-un (b) Eeji
- 2 – (a) Eeji (b) eefa
- 4 – (a) Eejo (b)Eerin
- Kiini oruko awon aworan wonyii:
- = (a) Ile (b) Ogba
- = (a) Owo, (b) Ese
- = (a) Oju (b) Eti
Ss
- = (a)Ododo (b) Ewe
- = (a) Igo (b) Agba
- Di awon oro wonyii pely leta ti o ye:
- IL___ (a) E (b) K
- OW___ (a) P (b) O
- OJ____ (a) K (b) U
- EW____ (a) E (b) T
- IG___ (a) M (b) O
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- ORIN AKOMONIWA: OMO RERE
- Omo rere kii ___________ (a) puro (b) soro
- Omo rere kii ___________ (a) korin (b) jale
- Omo rere kii ___________ (a) seke (b) kawe
- Omo rere kii ___________ (a) kole (b) ja
- Omo rere kii ___________ (a) sole (b) sun
- IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
- _______________ nse baba Aina (a) Aisan (b) Aarun
- _________________ wa kii. (a) Sola (b) Aina
- __________________ baba Aina nya die die (a) ese (b) Ara
- ___________________ su pupo (a) omi (b) ojo
- Iya _________________________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Kemi
- IROYIN ATI ASOGBA
- Ile-eko mi dara: talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
- Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko tiwa: talo lo nsoro yii? (a) Alaba
(b) Tunde
- Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka: talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
- Igi ti o olew po ni ile eko temiju tire lo: talo nsoro yii? (a) Tunde
(b) Alaba
- Wo maluu ti baba mi ra, talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
- AROFO IMOTOTO
- Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) ese
- Gba __________________ re pelu (a) inu (b) ayika
- Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun (b) imu
- Ge _______________ re to gun sobolo (a) eekanna (b) ori
- ______________ ti ngbe abe eekannaa ko kere (a) Aisan (b) Arun
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- EWI: IBAWI
E dake je je je
Omo ile eko, e gbohun enun mi,
E je nkorin ara si yin leti
Bee romo ile eko
Ti nsojika
Ti nwarun-un ki
- Arofo yii nba omo ________________ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise
- __________ to gbo baawi ni deni _________ leyin ola (a) aya lile (b) omo giga
- Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin (a) aye keke (b) ibawi moto
- Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi (a) iyan (b) deko
- Ero ____________ ni gbogbo omo ti nko ibawi (a) eyin lawujo (b) iwaju nita
- HUWA IMOORE SI OBI RE
Adan dori kodo
O nwose eye
Eje ka ronu wo
Ka mo baye tin lo
Ka mohun ti nsele nile, loko ati
Nibi gbogbo
- ____________________ dori kodo (a) Adan (b) Owiwi
- O nwose ___________________ (a) Eran (b) Eye
- E toju awon __________________ (a) ilu (b) obi
- Eyin _________________ gbogbo (a) omode (b) agba
- ___________ roko olowo (a) egbon (b) baba
- ITOJU ARA
- Ojoojumo ni _________ foe yin re (a) Ade (b) Kola
- A we gbogbo _________ re das aka (a) ese (b) ara
- ___________ re a mo nini ni gbogbo igba (a) aso (b) irun
- Ma __________ rira laaye (a) gbese (b) gbeyin
- ____________ ara a maa faisan (a) eeri (b) irun
- ITOJU ILE
- Ayika ile to doti maa nfa _______ (a) aisan (b) efori
- ________ kii se ore eniyan (a) arun (b) obun
- Ka maa gba ______ laaye (a) gbegbin (b) oorun
- ___________ nii wo aso _______ (a) omi igi (b) ina onida
- _________ lo yeni (a) obun (b) imototo
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- IWE KIKA: ASIMU OLE
- _________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu
- Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe.
(a) o nra epa je (b) o ni ore pupo (d) o nlo si oja ayelu
- Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki, oju re jaa na” ni __________
(a) Ore Pokii kan (b) obi pokii (d) Aladugbo Pokii kan
- _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan-an fun lati da seria fun-un
(a) olopaa (b) ore Pokii (d) ara oja ayelu
- Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile? (a) Adigun (b) Alao (d) Akanni
- IWE KIKA: ADUBI ATI IYA RE
- Omo melo ni Iya Adubi bi? (a) omo meta (b) omo merin (d) omo kan
- Iru owo wo ni Awele nse (a) o nta eja (b) o nta isu (d) o nta ounje
- Ona wo ni Olorun gba pon Adunbi le? (a) Adubi ba iya re ta eja (b) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan
- Kiini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu
(a) O fe kawe sii (b) ko mo eniyan kankan (d) Ise omo odo
- Kini koje ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re
(a) Ko feran oge (b) Aso won ni ilu won (d) Ere oja re ko po
- ILU ILE YORUBA
- ___________ lo ni ilu bata (a) onisango (b) olobatala
- Awon ____________ lo ni ilu ipese (a) ologun (b) Babalawo
- Awon ___________ lo ni ilu Agere (a) Elegun (b) ologun
- Awon ____________ lo ni ilu igbin (a) olobatala (b) elegun
- Awon ___________ lo ni ilu gbedu (a) olosa (b) oba ati ijoye
- OJU KO KURO
- Ohun to nfa oku kokoro ni ______ (a) iwa ibaje (b) afowofa (d) aini-itelorun
- Ohun ti o nbere ole ni ________ (a) afowofa (b) gbewiri (d) ojukokuro
- Ewo lo ye omo rere? (a) ole (b) afowora (d) itelorun
- Eba _______ to nse ojukokoro wi (a) odo (b) omode (d) arugbo
- Kini itumo agbewiri. (a) ole (b) ole (d) ika
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- ERE IDARAYA
- Eniyan melon lo nta Ayo olopon. (a) meji (b) merin (d) meta
- Omo Ayo me lo ni o ngbe oju opon aypo lapopo. (a) merinla (b) mejilelogun (d) mejidinladota
- Apa ____________ ni a nta ayo si (a) osi(b) otun (d) eyin
- Awon ti o nduro woran nibi ere Ayo ni a npe ni _______ (a) onilaja ayo (b) oniduro ayo (d) osefe ayo
- Iru awo wo ni awo omo ayo. (a) awoeeru (b) awo eweko (d) awo pupa
- AKANLO EDE :
- Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo
(a) ko si epa mo (b) ko si atunse mo (d) epa ko si ninu oro
- Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle
(a) edun ti o nrin ni ile (b) edun ti o po ganan (d) eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago
iii. Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori: (a) ki eniyan ko jale lati se nnkan (b) ki eniyan ko jale (d) kin eniyan fi aake si ori
- Kini itumo akanlo ede yii : te oju aje mole (a) ya ole (b) ya ika (d) ya apa
- Kini itumo akanlo ede yii : se aya gbangba. (a) ki a ta aya siwaju (b) ki adoju ko isoro pelu aiberu ati aifoya (d) ki aya eniyan le
- OWE ILE YORUBA:
- Pari owe yii:- Agba kii nwa loja. (a) ki inu o bini (b) ko maa se lagbalagba (d) kori omo tuntun wo
- Pari owe yii:- obe ti bale ile kii nje: (a)ko dun ni (b) iyo ja ni (d) iyale ile kii nse
- Pari owe yii:- bi okete badagba: (a) a paje ni (b) omu omo e nii mu (d) asalo ni
- Pari owe yii:- Bomode ba mowo we. (a) aba agba jeun (b) owo e mo ni (d) ate siwaju si
- Pari owe yii:- Ile ti a fi ito mo. (a) adara sini (b) ategun a gbe lo (d) iri ni yoo wo
- ONKA NI EDE YOURIBA
- Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 55 (a) Arundinlogun (b) Arundinlogoji (d) Arundinlogota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 70 (a) adota (b) Adorin (d) Ogorun
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 100 (a) Ogota (b) Ogorun (d) Ogoji
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 85 (a) Arundinladorun (b) Arundinlogoji (d) Arundinladota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) Ogorun (b) Ogota (d) Adofa
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- IWE KIKA: IYI ISE SISE
- Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) Inu oko (d) Odede
- Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) imele
- Iwa Agbeke di awokose fun awon elegbere nitori _________
(a) iro pipa re (b) iwa awon obi re (d) iwa omoluabi re
- Iya Agbeke fun-un ni _________ ko to bere ile-eko
(a) Aso tuntun (b) imoran (d) Ounje to dara
- Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko
(a) Won na-an legbe (b) won fun-un nise se (d) won fun-un ni eko ofe
- IWE KIKA: IJAKO LERE
- Kini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, “omo naa niyi”?
(a) o fe fun won ni ehoro (b) o fe ba ehoro sare (d) o fe salo
- Won ko pa tie bo o, “tumo si pe”
(a) won jaa ni patie (b) won na-an daadaa (d) won fi iya je e
- Inu Alagba Alao dun nitori won _____ (a) bu Ajao (b) na Ajao (d) ko won jade
- ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao (a) ile-eko (b) ita (d) ogba
- Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____
- sare pe awon obi (b) lo si ago olopaa (d) ba gbogbo awon akekoo soro
- LITIRESO: EWI OMOLUABI
- Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____ (a) siwahu (b) soyaya (d) se wobia
- Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______ (a) sepe (b) woso ti ko mo (d) jeun ni won-tunwon-si
- Omo ti yoo je asa mu tumo si _____ (a) omo ti yoo je ologbon (b) oruko re yoo maa je Asamu (d) yoo sa nnkan mu
- Akewi yii fe ki a je ________ (a) omoluabi (b) ole (d) gbewiri
- Ewi yii so pe:- “a-la-jewora ni _______ (a) gbewiri (b) ole (d) wobia
- ONKA NI EDE YORUBA
- Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 110 (a) Adofa (b) Ogorun (d) Ogota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 100 (a) Ogorun (b) Ogota (d) Ogoji
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 150 (a) Ogorin (b) Ogorun (d) Adojo
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) Adota (b) Ogoji (d) Adorun
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 60 (a) Ogoji (b) Ogbon (d) Ogota
Class: J.S.S 1 Subject: YORUBA
APA KINNI
Ka ayoka isale yiI ki o si dahun ibeere ti o te lee.
Ojo je omo ilu ilaro, ore re je Omo Agbele. Ojo feran ore re pupo nitori ata, tumati, isu, agbado, ati osan ti o maa n fun. Lotito ise agbe ni ise Alade sugbon Ojo ti o je ode kii fun ore re ni eran ti o ba fi ibon pa ninu igbo nitori wi pe oun se wahala pupo ki oun to pa a.
