SECOND TERM EXAMINATION 2020 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

SECOND TERM EXAMINATION 2020
CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
1.) DI AWON ALAFO WONYII PELU AWON LETA TI OYE
A ________ D ________ Ę ________ G _________ I
________ H ________ J ________ L ________ N _________
Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y

ERE IDARA YA:
1.) Eniyan melo ni o nta okoto_____ (a) meji (b) kan
2.) ______________ ni a fi nse okoto (a) ike (b) paanu ti odogun
3.) Ori ibo ni a ti nta okoto (a) Ile didan (b) eni
4.) Eniyan melo ni o nta ayo olopon (a) meta (b) meji
5.) Omo Ayo melo ni o wa ninu iho kankan (a) merin (b) mefa

ORIN IREMOLEKUN
1.) Talo ba mi ni _______ wi o? (a) loko (b) lomo
2.) ______ e lo ba a wi o? (a) iya (b) egbon
3.) Bi o ku o, maa ra ___________ fun o (a) egba (b) aso
4.) Bi o ku, maa ra ______ orun (a) ileke (b) egba
5.) ________ mo ra la pon o ka o (a) eru (b) ile

AFINJU EYE
1.) Inu _________ ni leyele ngbe (a) ile (b) igbo
2.) O fi ______ tonitoni bora (a) Aso (b) Iye
3.) ________ kii gbe inu igbe (a) eyele (b) ologbo
4.) O ____________ tonitoni (a) sun (b) rin
5.) Eyele kii ba ___________ je ko ba mu, ko dojo iku ko yeri (a) onile (b) olosi

 

 

 

[mediator_tech]

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *