1st Term Examination YORUBA JSS 3
Edu Delight Tutors
Subuode Gbaga Gasline Ogun State
1st Term Examination
YORUBA
JSS 3
IPIN A
Ka ewi yii ki o si dahun ibeere ti tele e
Bi won ba n ba o soro
Jowo ma se binu omo
Eni oyinbo feran lo n ti mole
Omo obi fera lo n ba wi
Igba obi ba feran omo a ni
Ma pa mi, ma pa mi
Sugbon bi obi ba jawo loro omo tan
Nii dip e omo yii, ma paara re
Edumare ko nii yowo loro koowa wa
Eni a n baa wi
To n warun ki
Se bi lojiji niru won I parun
Ki iparun jinna rer somode oun agba
Ki ibanuje maa gbenu wowa
Kire o je ti mutunmuwa
IBEERE
- Irufe Ewi Wo Ni Eyi (A) ewi abalaye (b) ewi omode (d) ewi agba (e) titun
- Itumo mutumnwa ni (a) omuti (b) mu ti ile wa (d)gbogbo eniyan (e) iwa omujo
- Ki lo sele si omo ti a n ba wi, (a) A parun lojiiji (b) A di olowo (d) iparun a jina sii (e) A di ore oyinbo
- Awon omo wo ni obi maa n ba wi (a) omo arole (b) omo mutunwa (d) omo abikeyin (e) omo ti won ba feran
- Akole wo lo to si ewi yii (a) ma pa mi (b) igboran san jebo lo (d) iparun (e) mutumnwa
- Faweli aranmupe ni (a) o (b) u (d) un
- Ami (/) duro fun (a) ami oke (b) ami aarin (d) ami (e) ami iwaju
- Silebu —– lo wa ninu irankiran (a) mejo (b) mefa (d) merin (e) meji
- —– ni faweli ti kii bere oro Yoruba ajumolo (a) u (b) e (d) o (e) i
- Pin dindindin si silebu (a) d-in-di-n-din (b) din-d-in-n-din (d) din-din-n-d-ni (e) din-din-n-din
- —————–je isori oro aropo oruko (a) iwo (b) emi (d) o (e) oun
- ‘Bola je eja ‘ je ninu gbolohun yii je (a) oro-oruko (b) oro- ise (d) oro apon le (e) oro apejuwe
- Iyere je orin (a) ifa (b) esu (d) ode (e) osun
- Ere idaraya ni awon wonyi ayafi (a) okoto (b) bojuboju (d) Ekun meran (e) awebi
- —- ni a fi n mo oba ni ile Yoruba (a) fila (d) ileke (e) oruko
- —- ni litireson Yoruba, ti o je mo egungun (a) Esa (b) olele (d) Iyere (e) Alamo
- Nibo ni a maa n sin eni ti o ku somi si (a) idi igi (b) eyin aaro (d) inu ile (e) e ti odo
- Inu —ni Yoruba maa n gbe oku abuke si, ki won to sin in (a) inu apo (b) inu ikoko (d) inu apere (e) inu fitila
- Baba-nla awon Yoruba, ni a mo si (a) okanbi (b) obatala (d) odudua (e) lamurudu
- Ta ni oruba n pe ni olojo-oni (a) olodumare (b) orunmila (d) odudua ogun € lamurudu
IPIN B
DAHUN IBEERE META PERE NIHIN IN
- Fa apola ise yo ninu gbolohun wonyi
- olu rin erin
- awada po
- oju re pon
- igi wo pa ode
- moto pa aja kan
2. (a) ta ni Yoruba n pe ni baba sinku (b) Daruko ona mejeeji ti a n gba pin ogun ni ile
Yoruba
- Awon Yoruba maa n saba ran won lowo. Daruko ona marun ti awon Yoruba gba n ran
ara won lowo
- (a) Kini gbolohun? (b)ko apeere gbolohun marun
5. se apejuwe iru eya awe gbologun ti a fala si wonyi
(i) Bi mo ba fe mo le pariwo
(ii) Baba da oko ti o po si ilu Ibadan
(iii) Iya naa ku leyin ti o se opolopo aisan