Ni Ojo kan bi ojo se n gbe eran oya ti o fi takute pa lo si oja lati lo ta ni o ba pade Alade ti o n ko isu ati efo bo wa fun un.
Ojo ko fe ki Alade mo ohun ti o wa ninu apo naa, sugbon Alade ko isu ati efo ti o ko wa fun un sinu apo. Igba ti alade wo apo ore re o ri oya ninu apo ti o gbe lowo. Oju ti Ojo pupo, inu si bi Alade fun iru iwa ti Ojo n hu.
Dahun ibeere
- Bawo ni ojo se je si Alade ? (a) Egbon (b)Baba (c)Oga (d)Ore
- Kin ni Alade fe fun ojo nigba ti o ri oya ninu apo re? (a) Agbado (b) Ata (c) Isu (d) Ore
- Ki ni Ojo fi pa oya ti Alade ri ninu apo re (a)Ibon ?(b)kunmo (c) Takute (d) Ofa
- Iru iwa wo ni iwa ojo (a) Ahun (b)Ika (c)Ole (d) Opuro
- Ki ni o mu Ojo ni igba ti Alade ri oya ninu apo re ?(a) ebi pa a (b) Inu bi i (c) Oju tii (d)Ori fo o
- Iro ede ni _____ ti a fi eti gbo ninu ede. (a) Ariwo (b) Ege (c) Ipin (d)Ohun
- Alifabeeti ede Yoruba je _______ (a) 24 (b)11 (c)18 (d)25
- Leta ti o pari alifabeeti Yoruba ni _____ (a)A (b) e (c)y (d)u
- Konsonanti inu ede Yoruba je (a) 20 (b)21 (c)7 (d)18
- Alifabeetiyoruba pin siorisii (a)Meta (b)Meji (c)Merin (d)Meje
- Iwe meji ati iwe meta je iwe (a)Meji (b) Meta (c)Merin (d)Marun
- Oruko miranti Yoruba n pe 20 ni (a) Ogoji (b) Okoo (c)Aado (d)eede
- Ti a ba ro 20+10, o je (a)ogun (b)Ogbon (c)Aadota (d)Ogorin
- Baba, iya ati omo meji je eniyan (a)Kan (b)Merin (c)Marun (d)Mefa
- Ogorun-un ni (a)60 (b)70(b)100 (c)90
- Edo foro ni (a) Voice box(b)Lungs (c)Liver (d)Leg
- Afipe akanmole ni (a)Ete isale (b)Eyin oke (c)Olele (d)Eyin isale
- Onamelooni a le pin afipesi? Ona (a)Meji (b)Meta (c)Merin (d)Kan
- Ona meloo ni ahon pin si? (a)Meji (b)Meta (c)Merin (d)Mefa
- Apeere eya-ara ifo ti a ko le fi oju ri ni (a)Edo-foro (b)Eyin-oke (c)Olele (d)Ete
- Konsonanti ____ ko si ninu alifabeeti yoruba (a)B (b)T (c)S (d)Z
- Ete mejeeji ni a fi pe iro (a)/t/ (b)/f/ (c)/r/ (d)/b/
- Konsonanti akunyun ni (a)/t/ (b)/j/ (c)/f/ (d)/h/
- Leta ti a pe nigba ti eyin oke ati ete isale pade ni (a)/f/ (b)/m/(c)/d/(d)/h/
- Konsonanti ti a pe nigba ti ahon kako ni (a)gb (b)w (c)j (d)r
- Meloo ni faweli aranmupe?(a)meje(b)mefa(c)maru-un(d)merin
- Faweli akoko ninu alifabeeti ni (a)/u/(b)/t/(c) I (d)a
- Oro tp ni faweli aranmupe ni (a)Iyan (b)Ile (c)Ara (d)oye
- _______ se iranlowo bi ede Yoruba se di kiko sile (a)Obafemi Awolowo (b)Ajayi Crowther (c)Oliver Twist (d)Wande Abimbola
- Ijo ti o se iranwo bi ede Yoruba se di kiko sile nI ijo (a)Sele (b)Ridiimu (c)Siemeesi (d)Gurumaraaji
APA KEJI
Dahun ibeere meta ni abala yii
- Ki ni iro ede?
1b. Ona meji ti iro ede pin si ni _____ ati _____
1d. Ko gbogbo iro konsonanti inu ede Yoruba sile
- Daruko eya ara ifo marun(5) ti ale fi oju ri
2b. ko afipe asunsi marun sile
- Ya ate faweli airanmupe inu ede Yoruba pelu iro inu won
- Ki ni silebu?
