Akole: iwe kika Darosa 

Class: Primary Five

Akole: Iwe Kika Darosa

Ki akekoo tun iwe yii ka ni owo won nile, kiwon si dahun awon ibeere wonyii lori re.
Ki won si oju iwe ketaleladorin (73) eko kerindinlogun (16) ninu iwe kika EKO EDE YORUBA ODE ONI.


Ibeere

1. Kini o so Darosa di olokiki?

  • (A) Aile ti oko
  • (B) Egbe ti o nko
  • (C) Eko ti o ko
  • (D) Owo ti o ni

2. Ona wo ni Darosa ngba ran Mekunu lowo?

  • (A) O n’ya won lowo
  • (B) O n’ran wo nile eko
  • (C) O nfun won ni ise se
  • (D) O n’ya won nile gbe

3. Darosa nfe ki omode ______

  • (A) Feran obi
  • (B) Maasa nile eko
  • (C) Fi oju si eko re
  • (D) Di folefole
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *