Alo Apamọ́

Akole:alo apamo

1. Alo o aalo, ikoko rugudu feyin tigbo
Kinni: IGBIN

2. Alo o aalo, ile gbajumo kik imi eran
Kinni: IBEPE

3. Alo o aalo, iyara kotopo kiki egun
Kinni:ENU

4.Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo lailai ojo to ba de fila pupa ni iku de ba
Kinni: ABELA

5. Alo o aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki aba
Kinni: AGBARA OJO

Ise kilaasi

1. Alo o aalo, ikoko rugudu feyin tigbo kinni o
(a). Igbin. (b) Isawuru

2. Alo o aalo, ile gbajumo kiki imi eran kinni o
(a) Agbalumo (b) Ibepe

3. Alo o aalo, iyara kotopo kiki egun kinni o
(a) Enu. (b). Eyin

4. Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo kan lailai ojo to ba de fila pupa ni iku de ba kinnio
(a) opo ina. (b) Abela

5. Alo o aalo, kilo koja niwaju oba ti ko ki oba kinni o
(a) Agbara ojo. (b) Esinsin

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share