4b. pin awon oro yii si silebu
- Konko
- Akan
- Agbalagba
- Omode
- Olopaa
- Oronbo
- Ekunrere
- Ayan
- Tun awon oro yii ko si sipeli ode-oni
- On
- Aiye
- Shaki
- Nigbati
- enia
FIRST TERM EXAMINATION
Class: JSS 2 Subject: YORUBA Time
Dahun gbogbo ibere wonyi
- ________ maa n ni awe gbolohun meji tabi ju bee lo ninu gbolohun (a) Gbolohun onijo (b) Gbolohun onibo (d) Gbolohun amulo (e) Gbolohun ayoka
- ________ je ohun to maa n waye laarin awon Yoruba lati gbogun ti orisi iwa ireje (a) Ounje jije (b) Ogun jija (d) Ogun agbaye (e) Ogun Amuye
- ________ je awon oro isiri tabi iwuri eyi ti awon Yoruba maa n fi yin ara won tabi eni ti inu won ba dun si (a) Hakangbon (b) Oriki (d) Ekun Iyawo (e) Orin ode
- ________ je okan lara awon ohun elo ogun (a) sakabula (b) ikerengbe (d) ogedegbe (e) ise amuye
- _______ je okan lara awon oogun ti awon eniyan ma an lo lati fi dira fun ogun jijae agbagba (a) Ayeta (b) Ogede agbagba (d) Abidogun (e) Ifara
- _______ je okan lara iwulo oriki (a) Oriki a ma fa ijangbon (b) Oriki a ma fa ipaniyan (d) oriki wulo lati fi iwa akin han (e) Oriki ama fa iran ija wa
- Egberun mesan-an je ____ ni ede geesi (a) 900 (b) 9000 (d) 1000 (e) 16000
- _____ je okan lara awon nkan ti ole fa ogun (a) iwa ilara (b) iwa rere (d) iwa irele (e) iwa isokan
- _____ je okan lara awon iran ti o ma ja ogun (a) iran onikoyi (b) iran Sunday igboho(d) iran kule poly (e) iran eleso
- Ninu onka ile yoruba tede gbe run je ______ (a) 900 (b) 200 (d) 5000 (e) 120
- Apetusija je ______ (a) eniyan ti o gbe igbese ki ogun le pari (b) eniyan ti ko je ki ija tan (d) eniyan bi esu (e) eniyan alawo funfun
- _______ je kika itan tabi isele kan ni ona ti a ka ye ni ye ye keyeke (a) pataki (b) akaye (d) ere ori tage (e) ohum elo
- Apetusiju je _______ (a) eniyan ti o gbe igbese ki ogun le pari (b) eniyan ti ko fe ki ija tan (d) eniyan bi esu (e) eniyan alawo funfun
- _______ je ki itan tabi isele kan ni ona ti yoo fi han pe ohun ti a ka ye ni keyeke (a) Pataki (b) akaye (c) ere ori tage (e) ohun elo
- _______ je okan Pataki oriki ile Yoruba (a) gbigbe asa ile wa laruge (b) fifa ija jija sarin ilu (d) bi ba eni loju je (e) fifi eto omoniyan dun
- _______ je oruko olori orile – ede yii lowolowo (a) Yemi Oshinbanjo (b) Myhammed Buhari (d) Adams Oshomole (e) Bukola Saraki
- Petepete ni ogun jija , bi oti nse ________ lo n se _________ (a) ibi , rere (b) Ara, Iyan (d) Ifokan bale (e) Ododo irawo
- ______ ni a maa nfi pon oro-ise dipo oro aponle tabi apola aponle. (a) gbolohun itoka (b) gbolohun iwaju (d) gbolohun onibo asaponle (e) gbolohun alawipe
- ________ je apeere gbolohun onibo asapejuwe (a) Mora moto (b) MOfe ra ile (d) Dodo ti mo ra ti omoje dun (e) Ade koi le
- _______ je okan lara awon ohun ti ko wulo fun awon jagunjagun (a) ibon (b) gudugudu (d) igbadun (e) ada
AKAYE
KA AKAYE YI KI OSI DA HUN AWON IBERE TI OWA NI IDI RE
Koju iseju marun-un ti won ri oku naa ti gbogbo ibi ise won ti daru lati oke de ile nigba ti yoo si fi to ogbon iseju si awon olopa ti bo ise bi igba ti it abo eyin.
Nigba ti awon olopa ye ibi ti kaka ku si wo won nip e awon oogun dudu kan wa lodo re nibe ati pe nes lo dabi eni subu lule lori aga.onisegun oyinbo ti won ni ki oye oku naa wo ni oun kori apeere pe oje majele sugbon boye ni ki se wipe ohun ti opa ni eye gbigbo na.
Oto osu mefa leyan iku kaka ki otito ohun ti o sele ti o fa okunfa ikure to yoju. Ase nse lo lo se Oogun ti ose fi si ori aga fun awon meji ti won je oga fun un ni ibi ise. Ni gbati oti sokale ni oti ran ofo ti won ni ki op emo enu ki oma ba gbabbe.
Bi oti wo ogba ibi se ni oran ti pe oun fey a gbe. Eyi je ki o ya si yara kan ti won ko lomo, ti osi ko ogun na si ori aga kan ti owa nibe. Nibe ti o yagbe tan lo wa ko oogun na kuro lori aga. Ofe joko lori aga na ki owa ronu ona ti yoo gba lo oogun owo re ti elomiran ko si fi ni le joko si ori ijoko naa.
Se ero re nip e oun ko iti pe ofo oogun naa ti oun fi ko le ijoko ti o wa ni iyara ti oun fi ko le ijoko ti o wa ni iyara ti oun ko mo pe soki lobe oge. Ase eyi ti on ran mo enu ki oto w pile sise fun ogun yi.
