Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogbon

Date: Friday, 1st May, 2020.
Class: Pry three
Subject: Yoruba Studies

Akole:onka ni ede Yoruba lati ori ookan de ogbon

1-Ookan
2-Eeji
3-Eeta
4-Eerin
5-Aarun
6-Eefa
7-Eeje
8-Eejo
9-Eesan
10-Ewaa
11-Okanla
12-Ejila
13-Etala
14-Erinla
15-Aarundinlogun
16-Eerindinlogun
17-Eetadinlogun
18-Ejidinlogun
19-Okandinlogun
20-ogun-un
21-Okanlelogun
22-Ejilelogun
23-Etalelogun
24-Erinlelogun
25-Arundinlogbon
26-Erindinlogbon
27-Etadinlogbon
28-Ejidinlogbon
29-Okandinlogbon
30-Ogbon.

Review work:

Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba:

1: 10- (a-Eejo b-Eewa)
2: 14- (a-Eerinla b-Eefa)
3: 15- (a-Arundinlogun b-Okanla)
4: 13- (a-Okanla b-Etala)
5: 20- (a-Ogbon b-Ogun)

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *