Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan.

OSE KEJI

EKA ISE EDE

AKOLE ISE Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan.

Ami ohun ni o maa n fi iyato han laarin iro kan si iro keji.

  1. Ohun Isale \ (d) o doju ko opa osi
  2. Ohun aarin – (r) O wa ni ibu
  3. Ohun Oke / (m) O doju ko apa otun

Ami Ohun lori faweli:

A E E I O O U (Faweli airanmupe)

AN EN IN ON UN (Faweli aranmupe)

Ami Ohun lori oro onisilebu kan

silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso lai si idiwo

Akiyesi: Iye ami ori oro ni iye silebu inu oro bee.

Apeere oro onisilebu kan

  1. Ta (sell) – ohun isale (d) kf
  2. Sun (sleep) – ohun isale (d) kf
  3. We (bath) – ohun isale (d) kf
  4. Mu (drink) – ohun aarin (r) kf
  5. Ko (write) – ohun aarin (r) kf
  6. Lo (go) – Ohun aarin (r) kf
  7. Ji (steal) – Ohun Oke (m) kf
  8. Fe (love) – Ohun Oke (m) kf
  9. Si (open) – Ohun Oke (m) kf

EKA ISE: ASA

AKOLE ISE: Ile – Ife saaju dide oduduwa ati idagbasoke ti oduduwa mu ba awujo naa.

  1. Itan so peilu ile-ife ni orisun Yoruba
  2. Itan fi ye wa pe inu igbo kijikiji ni ilu ile – ife wa
  3. Itan so pe awon Yoruba ni ibasepo pelu awon Tapa ati ibaripa
  4. Ilu ile-ife di agbogoyo eto oselu, esin abalaye ati awon asa Yoruba leyin dide oduduwa.
  5. Ninu eto eko ni odun 1962 ni a gbe ile eko giga yunifasiti lo si ilu ile-ife
  6. Ayipada otun de ba oro aje ilu ile ife leyin dide oduduwa

Igbelewon:

  • Fun ami ohun loriki
  • Ona meloo ni ami ohun ede Yoruba pin si?
  • Kin ni silebu?
  • Salaye idagbasoke ti o de ba ilu ile ife saaju dide oduduwa

Ise asetilewa: Ko oro onisilebu mewaa ki o si fi ami ohun ti o ba okookan won mu si i