SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
SECOND TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 2Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â Â
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE AYO
-  ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo        (b) awo ayo
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo    (b) merin
-   Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun         (b) osi
-   Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin   (b) meji
- Â Â Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun Â
ALOÂ APAMO
-  Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o (a) irin   (b) omorogun
-   Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo    (b) agbara
-   Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o  (a) ata  (b) ewa Â
-   Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o (a) ilu    (b) igba
-   Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin, kini o (a) agbara      (b) odo Â
ALO APAGBE: IJAPA Â ATI Â OKERE Â
-  _________ ati okere  je ore  (a) asin       (b) ijapa
- _______ kii  se ore won       (a) ijapa      (b) asin
- Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru
- Â Â Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere
-  Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese  Â
IMOTOTOÂ ILE
- _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde       (b) Kola
- ________ ngba idoti ati panti inu ile sita  (a) Yemi  (b) Bola
-  Mama ________ sese fo aso tan ni  (a) Bola     (b) Kemi
-   Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina  (a) Kola       (b) Tunde
-   O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun     (b) igi Â