Skip to content
Class: Pry two
Subject: Yoruba Studies
Akole: Alo Apamo
1. Alo o aalo, kilo bosomi ti ko ro to.
Kinni: OKINNI.
2. Alo o aalo,opa tinrin kanle o kanrun.
Kinni: OJO
3. Alo o aalo, awe obi kan aje doyo
Kinni: AHON
4. Alo o aalo, okun nho yaya osa nho yaya omo buruku tori bo.
Kinni:OMOROGUN
5. Alo o aalo, oruku tindin tindin oruku tindin tindin oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro
Kinni: EWA
*Ise kilaasi*
1. Alo o aalo, kilo bo somi ti ko ro to, kinni o?
(a) Okinni (b) Okuta
2. Alo o aalo, opa tinrin kanle o kanrun, kinni o?
(a) Irin. (b) ojo
3. Alo o aalo, awe obi kan a je doyo, kinni o?
(a)Ahon. (b) Eyin
4. Alo o aalo, okun nho yaya osa nho yaya omoburuku to ri bo, kinni o?
(a) Igi. (b) omorogun
5. Alo o aalo, oruku tindin tindin oruku tindin tindin oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro, kinni o?
(a) iresi. (b) Ewa.