Yoruba

EYA GBOLOHUN

OSE KETA EKA ISE:    EDE AKOLE ISE:    EYA GBOLOHUN Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re.   Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko   Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka

AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON

OSE KEJI EKA ISE – EDE AKOLE ISE  EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun alalaye Gbolohun Ibeere Gbolohun ase Gbolohun ebe Gbolohun ayisodi     Gbolohun alalaye:Eyi

SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA

OSE KIN – IN – NI  EKA ISE – EDE AKOLE ISE – SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti  Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo Oro ayalo Apetunpe abbl.   Atunyewo faweli

Third Term Examinations JSS 2 Yoruba

THIRD TERM IJIYA FUN IJIWE DAKO NI LILE KURO NI ILE IWE MASE KOPA NINU RE . JSS TWO – YORUBA LANGUAGE Wakati…….Wakati meji IPIN A: Akiyesi : Ka ayoka yi daadaa ki o si dahun awon ibeere isale yii. Eni a wi fun oba je o gbo “ori okere koko lawo” ni Orin ti

1st Term Examination YORUBA JSS 1

Edu Delight Tutors Subuode Gbaga Gasline Ogun State 1st Term Examination YORUBA JSS 1 IPIN A DAHUN GBOGBO IBEERE NI IPIN YII ————– ni baba n la awon Yoruba (a) Odudua (b) Orunmila (d) Obatala Nibo ni awon Yoruba ti se wa? (a) Oyo (b) meta (d) ile ife Ojo melo ni Oduduwa fi rin

Isori oro +ninu gbolohun

OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si.   Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL ) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( CONJUCTION ) EKA

Aroko atonisona Alapejuwe

OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AROKO ATONISONA ALAPEJUWE. Aroko je ohun ti a ro ti a sise akosile. Aroko alapejuwe ni aroko ti o man sapejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to n sele gege bi a se ri i gan-an. Apeere: Oja ilu mi Egbon mi Ile-iwe mi Ouje ti mo feran Ilu

ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE.

OSE KESA-AN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE. Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A

ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100).

OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100). 51 Ookan le laadota 50+1=51 52 Eeji le laadota 50+2=52 53 Eeta le laadota 50+3=53 54 Eerin le laadota 50+4=54 55 Aarun din logota 60-5=55 56 Eerin din logota 60-4=56 57 Eeta din logota 60-3=57

ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50).

OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Nonba 1 Ookan 2 Eeji 3 Eeta 4 Eerin 5 Aarun-un 6 Eefa 7 Eeje 8 Eejo 9 Eesan-an 10 Eewaa 11 Ookanla 10+1=11 12