Bi o ti fi idi le aga na lo subu yakata, iseju akan lo si ti pa ipo ola, ani bi segisegi ba segi tan ori ara re ni yio fi ruu
Dahun awon ibere ni isori yi
- Ori oro wo ni oba ayoka yi mu dara dara (a) oga olopa (b) ile nla (d) Arigisegi ori arare ni yoo fi ru (e) iran omo oba
- Kini oruko eniti ose iku paarare ninu akaye yi (a) kamoru (b) kaka (d) karimu (e) Aderemi
- Oto osu melo _______ ti asiri iku ti o pa ogbeni yi tu. (a) mewa (b) mejo (d) mefa (e) mesan
- Kini ero awon olopa lori okunfa iku kaka (a) erongba awon olopa nip e kaka gbe majele je (b) kaka po kun so (d) erongba won nipe kaka ku iku amutorunwa (e) kaka ku iku moto
- Awon wo ni won bo ibise bi igba ti it abo eyin (a) awon agbero (b) awon omo ile iwe (d) awon olopa (e) awon ara oko
- Ogo je je ______ ninu onka (a) 140 (b) 190 (d) 150 (e) 1200
- ________ onkan lara awon eran osin. (a) pepeye (b) kinihun (d) raliat (e) ejo la
- Kini oruko are onakakafo ile Yoruba ni bayi (a) iba Moshod Abiola (b) Iba Gani Adams (d) Are Afe Babalola (e) Ade elese
- ________ je okan lara awon oriki ni ile Yoruba (a) Abula (b) Akanbi (d) Abebe (e) Ayan mo
- Inu osu won in orilede Niajiria gba ominira (a) Osu kewa (b) Osu kefa (d) Osu kesan (e) Osun Kerin
IPIN KETA
Dahun ibere meji ni ipinyi
1a. Kini Oriki
- Daruko orisi oriki fun okunrin ati obinrin marun marun
ORIKI ORIKI
Okunrin | Obinrin |
1. | |
2. | |
3. | |
4. | |
5. |
2a. Daruko awon nka meta ti ole fa ogun jija
- Awon wo ni Yoruba npe ni apetu sija?
- ONKA
Ede Yoruba | Ede Geesi |
|
100 |
|
101 |
|
102 |
|
103 |
|
104 |
|
200 |
|
110 |
|
120 |
|
130 |
|
140 |
- Daruko merin lara awon ohun ti ale fi ja ogun ni ile Yoruba?
- Ki oriki Idowu lekunrere pelu akosile re si inu iwere
Class: J.S.S 3 Subject: YORUBA
Apa kinni
Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee
Ni ojo kan Funke wa ni ile-epo ibi ti o ti n sise ti o si n ta epo fun awon oni moto ni okookan, ejeeji
Ni ojiji ni awon igara olosa ti awon ti ibon lowo yawo ile epo ibi ti funke ti n sise. A fi koosa,koosa ti won da ibon bole. Oro di bo o lo, o yago. Gbogbo awon ti won paaki lati ra epo be sile ninu moto, won si n sa lo, lati sa asala fun emi won. Mo n gbo “doju e bole, doju e bole, bee ni won n yin ibon soke koosa-koosa. Logan ni awon eniyan bii meta ti fi ara gba ota,ti won si n we ninu eje ara won. Paapaapa ni awon ole yii ti gba gbogbo owo ti won ti pa lowoo kasia ile-epo yii won tun gba owo lowo atendanti ti won n ta epo naa. Nigba ti won ni ki Funke ko owo owo re wa ni o ba n lo tiko tiko. Won ta ibon mo funke ni kokose, ki won to gba owo naa ni owo re tipa-tipa. Won si ba ti won lo ki awon olopaa to de.
IBEERE
- Kin ni o sele ni ile-epo ti funke ti n sise? Awon (a)osise da ise sile (b)atendanti ko tete de (c)Ole ja nibe (d) Oko ko to daadaa
- Kin ni awon onibaara ti won gbo iro ibon se?won (a)Sa asala fun emi won (b)Koju awon ole (c)Ko tile bikita rara (d)N ra epo tiwon lo
- Kin ni o sele si awon meta ti won ku?won (a)Ba ole woya ija (b)Fi ara gba ota (c)Mu oti yo (d)Da ina sun ile-epo
- Kin ni idi ti won fi ta Funke ni ibon ni kokose? Ko fe (a)gbe owo owo re sile (b)ba won jale (c)ta epo fun won (d)so oruko re fun won
- Igbe wo ni awon ole n pa bi won ti wo ile-epo(a)E maa fo soke (b) E kawo yin soke (c)doju yin boole (d) kaasa
