AWON OLOYE OGUN
Subject : Yoruba
Class : Jss 2
Term : Second Term
Week : Week 6
Topic :
EDE: Akaye Oloro Geere/Wuuru.
ASA: (a) Ipari ogun . (b) Ona ti a le gba dena ogun (d) anfaani ati aleebu.
LIT: Kika iwe Apileko ti ijoba yan.
EDE: Atunyewo ise saa kin-in-ni
ASA: Atunyewo ise saa kin-in-ni
LIT: Atunyewo ise saa kin-in-ni
WEEK 2
EDE: Aroso Alapejuwe (ilana bi a se le ko aroko Yoruba )
ASA: Asa Iranra Eni lowo- Ajo, Esusu, Egbe Alafowosowopo
LIT: Litireso Alohun to je mo Esin Ibile- Iyere Ifa, Iwi, Ijala Iremoje.
WEEK 3
EDE: Aroko Asapejuwe ( kiko aroko alapejuwe).
ASA: Asa Iranra eni lowo (owe, aaro, arokodoko, ebese )
LIT: Kika Iwe Apileko: ere onise ti ijoba yan
OSE KEFA
AKAYE
akaye ni ohun ti a ka ti o si ye wa yekeyeke. Ti a ba fe dahun ibeere ti o tele akaye, a gbodo fi ara bale daadaa ka akaye, a gbodo ka akaye ni eemeji. Leyin eyi ni o wo awon ibi ti ibeere ti jeyo ninu akaye. Leyi ni yoo dahun ibeere. Ti o ba ti dahun ibeere tan ni yoo tun wo boya idahun ba ibeere mu.
Ka ayoka isale yii ki o si dahun ibeere ti o tele e.
Owo se pataki, o se koko. Bi o tile je pe owo ko fe ki enikeni damoran kanakan leyin
ohun, sibe a gbodo mo pe iranse lo je. Ko ye ki o di oga fun enikeni, ti Oba oke ba fi se buruji fun. Laye atijo, bi enikan ba sise to lowo laarin ebi, gbogbo ebi ni yoo janfaani re. Imo won ni pe owo ko niran, ko je ki won di agberaga. Bi awon baba wa se ni itara ise aje to, won ki i saba gbona alumokoro wa owo. Lode oni awon eniyan n digunjale, won n sese, won n gbe kokeeni nitori owo.
- Ayoka yii fi ye wa pe owo je ……………………. A. agberaga B. oga D. iranse E. onitara.
- Ona wo lo daraju lati lowo? A. oso sise B. omo gbigbe D. ise sise E. gbigbo tebi
- Akole to ba ayoka yii mu ju ni…………. A. awon adigunjale B. owo nini D. anfaani olowo E. gbigbe kokeeni
- Itara ki ni awon Yoruba ni? A. igberaga B. ise aje D. buruji E. owo nini
- Pari oro yii ‘Imo won ni pe ……………. A. owo ko niran B. owo ni koko D. owo dara E. owo je ajemonu.
AWON OLOYE OGUN Deeti………………..
Ni ilu Oyo, awon ode ati awon akoni ni awon oloye ti o maa n dajo lati lo jagun. Pupo lati iran onikoyi, iremogun ati oluoje ni o maa n jagun ju nile Yoruba. Awon iran onikoyi ko ni ise meji ju ogun lo. Aadorin ni awon oloye ogun laarin awon eso ikoyi ni o n so ilu Oyo. Laarin won ni a ti yan Aare onakakanfo Eleyi ni olori ogun gbogbo ile Yoruba.
Oloye ogun ti ipo re ga ju ni ilu kookan ni ile Yoruba ni Balogun. Balogun ni isomogbe re . Awon ni otun balogun ti o gbodo maaa ja ni egbe otun re ni oju ogun. Osi Balogun naa je okan lara oloye Balogun. Ohun ni o maa n ja ni egbe osi Balogun ni oju ogun. Leyin eyi ni a ni ekerin, ekarun ati ekefa Balogun. Awon oloye mefeefa yii ni ipo won ga ju ni ninu oye ogun.
Seriki ni oye ogun ti o pawo le Balogun. Sarumi ni oloye ogun to kan, oun naa ni isomogbe bi ti Balogun ati Seriki.
ETO OGUN: Gege bi ipo awon oloye ogun ba se ri ni won se n to ja ogun. Oloye asiwaju ni o maa saaju pelu awon isomogbe re. Leyin won ni Bada pelu awon isomogb re leyin re ni asipa. Leyin patapata ni Balogun pelu awon isomogbe re yoo wa ni oju ogun.
