Comprehensive Primary 5 Yoruba Language Examination Primary 5 Yoruba First Term Examination

FIRST TERM EXAMINATION

CLASS: PRIMARY 5
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:____________________

ERE IDARAYA: ERE AYO

  1. Omo Ayo melo ni o ngbe ni oju opon?
    (a) Merinlelogun
    (b) Mejidinlogbon
    (c) Mejidinladota
    Correct Answer: (b) Mejidinlogbon
  2. Omo Ayo melo lo nwa ninu iho kankan?
    (a) Mefa
    (b) Merin
    (c) Mejo
    Correct Answer: (a) Mefa
  3. Apa __________ ni a nta ayo si.
    (a) Otun
    (b) Osi
    (c) Eyin
    Correct Answer: (a) Otun
  4. Eniyan ______________ ni o nta ayo olopon.
    (a) Meji
    (b) Meta
    (c) Merin
    Correct Answer: (a) Meji
  5. Asiko wo ni a nta ayo ni ile Yoruba?
    (a) Osan
    (b) Owuro
    (c) Irole
    Correct Answer: (c) Irole

ERE AARIN

  1. Awon wo ni a le ba nidi arin tita?
    (a) Gende
    (b) Omo wewe
    (c) Obinrin
    Correct Answer: (b) Omo wewe
  2. Kin ni eso arin fi awo jo?
    (a) Paanu to dogun-un
    (b) Ayo
    (c) Oronbo
    Correct Answer: (c) Oronbo
  3. Ona meji ti a le fi ta arin ni _______.
    (a) Ori ila ati inu ape arin
    (b) Inu opon ayo ati ori ila
    (c) Ori eni arin ati inu iho alatako
    Correct Answer: (a) Ori ila ati inu ape arin
  4. Eso wo ni a le lo dipo eso arin?
    (a) Osan mimu
    (b) Ayo
    (c) Oronbo wewe
    Correct Answer: (c) Oronbo wewe
  5. Ibo la ti nse ere arin?
    (a) Ori eni
    (b) Ita gbangba
    (c) Ori pakiti
    Correct Answer: (a) Ori eni

AKANLO EDE

  1. Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori?
    (a) Ki eniyan salo
    (b) Ki eniyan ko jale
    (c) Ki eniyan ku
    Correct Answer: (a) Ki eniyan salo
  2. Kini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe ni ko?
    (a) Ba eniyan ja
    (b) So oro pato sibi ti oro wa
    (c) Fi abe kan eniyan lori
    Correct Answer: (b) So oro pato sibi ti oro wa
  3. Kini itumo akanlo ede yii: Fi imu finle?
    (a) Se iwadi oro
    (b) Fi imu si ile
    (c) Fi imu gbo oorun
    Correct Answer: (a) Se iwadi oro
  4. Kini itumo akanlo ede yii: Fomo yo?
    (a) Fa omo jade
    (b) Se asyori
    (c) Pa omo ti
    Correct Answer: (b) Se asyori
  5. Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo?
    (a) Epa ko si ninu oro
    (b) Ko si atunse mo
    (c) Ko si eniyan mo
    Correct Answer: (b) Ko si atunse mo

OWE ILE YORUBA

  1. Pari owe yii: Agba kii nwa loja ________________________.
    (a) Kinu o bini
    (b) Ki o salo
    (c) Kori omo tuntun wo
    Correct Answer: (c) Kori omo tuntun wo
  2. Pari owe yii: Bi Okete ba dagba ________________.
    (a) Omo omo e nii mo
    (b) A pajeni
    (c) A salo ni
    Correct Answer: (a) Omo omo e nii mo
  3. Pari owe yii: Bami na omo mi _______________.
    (a) Owo lo ndun iya e
    (b) Iya e rindin ni
    (c) Ko de inu olomo
    Correct Answer: (a) Owo lo ndun iya e
  4. Pari owe yii: Ile ti a fi ito mo, _____________.
    (a) Adara si ni
    (b) Ategun a gbe lo
    (c) Iri ni yoo wo
    Correct Answer: (b) Ategun a gbe lo
  5. Pari owe yii: Esin iwaju ________________.
    (a) Ni o gbe ipokiini
    (b) Lo ya raju
    (c) Ni teyin nwo sare
    Correct Answer: (c) Ni teyin nwo sare

ITAN IRIRI ODE KAN

  1. Akikanju ode ni Oderemi nitoripe _____________.
    (a) O laya, o loogun
    (b) O ti se ise ode fun igba pipe
    (c) Ore Odediran ni
    (d) O nran awon aladugbo lowo
    Correct Answer: (a) O laya, o loogun
  2. ‘Ewe sunko’ ninu Ayoka yii tumo si __________.
    (a) Ogun ko je mo
    (b) Esu gbomi mu
    (c) Odere mi sunko
    Correct Answer: (a) Ogun ko je mo
  3. Eni ti o pa ekun ninu itan yii ni _____________.
    (a) Ibon
    (b) Oderemi
    (c) Odediran
    (d) Omo-ode akoko
    Correct Answer: (b) Oderemi
  4. Omo ode yibon lu Odediran nitori pe ___________.
    (a) O fe pa a tele
    (b) Ode ni
    (c) Iberu ni o fi yinbon
    (d) O gbabode
    Correct Answer: (c) Iberu ni o fi yinbon
  5. Odediran ko je ki won sipa ore re nitori pe ____________.
    (a) Kosi owo
    (b) Eewo ni
    (c) Oku ofo ni
    (d) O fe mo iku to pa ore re
    Correct Answer: (b)
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share