Third Term Examinations Primary 4 Yoruba
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Oriki orile yato si oriki ilu (a) beeko (b) beeni (d) n ko mo
- Kini ogota ni nomba (a) 50 (b) 70 (d) 60
- Okan lara awon ohun ti o maa n han ninu oriki ilu ni ___(a) orisa ilu (b) awo (d) ilu
- Apeere oro oruko aseeka ni ___(a) aga (b) oyin (d) omi
- Omo olofa mojo , olalomi omo abisu joruko awon iran wo ni a n ki bayi? (a) oluoje (b) olofa (d) opomulero
- Kemi sun fonfon, kini oro oruko ninu gbolohun naa? (a) sun (b) fonfon (d) kemi
- Okan lara apeere aroko ni ___(a) aroko alapejuwe (b) aroko onikalamu (d) aroko Oba
- Ijamba moto to soju mi je aroko ___(a) aroko onileta (b) aroko oniroyin (d) aroko ajiroro
- Ohun ti ko dara ti a ko gbodo se ni a n pe ni ___(a) eewo (b) ere ayo tita (d) ere owo
- Tani o fi omo re rubo fun odo Esinmiri? (a) Moremi (b) Tinubu (d) Ajayi Crowther
- Odun wo ni a bi Obafemi Awolowo (a) 1909 (b) 1910 (d) 1991
- Tani o se atunko bibeli lati ede geesi si ede Yoruba (a) moremi (b) Ajayi Crowther (d) Mosudi
- Tani obinrin akoko ti o koko wa oko mi orile ede Naijiria (a) olufunmilayo Kuti (b) Moremi (d) Efunroye
- Ilu ibo ni efunroye Tinubu pada si, leyin ti o kuro ni ilu Eko (a) Ijebu (b) Abeokuta /Egba (d) Ijanikin
- Meloo ni ami ohun ti o wa (a) meje (b) mejila (d) meta
- Ilu ti o wa fun gbogbo ayeye ni (a) dundun (b) agere (d) seli
- Kini Aadorin ni nomba? (a) 80 (b) 90 (d) 70
- Kini a n pe Ojo Abameta ni ede geesi? (a) Tuesday (b) Saturday (d) Monday
- Owara ni a pe ni ____ni ede geesi (a) November (b) January (d) October
- Idakeji olowo ni ____(a) olode (b) Talaka (d) amugo
- Itumo ile eko aladaani ni ile eko____ (a) olowo (b) nla (d) ti ki I se ijoba lo ni
Ninu iwe kika Ajoke se bebe
- Agogo meloo ni alaga ojo naa de? (a) mesan-an (b) mewaa ku iseju mewaa
(d) mewaa ku iseju marun
- Meloo ni awon akekoo ti n jade lo (a) ogorun (b) aadota (d) ogoji
- Apapo ebun ti Ajoke Akanji gba ni ojo naa ko din ni ____ (a)mewa (b) mejo (d) mejila
- Kini Ajoke se, ti won fi so pe o se bebe? (a) Ajoke ni o gba ebun ti o po ju
(b) Ajoke sun (d)Ajoke salo
NInu itan aworawo ko kan tise
- Asiko wo ni aworawo maa n de oko olowo re (a) owuro (b) osan (d) irole
- Kin o sele lojo kan ti o n ko ebe? (a) o ri oru owo (b) o ri kinun (d) o ri ejo
- Owo ti aworawo ri to elo (a) ogofa naira (b) ogoji naira (d) ogorun naira
- Kin ni Aworawo se si owo owo naa? (a) o gbe salo (b) ko fowo kan (d) o gbe owo naa lo fun ola ti I se olowo re
- Kin ni o sele si Aworawo ni igbeyin? (a) o ku (b) o di oba (d) o di ole
IPIN KEJI : Dahun gbogbo awon ibeere wonyi:
- Ko awon onka wonyi ni nomba
- Eetalelogota = _______________________
- Aadorin= __________________
iii. Ookanlelaadota = ___________________________
- Aarundinlogota = _______________________
v Aadota = _______________________________
- Daruko akoni ile Yoruba marun
- ________________________________ ii. ________________________
iii. _______________________________ iv. ________________________
- _________________________________
- Di alafo wonyi pelu oro ti o bamu ni isale
- Eni ti ko ni ewa rara _____
- Eni ti o maa n Daraya si enikeji _______
iii. Eni ti ko ni Igberaga rara ni ________
- Oro ti o lodi si ologbon ni ____________
- Omo ti o n na owo ni inakunaa ni _____
(oloyaya, apa, oburewa, omugo, onirele