YORUBA LANGUAGE PRIMARY 1 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 1

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

  1. Iro Ede:

Di alafo awon leta wonyii

A ______ d ______ e ______ g ______ h

______ j ______ l ______ n ______ o ______ r _______ s

  1. Kini Oruko awon aworan wonyii
  2. (Lodo, opon)
  3. (ibon, igi)
  4. (irin, okun)
  5. (ayan, eye)
  6. (igba, irin)
  7. Di awon alafo wonyii
  8. O j ____ (u, k)
  9. O w ____ (p, o)
  10. E s ____ (e, m)
  11. O r ____ (y, i)
  12. I k ____ (a, m)
  13. Onka ni ede Yoruba:

Kini oruko awon nomba wonyii ni ede Yoruba

  1. 2 = (eeji, eerin)
  2. 3 = (eefa, eeta)
  3. 5 = (arun-un, eejo)
  4. 1 = (eeta, ookan)
  5. 4 = (eerin, eesan)
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share