- Oro____le se ise oluwa, abo,ati eyan ninu gbolohun (a)Atokun (b)Apejuwe (c)Aponle (d)Oruko
- Toka si oro oluwa inu gbolohun yii. Gbenga mu ijo l’agbo (a)Gbenga (b)Ijo (c)L’agbo (d)Jo
- Toka si akoto ti o tona ninu awon wonyi (a)gan (b)gan-nan (c)gan an (d)gan-an
- Ninu akoto Yoruba, a maa n ko “wa ise” bayi (a)waasee (b)waase (c)waise (d)wasee
- Ninu akoto ede Yoruba, bi a ti n ko sipeli “pepeiye”(a)pepeye(b)peipeye(c)pepe I eye (d)iyepepe
- Odun ___ni awon igbimo ede fi owo si lilo akoto Yoruba (a)1971 (b)1972 (c)1973(d)1974
- Iro meji wo ni ko gbodo te le ara won ninu ede Yoruba (a)faweli (b)Konsonanti (c)Silebu (d)Ami ohun
- “Biotilejepe” ni a n ko bayi(a)Bio tile jepe (b)Bi o tile je pe(c)Bi o tile je-pe (d)Bi o tilejepe
- _____ ni ege oro ti eemi le gbe jade leeka soso
- Oro oni silebu meji ni (a)fun (b)wo (c)yin(d)ara
- Oro onisilebu kan ni (a)baba (b)iya (c)ran (d)ara
- Leta ti ogba ki a ko oruko kan ni ipari ni (a)gbefe (b)aigbefe(c)oniroyin(d)isorogbesi
- Adiresi meloo ni a n ko ninu leta aigbefe?adiresi(a)kan (b)Meji(c)meta (d)merim
- Envelope ni a n pe I (a) Apo-iwe(b)apo eru (c)Baagi akoleta (d)apo oro
- “Bunmi pa ejo” oro aropo oruko ti a le lo fun ejo ni (a) Mi(b)Won (c)e (d)a
- “Abike ni o ra aso” oro oruko oluwa ni (a)ra (b)o (c)Abike (d)Aso
- “Olopaa mu omo pupa lanaa” (a)Oro apejuwe (b)Oro-ise (c)oro oruko (d)Oro-asopo
- Oro aropo oruko enikinni eyo ni ipo abo ni (a)Mo (b)A (c)Mi (d)Won
- “Tolulope jeun amo ko yo” oro asopo inu gbolohun yii ni (a)Ko (b)Tolulope(c)Amo (d)Jeun
- “Taiwo n wo sun-un” sun-un ti a fala si nidi je (a)Oro-ise (b) Oro aponle (c)Oro atokun (d)Oro eyan
- Iwa ika wonyi wopo ni aye atijo ayafi (a)Ifiniseru(b) Igbeselobinrin(c)Ifomosowo(d)Ifinirubo
- Iwa-ika to wopo lode oni niwonyi ayafi (a)Ijinigbe (b)Ifinisofa (c)lilo omo nilokulo (d) Ifinisowo
- Fifi owo duro fun owo ti a ya ni a n pe ni (a)ifiirubo (b)Ifomosowo (c)Jiji eniyan gbe (d)Ifinisofa
- Ohun ti a se si eniyan ti o buru jai ni a n pe ni (a)Iwa ika (b)Ifinirubo (c)Iwa-omoluabi (d)Iwa eniyan
- Awon____ ni o saaba maa n gbe ese le iyawo oniyawo laye atijo (a)Olowo (b)Oba (c)Ijoye (d)Baale-ile
APA KEJI
Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki
- Ko aroko ti ko din ni oju-ewe kan lori okan lara koko wonyi
- Ounje ti mo feran ju lo
- Omo wulo ju owo lo
- Ko leta si ore re ti o wa ni ile-iwe miran, salaye fun un lori akitiyan obi re lori eko re
- Toka si ise meta ti oro aropo oruko le se ninu gbolohun
2b. Ko apeere oro meji –meji ti o fi idi ise wonyii mule
- Ko awon figo yii sile ni onka Yoruba
- 12,000
- 2,000
- 400
- 1060
- 500
- Tun awon oro yii ko si sipeli ode-oni
- Gegebi
- Shugbon
- Olopa
- Ebute metta
- Niwongbati
- Daruko iwa ika marun(5)ti o wopo ni aye atijo
5b. Menuba iwa ika marun(5)ti o wopo ni ode-oni
Class: S.S.S 1 Subject: YORUBA
Apa kinni
Dahun gbogbo ibeere
Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee
Ni aye atijo,eko ile se Pataki ju lo laarin awon omo Yoruba sugbon laye ode –oni, eko ile-iwe ni awon eniyan gbojule nitori ona atije- atimu nikan. Won ko mo wi pe eko kookan lo ni aye tire. Bi omo ba ni eko-iwe ti ko ni eko ile, alailekoo ni won maa n pe iru omo bee, nitori omo ti o ba ni eko-ile ni Yoruba maa n pe ni omoluabi.
