YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6 FIRST TERM EXAMINATION 

FIRST TERM EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………………………………

  1. Iwe Kika:- Ewi Omoluabi
  2. Ninu ewi omoluabi, a rip e, omoluabi maa n _____ (a) si wahu (b) so yaya
  3. Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______ (a) jeun ni won-tonwon si (b) sepe
  4. Omo ti yoo je asa mu tumo si _____ (a) yoo sa nnkan mu (b) omo ti yoo je ologbon
  5. Akewi yii fe ki a je ________ (a) ole (b) omoluabi
  6. Ewi yii so pe:- a ja je wora ni _______ (a) wobia (b) obun

 

  1. Owe Ile Youba

Pari awon owe wonyii

  1. Ile la nwo: (a) ka to ja (b) ka to somo loruko
  2. Esi iwaju: – (a) ni teyin nwo sare (b) lo gba ipo kiini
  3. Agba kii nwa loja:- (a) kasa lo (b) Kori omo tuntun wo
  4. Bami na omo mi:- (a) Ko de inu olomo (b) owo lo ndun iya e
  5. Bi omode bamo owo we:- (a) a dara si (b) a ba agba jeun
  6. Iwe Kika: – Iyi Ise Sise
  7. Ibo ni orison gbogbo iwa ibaje (a) inu oko (b) odede
  8. Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akinkanju (d) imele
  9. Iwa Abeke di awokose fun awon elegbe re nitori _____ (a) iro pipa re (b) iwa omoluabi re (d) agbagun elubo re
  10. Iya Agbeke fun-un ni _______ ko to bere ile-eko (a) Aso tuntun (b) ounje to dara (d) imoran
  11. Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko (a) won na-an legba (b) won fun-un lekoo ofe (d) won da seria fun-un
  12. Iwe Kika:- Ija Ko Lere
  13. Kini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, omo naa niyi? (a) o fe salo (b) o fe ba ehoro sare
  14. Won ko pati e bo o, tumo si pe (a) won na-an daadaa (b) won ja ni patie
  15. Inu Alagba Alao dun nitori won _____ (a) bu Ajao (b) ko won jade (d) na Ajao
  16. ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao (a) ile-eko (b) ogba (d) ita
  17. Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____ (a) sare pea won obi (b) ba gbogbo awon ake koo soro (d) dojuti won
Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share