1st Term Examination YORUBA JSS 1
Edu Delight Tutors
Subuode Gbaga Gasline Ogun State
1st Term Examination
YORUBA
JSS 1
IPIN A
DAHUN GBOGBO IBEERE NI IPIN YII
- ————– ni baba n la awon Yoruba (a) Odudua (b) Orunmila (d) Obatala
- Nibo ni awon Yoruba ti se wa? (a) Oyo (b) meta (d) ile ife
- Ojo melo ni Oduduwa fi rin lati Meka de ile ife? (a) ogun ojo (b) adota ojo (d) adorin ojo (e) aadorun ojo
- Kini o le awon Yoruba kuro ni meka? (a) ija esin (b) oro aje (d) oselu (e) iwa
- Ta ni baba Odudua? (a) obatala (b) lamurudu (d) olodumare (e) sango
- Ona melo ni a pin iro ede si (a) meta (b) merin (d) marun
- Gbogbo iro konsonanti je (a) meje (b) mejidinlogun (d) meedogbon
- Ori iro wo ni a maa n fi ami ohun si (a) iro consonant (b) ir afo (d) iro faweli
- Orisi ami-ohun melo lo wa (a) meje (b) meta (d) merin
- ______________ ni o se Pataki fun gbogbo eni ti o ba n ko ede Yoruba (a0 litireso Yoruba (b) ami ohun (d) Iwe kika
- Eya litireso Yoruba lo da lori itan yuuru (a) ewi (b) ere onise (d) litireso Yoruba oloro geere
- Isori keta ti a pin litireso Yoruba si ni (a) ere onise (b) litireso Yoruba oloro geere (d) ewi
- Apa ibo ni a ti le ri awon eya Yoruba ni orile-ede Naijiria (a) iwo oorun (b) ila oorun (d) apa gusu
- Nibo ni a ti le ri awon ara Ibadan (a) Abeokuta (b) Oyo (d) kware
- Awon Awori wa ni (a) ilu Oyo (b) Ile ila (d) ilu eko
- Ona ti a n gba ko sipeli Yoruba sile lode oni ni a mo si (a) Akoto ede Yoruba (b) akosile (d) ona kiko sile
- Akoto ode oni fun aiye ni (a) ai-ye (b) aye (d) yea
- Bi omokunrin baji o gbodo ———- ki bab re (a) kunle (b) duro (d) dobale
- Bawo ni a se n ki babalowo (a) aboru boye (b) e ku ise o (d) ojugbooro
- Aweye ni a n ki (a) atuko (b) awako (d) alagbede
IPIN B
DAHUN IBEERE META PERE NI IPIN YII
1. (a) ko gbogbo iro ede yourba sile (b) ko apeere iro faweli
2. Bawo ni Yoruba se n kini ni awon akoko wonyi (i) Ni aaro (ii) Ni irole (iii) ni ale (iv) Ni osan (v) Ni iyaleta
3. Tuna won oro wonyi ko ni akoto ode oni (i) aiye (ii) shola (iii) ottun (iv) pepeiye (v) Bakana
4. Daruko eya Yoruba mewa ti o mo
5. Daruko eya litireso meteeta (b) ewo ninu eya litireso Yoruba lo je ere gidi