Lara eko ile ni iwa ikini,imototo,ibowo fagba,itiju,itoju ounje,abbl. Opolopo omo ode-oni ni o ni eko ile-iwe. Sugbon ti ko ni eko ile nitori pe awon obi won paapaa ko ka eko ile kun Pataki. Omo won ko mo ina da, ko ni ibowo fagba, sibe inu awon obi won si dun sii. Won ti gbagbe pe eko ile-iwe lai si eko ile dabii tii ti ko ni suga, omo binrin ti ko ni eko ile ni yoo so iru eni ti awon obi re je ni ile-oko
Dahun ibeere
- Kin ni o n mu ki inu awon obi dun si eko ile-iwe (a)gbayi pupo (b)o le mu eniyan bimo pupo (c) le e pese atije ati atimu (d)maa n fa aisan si eniyan lara
- Eyi maa n fa iwa olaju ailekoo laarin awon Yoruba tumo si omo fi ko (a)Feran oluko re (b)Jara mose (c)Mo nipa ise owo (d) ni eko ile
- Ewo ni ko si lara eko ile lara awon wonyi(a)Ibowo fagba (b)Ikini (c)Imototo(d)iwe kika
- Eko wo lo se Pataki laarin awon Yoruba ni ode-oni gege bi o ti wa ninu ayoka yii? (a)Ile (b)Imototo (c)Iwe (d)Isoro
- Ewo ni o tona gege bi o ti wa ninu akaye yii? Eko (a)Ile ko gbayi (b)Ile nikan ni o dara (c)iwe ati tile ko dara (d)iwe ati tile ni o dara
- Ewo ni o le je ori-oro fun aroko asapejuwe ninu awon wonyi (a)asa ibile dara ju asa oyinbo lo(b) Ti mo ba je oga ile eko(c)Faari aseju (d)Ile awon Bukunmi
- Ewo ni igbese ti o saaju ninu leta kiko? (a)Ori-oro (b)Deeti (c)Adiresi(d)Ikini
- /W/je konsonanti (a)Afeji-ete-pe (b)Aferigipe(c)Afafasefetepe (d)Afajape
- Kin ni batani silebu ti o pari ipekun? (a)N (b)KF (c)KFN (d)F
- /O/ ninu ogbon je Mofiimu (a)Afomo (b)Adaduro (c)Ipile (d)Afarahe
- Silebu meloo ni o wa ninu “BELENTASE” (a)Mesan (b)Mejo (c)Mefa (d)Marun
- /e/ je faweli (a)Ayanupe (b)Ayanudiepe(c)Ahaupe(d)Ahanudiepe
- Konsonanti akunyun ni (a)/P/(b)/j/(c)/s/(d)/f/
- Eyin oke ati ete isale ni a fi pe iro (a)/d/(b)/f/(c)/g/(d)/h/
- “F-KF-KF-KF-KF” je batani silebu fun (a)Alaafia (b)Agabagebe (c)Agandangodo (d)Arugbo
- /r/je konsonanti (a)Arehon (b)Afegbeenupe (c)Aseesetan (d)Asenupe
- Ki ni itupale si mofiimu “OMOKOMO”(a)OMO+KO+MO (b)OMO+KOMO (c)OMOKO+MO (d)OMO+KI+OMO
- Apetunpe waye ninu (a)Wase (b)Lilo (c)Eewo (d)Darandaran
- Okan lara ise isenbaye iran Yoruba ni (a)Tisa (b)Loya (c)Igba finfin (d)Dokita
- Iran Yoruba wo lo ni epo fifo? Iran (a)Aresa (b)Irese (c)Onikoyi (d)Olugbon
- Okan ninu ise wonyi nilo oogun (a)Agbe (b)Onidiri (c)Aro dida (d)Ode
- Awon wo ni won n pa oko ni ile Yoruba? Awon (a)ode (b)agbede (c)Agbe (d)Onigbajamo
- Igbese akoko ninu asa igbeyawo ni (a)Iwadii (b)Ifojusode (c)Itoro (d)ijohen
- Gbigba ti omobinrin gba lati fe omokunrin ni a n pe ni (a)Iwadii (b)Ifojusode (c)Ijohen (d)Ibale
- Igbeyawo ti omokunrin ati obirin da ara won yan lore ni a n pe ni (a)Asante (b)Ibale (c)Momi-n-mo-e (d)Abasile
ITAN AROSO
DEBO AWO,MOREMI AJANSORO
- Olu eda itan iwe yii ni _______ (a)fogido (b)Diwura (c)Moremi (d)Orunto
- ______ ni won ba ninu agbara eje ara re? (a)Moremi (b)Olurobi (c)Olu orogbo (d)Fogido
- Kini Elujoba fe fi ewe ti o fe ra se? o fe (a)Fi pon eko (b)Fi bo ile re (c)Fi pon olele (d)ta a
- Iya – baba Moremi ni (a)Diwura (b)Fogido (c)Samosegi (d)Iyun
- _____ ni o toju Moremi dagba (a) Samosegi (b) Diwura(c)Orunto (d)Arole Atewon ro
APA KEJI
Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki
- Ko aroko ti ko din ni 300 eyo oro lori okan lara koko wonyi
- Oremi ti mo feran julo
- Ere alarinrin kan ti mo wo
- Iya wulo fun omo ju baba lo
- Ko leta si ore re ni ilu miran salaye akitiyan ijoba lori awon ona ti o wo ilu re
- Salaye lori awon wonyi pelu apeere meji-meji
- Ipo ete
- Giga apakan ahon
- Toka si ona merin ti a le gba seda oro oruko titun ki o si fi apeere meji -meji gbe idahun re lese
- Ki ni itumo awon oro wonyi?
- Abasile
- Asante
- Apon
- Alarina
- Ifojusode
- Daruko ise abinibi marun, ko si ko ohun elo meta-meta fun okookan won
Class: S.S.S 2 Subject: YORUBA
Apa kinni
Dahun gbogbo ibeere
Ka ayoka isale yii, ki o si dahun ibeere ti o te lee
Ise agbe se Pataki. Gbogbo eniyan lo mo ise ribiribi ti awon agbe n se lawujo. Idi ti a fi gbodo mu ise agbe ni okunkun dun niyii. Gege bi a se mo,awon agbe lo n gbin oniruuru ounje ti a n je. Lai si akitiyan awon agbe, nje enikeni le wa? Ti elomiran ko ba ri ounje je ni ojo kan, a dabi eni pe eni naa ko jeun lati bi ojo meta seyin ni.
Bi a se ni agbe olounje naa ni a ni agbe eleran osin. Iru awon agbe yii a maa sin awon eranko bi maluu, ewure, adiye ati bee bee lo. Awon eranko wonyi ni a n pa, ti a si fi se obe eyi ti o n tun eje ati ara wa se.