BI A SE LE DENA OGUN JIJA
Orisiirisii ona ni awon Yoruba maa n gba dena ogun paapaa julo won maa n mo odi yi ilu ka lati soro fun ota lati koja si ilu won.
Wiwa Yara: Yara yii ni won maa n gbele/koto lati soro fun awon ota lati koja nibe
Tituba: Ni iwon igba ti owo ilu kin-in-ni ba te ekeji awon ara ilu yii le bebe ki won ni awon o se ohun ti won ni ki awon o se, awon ti fara mo ohun ti won ba ti so. Iru igbese bayi ni a n pe ni tituuba
Lilo Alami: Alami/Aloore ni eni ti o n so enu ibode kookan. Awon ni won maa tete ri ti ogun ba ti n bo. Laifotape won ti fi to eni ti o ye leti pe ogun ti de.
IGBELEWON
- Ko orisi ona meta ti a n gba dena ogun sile
- Salaye wiwa/Yara ninu eto ogun jija
- Ko oruko oloye ogun marun-un sile
- Awon iran wo ni won maa n jagun nile Yoruba.
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
1 Eko ede ati asa Yoruba titun iwe kin-in-ni ( S S S ) Oju iwe 75-86 lati owo Oyebamji Mustaph.
2 Oyebamiji Mustapha (2009) Eko ede Yoruba titun iwe keji (J.S.S.3) oju iwe 1-15 university Press Plc.
LITIRESO
Kika iwe apileko ti ijoba yan.
APAPO IGBELEWON
- Ko orisi ona meta ti a n gba dena ogun sile
- Salaye wiwa/Yara ninu eto ogun jija
- Ko oruko oloye ogun marun-un sile
- Awon iran wo ni won maa n jagun nile Yoruba.
- Ya ate faweli aranmupe.
ISE ASETILEWA
- Ohun ti a ka ti o ye wa ni A. oniroyin B. akaye D. alalaye
- Ewo ni o tona? A. a gbodo fi ara bale ka akaye B. a ko gbodo ka akaye ti a ko mo eni ti o ko o D. akaye gbodo gun.
- Ewo ni ko tona? A. a gbodo fi ara bale ka akaye B. a ko gbodo ka akaye ti a ko mo eni ti o ko o D. idahun gbodo ba ibeere mu
- Oloye ogun ti o ga ju ni …… A. Balogun B. Aare Onakakanfo D. bada D. Seriki
- Ni aarin ilu kookan eni ti oye ogun re ga ju ni ……A. Balogun B. Aare Onakakanfo D. seriki
APA KEEJI
- Ona wo ni won n gba dena ogun? Salaye.
- Ko anfaani ogun jija meta sile.
- Salaye ona meta ti a n gba dena ogun jija.
IGBELEWON
Salaye ewi alohun ajemesin marun-un.
IWE AKATILEWA
S.Y Adewoyin (2003) YORUBA LI BOOK 2 Corpromutt Publishers Oju Iwe 16-17.
ÌWÉ ÀKÀTILÉWÁ
Egbe akomolede ati asa Yoruba (2002) Eko ede ati asa Yoruba iwe keji (J.S.S.2) Longman Nig Plc Oju Iwe 14-16.
APAPO IGBELEWON
- Ki ni aroko oniroyin/asotan?
- Ko aroko lori ojo ibi re ti o koja
- Ko ilapa ero lori “Ojo kan ti nko le gbagbe”
- Salaye ewi alohun ajemesin marun-un.
- Ko aroko lori ‘ile iwe mi’
ISE ASETILEWA
- Ti won ba fun wa ni akaye ohun ti won fe ki a se ni ki a ……A. ronu B. sa ere kiri D. fa ogbon inu re yo
- Ota ibon, etu je aroko ….. A. alaafia B. ipalemo ise ode D. ogun jija.
- Awon ti ogun ba ko lati ilu kan si omiran ni a n pe ni ….. A. jagunjagun B. iwofa D. eru
- Awon ……. ni olusin ogun A. olounje B. ode D. onirara.
- …….. ni won n fi ijala bo A. ogun B. ifa D. sango.
WEEK 4
EDE: Aroso Oniroyin/Asotan ( ilana)
ASA: Ogun Jija (awon ohun ti o n fa ogun jija ati ohun ti ko ye ko fa ogun jija, awon oloye ogun).
APA KEJI
- Ko ohun elo ogun jija meji sile
- Ko merin sile ninu ewi atenudenu to je mo esin abalaye