SECOND TERM EXAMINATION PRIMARY 5 YORUBA LANGUAGE
……………………………………………………………………………………
- Ko orin ibile kan fun ayeye, eyikeyi ti o ba mo, o le je nibi igbeyawo, nibi isomo loruko tabi nibi oye jije
- Daruko igbese marun-un ninu asa igbeyawo abinibi ki o se alaye okan ninu won
IWE KIKA DAROSA
- Kini so darosa di olokiki? (a) ile ti o ko (b) egbe ti o nko (d) eko ti o ko (e) owo ti o ni
- Ona wo ni darosa ngba ran mekunnu lowo (a) o nya won lowo (b) o nran won nile eko (d) o nfun won ni ise se (e) o nya won nile gbe
- Iru iranlowo wo ni darosa nse fun awon akekoo? (a) o nraso ile-eko fun won (b) o nfun won ni eko-ofe (d) o nra aso odun funwon (e) o nfun won ni ebun owo
- Nibo ni darosa ti nri owo tire? (a) nibi ole jija (b) nibi jibiti lilu (d) nibi iranlowo (e) nibi ile-ise re
- Darosa nfe ki omode ______ (a) feran obi (b) maa sa ni ile-eko (d) fi oju si eko re (e) di fole fole
OWE ILE YORUBA
Pari owe yii:
- Agba kii nwa loja __________________________________________________
- Bami na omo mi, _____________________________________________________________
- Ile ti a fi ito mo ______________________________________________________________
- Esin iwaju, __________________________________________________________________ 5.) Obe ti baale ile kii nje, _________________________________________________________