Oniruuru aso ti a n wo naa je ise owo agbe. Awon lo n gbin owu ti a fi n hun aso . isori awon agbe olohun osin naa maa n lo awo eran lati se baagi ati bata ti a le fi se amuyangan ni awujo wa titi lo fi de oke-okun
IBEERE
- Ewo ninu awon wonyi ni a le fi se bata ____eran(a)Awo (b)Eti (c)Ese (d)Iwo
- Kin ni idi ti ise agbe se se Pataki lawujo gege bi alayoka se menu ba a?(a)Gbogbo eniyan lo nilo ise agbe (b) O n je ki agbe le lowo-lowo (c)O n je ki a rowo fe iyawo (d)O n pese ohun abalaye
- Awon agbe a maa sin ohun-osin wonyi ayafi(a)Ologbo (b)Maluu (c)Adiye (d)Agutan
- Orisii agbe meloo ni alayoka menuba? (a)Okan (b)Meta (c)Meji (d)Merin
- Ewo ni a ko le fi owu hun ninu awon wonyi (a)Ankara (b)Apere (c) Leesi (d)Ofi
- “Omo yin tooto” le je yo ninu aroko (a)Alalaye (b)Oni leta (c)Alariyanjiyan(d)Asotan
- Ninu leta aigbefe ni kan ni a ti maa n ko (a)Adiresi (b)Oruko (c)Akori (d)Afiwe
- “Ile-iwe mi” je ori oro fun aroko (a)Oniroyin (b)Oni leta (c)Alapejuwe(d)Alariyanjiyan
- Faweli aranmupe meloo ni o wa ninu ede Yoruba (a)Meje (b)Mefa (c)Marun (d)Merin
- Esin ti o wopo julo lawujo Yoruba lode-oni ni (a)Isegun (b)Kirisiteeni (c)Buda (d)Oro
- Okan Pataki lara opo ti esin musulumi duro le lori ni (a)Ogun jija (b)Itore aanu sise (c)Iku ati ajinde Allah(d)Fifi iya je elesin miran
- Awon____ ni o ko esin Musulumi wo awujo Yoruba(a)Heberu (b)Hausa (c)Giriki (d)Larubawa
- Ere idaraya ojumomo ni (a)Okoto tita (b)Alo pipa (c)Ijakadi(d)Ekun meeran
- Akoko wo ni Yoruba maa n saaba se ere idaraya (a)Owuro kutu hai (b)Iyaleta (c)Osan gangan(d)Leyin ise
- Awon _____ ni o ni ege dida (a)Ijebu (b)Oyo (c)Osogbo (d)Egba
- Awon ilu wo lo ni oro ayingun? Awon (a)Oyo (b)Ife (c)Osogbo (d)Egba
- Okan ninu awon wonyi ni a maa n lo oro fun (a)Wiwa Owo (b)Lile ajakale arun ni ilu (c)Lati je ki eto oro aje gbooro si (d)Fun eni ti o n wa omo
- Akoko wo ni a le da ege? (a)Osan (b)Owuro (c)Asale(d)Igbakuugba
- Okan lara ewi alohun ajemesin ni (a)Ekun iyawo (b)Bolojo (c)Alamo(d)Iyere
- Orisa_____ ni o ni arungbe (a)Sago(b)Oro (b)Egungun(d)Oya
- Orisa ti o ni iwi kike ni (a) Sango (b)oro (c)Egugun(d)Obatala
- Gbolohun ti a fi n gbe ero okan kale lori koko kan ni gbolohun (a)Abode (b)Alakanpo (c)Alaye (d)Onisorogbesi
- Irufe gbolohun wo niyi “Gbigba ni won gba owo ayo ni owo mi ”Gbolohun ”(a)abode (b)Ase (c)ibeere (d)akiyesi alatenumo
- “Pa ilekun de” je apeere gbolohun (a)Abode (b)Ase (c)Alalaye(d)Ibeere
- “Nje oga ti de ”gbolohun(a)Abode (b)Ase (c)Alayaye(d)Ibeere
- “Ki I se olu ni o mu owo ”je apeere gbolohun(a)Abode (b)Ayisodi (d)alalaye(c)ibeere(d)Ase
- Olori awon oyomesi ni (a)Agbaakin(b)Basorun(c)Asipa (d)samu
- Oloye Meloo ni iwarefa? (a)Marun (b)Mefa (c)Meje (d)Mejo
- Oye ajewo ni oye (a)iyaloja (b)Iyalode (c)Bobagunwa(d)Ajiroba
APA KEJI
Dahun ibeere meta ni abala yii, sugbon nomba (1) se Pataki
- Ko aroko ti ko din ni 300 eyo oro lori Okan ninu koko wonyi
- Ile iwe ijoba dara ju ile iwe aladani
- Omo kunrin wulo fun obi ju omobinrin lo
- Ojo kan ti n ko le gbagbe
- Ko leta si olootu iwe iroyin kan ni agbagbe re salaye fun nipa awon ona ti o ti di koto orun ni adugbo re
- Toka si ojuse osugbo marun
2b. Menuba ohun marun ti a le fi oro se
- Menuba opo marun ti esin Musulumi duro le lori.
3b. Daruko esin marun ti o wa ni awujo Yoruba lode oni
- Menuba ise olori ilu marun . (b) salaye awon wonyi
- Oba alakoro
- Oba alade
- Pelu apeere meji-meji, ki ni
- Gbolohun ase
- Gbolohun ibeere
- Gbolohun abode
- Gbolohun akanpo
- Gbolohun ayisodi